JÍ! March 2015 | Nje Bibeli Wulo fun Wa Lonii?
Wo merin lara awon ilana inu re to fi han pe o si wulo lonii gege bo se wulo nigba ti won ko o.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Nje Bibeli Wulo Fun Wa Lonii?
Nigba ti Hilton fi ile sile, awon obi re ro pe ko le yiwa pa da mo. Nigba to pa da de leyin odun 12, won si i mo tori o ti yi pa da. Ki lo sele?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Jije Oloooto
Raquel i ba lowo repete ka ni o gba riba, sugbon o gba pe ere toun ri ju owo lo.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ikora-Eni-Nijaanu
Ki lo ran okunrin kan to n je Cassius lowo lati maa ko ara e nijaanu?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Isotito Laaarin Tokotaya
Obinrin kan ri ibanuje ti aisooto maa n fa. Se aarin oun ati oko re tun le gun?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bi O Se Le Sakoso Ibinu Re
Ilana Bibeli marun-un to le ran e lowo lati sakoso ibinu re.
Ogbon To N Daabo Boni
Ki ni itumo owe Bibeli to so pe: “Irapada okan eniyan ni oro re, sugbon eni ti o je alainilowo ko gbo ibawi mimuna”?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bi O Se Le Salaye Ohun Ti Iku Je fun Omo Re
Ohun merin to o le se lati dahun ibeere won, ta a si mu ki won fara da a ti eni ti won feran ba ku.
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fífi Ọ̀rànyàn Báni Tage
Gbọ́rọ̀ lẹ́nu àwọn ọ̀dọ́ márùn-ún nípa fífi ọ̀ranyàn báni tage àtohun tó o lè ṣe tó bá ṣẹlẹ̀ sí ẹ.
Máa Wà ní Mímọ́ Tónítóní
Jèhófà ní ibi to máa ń tọ́jú àwọn nǹkan sí. Kọ́ bí o ṣe lè wà ní mímọ́ tónítóní!