JÍ! No. 1 2016 | Ṣé Ìsìn ti Fẹ́ Kógbá Wọlé?
Ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn tó ní èrò tó yàtọ̀ síra ló ti gbé irú ìgbésẹ̀ kan náà.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Kí Ló Máa Ń Fa Wàhálà Nínú Ilé?
Ṣé àwọn wàhálà tá a ṣàlàyé nínú àpilẹ̀kọ yìí ti ṣojú ẹ rí?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bí Ẹ Ṣe Lè Dín Wàhálà Kù Nínú Ilé
Ṣé ohun mẹ́fà yìí, kó má bàa máa sí ìjà láàárín yín, kí àlàáfíà sì jọba.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bí Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Àlàáfíà Wà Nínú Ilé
Ṣé àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì lè mú kí àlàáfíà wà níbi tí kò sí tẹ́lẹ̀? Wo ohun táwọn tó ti fi ìmọ̀ràn Bíbélì sílò sọ.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Ara Wa Ṣe Ń Mú Kí Egbò Jiná
Báwo làwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ṣe wo àpẹẹrẹ yìí láti fi ṣe oríṣi ike tuntun kan?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Nígbà Téèyàn Bá Kú?
Ṣé àwọn tó ti kú mọ ohun tó ń lọ láyìíká wọn?
Ohun Táwọn Ọ̀dọ́ Sọ Nípa Owó
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè fowó pa mọ́, bó ṣe yẹ kó o ná an àti bó ò ṣe ní sọ ara rẹ di ẹrú owó.