ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2021 Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 7–July 4, 2021 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí. “Tọ Ipasẹ̀ Rẹ̀ Pẹ́kípẹ́kí” Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àwọn Ọ̀rọ̀ Tí Jésù Sọ Kẹ́yìn Máa Fi Hàn Pé O Mọyì Ìràpadà Nígbà Gbogbo O Ṣeyebíye Gan-an Lójú Jèhófà! ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ “Mo Ti Ń Gbádùn Iṣẹ́ Ìwàásù Báyìí!” Ìtàn ìgbésí ayé: Vanessa Vicini Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé