ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2023
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 5–July 9, 2023 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 15
Kí La Rí Kọ́ Nínú Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Tí Jésù Ṣe?
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 16
“Arákùnrin Rẹ Máa Dìde”!
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 17
Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Ìṣòro Tó Dé Bá Ẹ
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 18
Ẹ Máa Gba Ara Yín Níyànjú Nípàdé Ìjọ
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 19