ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ August 2023
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní October 9–November 5, 2023 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 34
Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 16-22, 2023.
Tí Ọkọ Tàbí Aya Kan Bá Ń Wo Àwòrán Ìṣekúṣe
Báwo ni tọkọtaya ṣe lè ṣiṣẹ́ pa pọ̀ kí ọkọ lè jáwọ́ nínú wíwo àwòrán ìṣekúṣe tó ti mọ́ ọn lára, kí wọ́n lè pa dà fọkàn tán ara wọn?
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 36
Gbé Ẹrù Tó Yẹ Kó O Gbé, Kó O sì Ju Èyí Tí Ò Yẹ Nù
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 30–November 5, 2023.