ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ August 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti October 7–​November 10, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 31

Ohun Tí Jèhófà Ṣe Ká Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ àti Ikú

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 7-13, 2024.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

2 Tẹsalóníkà 3:14 sọ pé ká sàmì sí àwọn èèyàn kan. Ṣé àwọn alàgbà ló máa sàmì náà àbí Kristẹni kọ̀ọ̀kan?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 32

Jèhófà Fẹ́ Kí Gbogbo Èèyàn Ronú Pìwà Dà

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 14-20, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 33

Báwo Ni Jèhófà Ṣe Fẹ́ Kí Ìjọ Máa Ṣe Sáwọn Tó Dẹ́ṣẹ̀ Tó Burú Jáì?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 21-27, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 34

Bá A Ṣe Lè Ṣàánú Ẹni Tó Dẹ́ṣẹ̀, Ká sì Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Ẹ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 28–​November 3, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 35

Báwọn Alàgbà Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tí Wọ́n Mú Kúrò Nínú Ìjọ

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 4-10, 2024.

Ohun Tá A Fẹ́ Kẹ́yin Òǹkàwé Wa Mọ̀

Nínú Ilé Ìṣọ́ yìí, a ti jíròrò àwọn àpilẹ̀kọ tó jẹ́ ká rí i pé Jèhófà ran àwọn tó dẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́, ó ń gba tiwọn rò, ó nífẹ̀ẹ́ wọn, ó sì ń fàánú hàn sí wọn àti báwa náà ṣe lè fìwà jọ Jèhófà.