Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2018
Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
1918—Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.
Àsọyé Mú Kí Ìhìn Rere Tàn Kálẹ̀ (Ireland), Feb.
Ẹ̀bùn Wo La Lè Fún Jèhófà? (ọrẹ), Nov.
Ẹ̀yin Àgbàlagbà—Jèhófà Mọyì Yín, Sept.
Ẹ̀yin Tá A Yàn Sípò—Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Tímótì, Apr.
Ìkórè Yìí Mà Pọ̀ O! (Ukraine), May
Iṣẹ́ Fífúnrúgbìn Ìjọba Náà Bẹ̀rẹ̀ (Pọ́túgà), Aug.
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Madagásíkà, Jan.
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Myanmar, July
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Jẹ́ ti Jèhófà, July
A Máa Láyọ̀ Tá A Bá Jẹ́ Ọ̀làwọ́, Aug.
“Àá Pàdé ní Párádísè!” Dec.
Aájò Àlejò Ṣe Pàtàkì Gan-An! Mar.
Alágbára Ńlá Ni Jèhófà, Síbẹ̀ Ó Ń Gba Tẹni Rò, Sept.
Aláyọ̀ Ni Àwọn Tó Ń Sin “Ọlọ́run Aláyọ̀,” Sept.
Bá A Ṣe Lè Ní Òmìnira Tòótọ́, Apr.
Báwo Ni Ìbáwí Ṣe Ń Fi Hàn Pé Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Wa? Mar.
“Bí Ẹ Bá Mọ Nǹkan Wọ̀nyí, Aláyọ̀ Ni Yín Bí Ẹ Bá Ń Ṣe Wọ́n,” Sept.
Bí Ẹ̀yin Ọ̀dọ́ Ṣe Lè Gbádùn Ìgbésí Ayé Yín, Dec.
Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn Láìka Ìyípadà Èyíkéyìí Sí, Oct.
Ẹ Jẹ́ “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn” Kẹ́ Ẹ Lè Fògo fún Jèhófà, June
Ẹ Máa Fìfẹ́ Gbé Àwọn Míì Ró, Sept.
“Èmi Yóò Máa Rìn Nínú Òtítọ́ Rẹ,” Nov.
Ẹ̀yin Òbí, Ṣé Ẹ̀ Ń Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi? Mar.
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Dúró Gbọn-In Lòdì sí Èṣù, May
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹlẹ́dàá Yín Fẹ́ Kẹ́ Ẹ Láyọ̀, Dec.
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Ìjọsìn Jèhófà Ló Gbawájú ní Ìgbésí Ayé Yín? Apr.
‘Fetí sí Ìbáwí Kó O sì Di Ọlọ́gbọ́n,’ Mar.
Fi Ọwọ́ Pàtàkì Mú “Ohun Tí Ọlọ́run Ti So Pọ̀,” Dec.
Fọkàn Tán Kristi Tó Jẹ́ Aṣáájú Wa, Oct.
Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Kó O Lè Wà Láàyè! Nov.
Ìfẹ́ Wo Ló Ń Mú Kéèyàn Ní Ojúlówó Ayọ̀? Jan.
“Ìjọba Mi Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé Yìí,” June
Ìrántí Ikú Kristi Ń Mú Ká Wà Níṣọ̀kan, Jan.
Ìrìbọmi—Ohun Tó Yẹ Kí Gbogbo Kristẹni Ṣe, Mar.
Ìsinsìnyí Ló Yẹ Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí Ju ti Ìgbàkigbà Rí Lọ, Apr.
Ìyàtọ̀ Tó Wà Láàárín Àwọn Tó Ń Sin Ọlọ́run Àtàwọn Tí Kò Sìn Ín, Jan.
Jẹ́ Onígbọràn Kó O sì Nígbàgbọ́ Bíi Ti Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù, Feb.
Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Tó Ń “So Èso Pẹ̀lú Ìfaradà,” May
ọ́Jọ́sìn Jèhófà, Ọlọ́run Tí Ń Fúnni Ní Òmìnira, Apr.
Ká Jẹ́ Ọ̀kan Bí Jèhófà àti Jésù Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan, June
Kí Ló Túmọ̀ Sí Pé Kéèyàn Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí? Feb.
Kí Nìdí Tá A Fi Ń “Bá A Nìṣó ní Síso Èso Púpọ̀”? May
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fún Ẹni Tó Ni Ohun Gbogbo Ní Nǹkan? Jan.
Má Ṣe Máa Fi Ìrísí Dáni Lẹ́jọ́, Aug.
Máa Bá Jèhófà Ṣiṣẹ́ Lójoojúmọ́, Aug.
Máa Fi Àwọn Òfin àti Ìlànà Jèhófà Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ, June
Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni, Oct.
Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà, Apr.
Máa Gba Tàwọn Míì Rò Bíi Ti Jèhófà, Sept.
Máa Rí Àrídájú Ọ̀rọ̀, Aug.
Máa Sọ Òtítọ́, Oct.
Mọ Ọ̀tá Rẹ, May
“Ó Ń Fi Agbára fún Ẹni Tí Ó Ti Rẹ̀,” Jan.
Ojúure Ta Lò Ń Wá? July
“Ra Òtítọ́, Má sì Tà Á,” Nov.
Sapá Láti Túbọ̀ Di Ẹni Tẹ̀mí, Feb.
Ṣé Jèhófà Lo Tẹjú Mọ́? July
Ṣé O Mọ Jèhófà Dáadáa Bíi Ti Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù? Feb.
Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Nǹkan Ni Ìwọ Náà Fi Ń Wò Ó? Nov.
Ta Ló Ń Darí Èrò Rẹ? Nov.
“Ta Ni Ó Wà ní Ìhà Ọ̀dọ̀ Jèhófà?” July
BÍBÉLÌ
Jẹ́ Kí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Gbádùn Mọ́ Ẹ Kó sì Ṣe Ẹ́ Láǹfààní, July
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Àwọn wo ni àwọn Olóore tí Jésù mẹ́nu kàn? Nov.
Báwo ni a ṣe gba Pọ́ọ̀lù ‘lọ sí ọ̀run kẹta’ àti “sínú párádísè”? (2Kọ 12:2-4), Dec.
Kí nìdí tá a fi máa ń yàwòrán Pọ́ọ̀lù bí ẹni tó pá lórí? Mar.
Kí nìdí tá a fi ṣàtúnṣe sí Sáàmù 144:12-15? Apr.
Kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa gbé àwọn ìtẹ̀jáde wa sórí ìkànnì míì? Apr.
Ṣé wọ́n lè gbé ìgbìmọ̀ onídàájọ́ dìde táwọn méjì tí kì í ṣe tọkọtaya bá sun inú ilé kan náà mọ́jú? July
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Àlàáfíà—Báwo Lo Ṣe Lè Ní In? May
Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Kí Àwọn Èèyàn, June
Ìdùnnú—Ànímọ́ Tí Ọlọ́run Ń Fúnni, Feb.
Inú Rere—Ànímọ́ Kan Tó Yẹ Kó Hàn Nínú Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Wa, Nov.
Ìpamọ́ra—Fífaradà Á Pẹ̀lú Ìrètí, Aug.
Máa Fàánú Hàn sí Àwọn Èèyàn, July
‘Olódodo Yóò Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà,’ Dec.
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Jèhófà Bù Kún Ìpinnu Tí Mo Ṣe (C. Molohan), Oct.
Jèhófà Dá Mi Lọ́lá Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Ọmọ Tálákà (S. Herd), May
Jèhófà Fi Inú Rere Hàn sí Wa (J. Bockaert), Dec.
Jèhófà Ò Já Mi Kulẹ̀ Rí (E. Bright), Mar.
Jèhófà Tù Mí Nínú (E. Bazely), June
Mo Pinnu Pé Mi Ò Ní Juwọ́ Sílẹ̀ (M. Danyleyko), Aug.
Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe Lọ́dọ̀ Jèhófà (B. Berdibaev), Feb.
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Ǹjẹ́ O Mọ Ohun Tí Aago Sọ? (Àsìkò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), Sept.
Ó Pàdánù Ojú Rere Ọlọ́run (Rèhóbóámù), June
Ọkàn Sítéfánù Balẹ̀ Nígbà Tí Wọ́n Ṣenúnibíni sí I, Oct.
Ṣé Wọ́n Fi Àwọn Ìlànà Inú Òfin Mósè Yanjú Èdèkòyédè? Jan.
ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE
Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú? No. 2
Ṣé Bíbélì Ṣì Wúlò Lóde Òní? No. 1
Ṣé Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ? No. 3
JÍ!