ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ December 2020

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 1-28, 2021 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ṣé ohun tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ nínú 1 Kọ́ríńtì 15:29 ni pé àwọn Kristẹni kan ṣèrìbọmi nítorí àwọn òkú?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Òwe 24:16 sọ pé: “Olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje, á sì tún dìde.” Ṣé ohun tí ẹsẹ yìí ń sọ ni pé èèyàn lè máa dẹ́ṣẹ̀ léraléra kí Ọlọ́run sì máa dárí jì í?