Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2020

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2020

Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ILÉ ÌṢỌ́​—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • 1920​—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.

  • Kí Ni Wàá Ṣe Tí Kàkàkí Bá Dún? June

  • Òjò Ìbùkún Rọ̀ Sórí Àwọn Tó Pa Dà sí Ìlú Ìbílẹ̀ Wọn, Nov.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

  • A Máa Bá Yín Lọ, Jan.

  • A Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Baba Wa Gan-an, Feb.

  • Àjíǹde Dájú! Dec.

  • Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Wa Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi​—Apá Kìíní, Oct.

  • Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Wa Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi​—Apá Kejì, Oct.

  • Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Láti Máa Pa Àṣẹ Kristi Mọ́, Nov.

  • “Báwo Ni Àwọn Òkú Ṣe Máa Jíǹde?” Dec.

  • Bó O Ṣe Lè Borí Ìrẹ̀wẹ̀sì, Dec.

  • “Èmi Fúnra Mi Yóò Wá Àwọn Àgùntàn Mi,” June

  • Ẹ Máa Fún Àwọn Arábìnrin Níṣìírí, Sept.

  • Ẹ Máa Rìn Nínú Òtítọ́, July

  • Ẹ Ní Ìfẹ́ Tó Jinlẹ̀ sí Ara Yín, Mar.

  • “Ẹ Pa Dà Sọ́dọ̀ Mi,” June

  • “Ẹ̀mí Fúnra Rẹ̀ Ń Jẹ́rìí,” Jan.

  • “Fún Mi Ní Ọkàn Tó Pa Pọ̀ Kí N Lè Máa Bẹ̀rù Orúkọ Rẹ,” June

  • Gbogbo Wa La Wúlò Nínú Ìjọ! Aug.

  • Ìgbà Wo Ló Tọ́ Pé Kéèyàn Sọ̀rọ̀? Mar.

  • Ìgbéjàkò Láti Apá Àríwá! Apr.

  • Ìrètí Àjíǹde Jẹ́ Ká Rí I Pé Jèhófà Jẹ́ Onífẹ̀ẹ́, Ọlọ́gbọ́n àti Onísùúrù, Aug.

  • Jèhófà Baba Wa Ọ̀run Nífẹ̀ẹ́ Wa Gan-an, Feb.

  • Jèhófà Ló Ń Darí Ètò Rẹ̀, Oct.

  • Jèhófà Ń Tu Àwọn Tó Rẹ̀wẹ̀sì Nínú, Dec.

  • Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Rẹ, Ó sì Mọyì Ẹ Gan-an! Jan.

  • Jẹ́ Kí Jèhófà Tù Ẹ́ Lára, Feb.

  • Jẹ́ Kí Òtítọ́ Tó O Gbà Gbọ́ Dá Ẹ Lójú, July

  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bí O Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Rẹ Rìn, Aug.

  • Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n ní Àkókò Àlàáfíà, Sept.

  • “Kí Orúkọ Rẹ Di Mímọ́,” June

  • ‘Má Ṣe Dẹwọ́’ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù, Sept.

  • Má Ṣe Ro Ara Rẹ Ju Bó Ṣe Yẹ Lọ, July

  • “Máa Ṣọ́ Ohun Tí A Fi sí Ìkáwọ́ Rẹ,” Sept.

  • “Mo Pè Yín Ní Ọ̀rẹ́,” Apr.

  • Mọ́kàn Le​—Jèhófà Ni Olùrànlọ́wọ́ Rẹ, Nov.

  • Mọyì Àwọn Ìṣúra Tí Kò Ṣeé Fojú Rí, May

  • Mọyì Àwọn Míì Nínú Ìjọ, Aug.

  • “Nígbà Tí Mo Bá Jẹ́ Aláìlera, Ìgbà Náà Ni Mo Di Alágbára,” July

  • O Lè Jẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà Tó O Bá Sapá Láti Borí Ìlara, Feb.

  • O Lè Jẹ́ “Orísun Ìtùnú” Fáwọn Míì, Jan.

  • Ojú Wo Lo Fi Ń Wo Àwọn Tó Wà ní Ìpínlẹ̀ Ìwàásù Rẹ? Apr.

  • “Ọba Àríwá” Ní Àkókò Òpin Yìí, May

  • Ọjọ́ Iwájú Ni Kó O Tẹjú Mọ́, Nov.

  • “Sá Eré Ìje Náà Dé Ìparí,” Apr.

  • Ṣé O Mọyì Àwọn Ẹ̀bùn Tí Ọlọ́run Fún Ẹ? May

  • Ṣé O Múra Tán Láti Di Apẹja Èèyàn? Sept.

  • Ṣé Ò Ń Retí “Ìlú Tó Ní Ìpìlẹ̀ Tòótọ́”? Aug.

  • Ṣé O Ti Ṣe Tán Láti Ṣèrìbọmi? Mar.

  • Ṣé Wàá Máa Ṣe Ìyípadà Tó Yẹ? Nov.

  • Ṣé Wọ́n Máa Sin Jèhófà Tí Wọ́n Bá Dàgbà? Oct.

  • Ta Ni “Ọba Àríwá” Lónìí? May

  • Tó O Bá Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tó O sì Mọyì Rẹ̀, Wàá Ṣèrìbọmi, Mar.

  • “Torí Náà, Ẹ Lọ, Kí Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn,”Jan.

  • Túbọ̀ Mọ Àwọn Ará, Kó O sì Máa Gba Tiwọn Rò, Apr.

BÍBÉLÌ

  • Kí Làwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Bẹliṣásárì? Feb.

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

  • Àwọn wo ni ẹ̀ṣọ́ tẹ́ńpìlì, iṣẹ́ wo ni wọ́n sì ń ṣe? Mar.

  • Ìgbà wo ni Jésù di Àlùfáà Àgbà, ìgbà wo sì ni májẹ̀mú tuntun fìdí múlẹ̀? July

  • Ṣé àwọn ànímọ́ mẹ́sàn-án tó wà nínú Gálátíà 5:​22, 23 nìkan ni “èso ti ẹ̀mí”? June

  • Ṣé àwọn èèyàn tó ń ṣàkóso nìkan ni Oníwàásù 5:8 ń tọ́ka sí àbí ó kan Jèhófà náà? Sept.

  • Ṣé ẹni tó ń dẹ́ṣẹ̀ léraléra ni Òwe 24:16 ń tọ́ka sí? Dec.

  • Ṣé ohun tí 1 Kọ́ríńtì 15:29 sọ ni pé àwọn Kristẹni kan ṣèrìbọmi nítorí àwọn òkú? Dec.

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

  • Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ sí Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ! Dec.

  • Ìkóra-Ẹni-Níjàánu​—Ànímọ́ Táá Jẹ́ Ká Rí Ojúure Jèhófà, June

  • Ìwà Tútù​—Báwo Ló Ṣe Ń Ṣe Wá Láǹfààní? May

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

  • “Àwa Nìyí! Rán Wa!” (J. àti M. Bergame), Mar.

  • “Jèhófà Ò Gbàgbé Mi” (M. Herman), Nov.

  • Mo Rí Ọ̀pọ̀ Ìbùkún Gbà Torí Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Tó Fi Àpẹẹrẹ Tó Dáa Lélẹ̀ (L. Crépeault), Feb.

  • Ohun Tó Yẹ Kí N Ṣe Ni Mo Ṣe (D. Ridley), July

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

  • Àwọn Ọba Tó Ń Bára Wọn Jà Lákòókò Òpin Yìí, May

  • Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Jẹ́ Ẹrú Nílẹ̀ Íjíbítì, Mar.

ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE

  • Ibo La Ti Lè Rí Òtítọ́? No. 1

  • Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? No. 2

  • Ọlọ́run Ìfẹ́ Máa Bù Kún Ẹ Títí Láé, No. 3

JÍ!

  • Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn, No. 1

  • Kí Nìdí Tí Ìyà Fi Ń Jẹ Aráyé? No. 2

  • Ṣé Ìkórìíra Lè Dópin? No. 3