ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ December 2021

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti January 31–February 27, 2022 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 48

“Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”

Ǹjẹ́ O Rántí?

Ṣó o gbádùn kíka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lọ́dún yìí? Wò ó bóyá wàá lè dáhùn àwọn ìbéèrè yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 50

Ẹ Máa Fetí sí Ohùn Olùṣọ́ Àgùntàn Rere

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 51

Ẹ Máa ‘Fetí sí Jésù’

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2021

Atọ́ka àwọn àkòrí tó jáde nínú Ilé Ìṣọ́ àti Jí! lọ́dún 2021