Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2021

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2021

Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ILÉ ÌṢỌ́​—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • 1921​—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

  • Bá A Ṣe Lè Máa Láyọ̀ Tá A Bá Ń Fara Da Ìṣòro, Feb.

  • Báwo La Ṣe Lè Tọ́ Oore Jèhófà Wò? Aug.

  • Báwo Ni Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì Í Yẹ̀ Ṣe Ń Ṣe Ọ́ Láǹfààní? Nov.

  • Bí Gbogbo Ìjọ Ṣe Lè Mú Kí Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Kan Tẹ̀ Síwájú Kó sì Ṣèrìbọmi, Mar.

  • Bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ṣe Lè Mú Kó O Fara Da Ìṣòro, Mar.

  • “Èmi Yóò Mi Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Jìgìjìgì” Sept.

  • Ẹ Di Ẹ̀kọ́ Òtítọ́ Tó Dá Yín Lójú Mú Ṣinṣin, Oct.

  • “Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́,” Dec.

  • Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ Ní fún Ara Yín Túbọ̀ Jinlẹ̀, Jan.

  • Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kó Rẹ̀ Yín! Oct.

  • Ẹ Má Ṣe Máa Bá Ara Yín Díje, Àlàáfíà Ni Kí Ẹ Máa Wá, July

  • Ẹ Máa ‘Fetí sí Jésù,’ Dec.

  • Ẹ Máa Fetí sí Ohùn Olùṣọ́ Àgùntàn Rere, Dec.

  • Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn sí Ara Yín, Nov.

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Ṣe Ohun Tó Máa Jẹ́ Káwọn Míì Fọkàn Tán Yín Mar.

  • Ẹ̀yin Tẹ́ Ẹ Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ṣègbéyàwó, Ẹ Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà, Nov.

  • Fara Balẹ̀, Kó O sì Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Jan.

  • Fọkàn Balẹ̀, Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ, June

  • Ìfẹ́ Ń Jẹ́ Ká Lè Fara Da Ìkórìíra, Mar.

  • Jèhófà Máa Dáàbò Bò Ẹ́​—Lọ́nà Wo? Mar.

  • Jèhófà Máa Fún Ẹ Lókun, May

  • Jẹ́ Kí Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn Tó O Ní Máa Múnú Rẹ Dùn, Aug.

  • Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Tó O Ní fún Jèhófà Àtàwọn Ará Túbọ̀ Jinlẹ̀, Sept.

  • Jẹ́ Kí Ìtẹ̀síwájú Rẹ Máa Múnú Rẹ Dùn! July

  • Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ẹlẹ́dàá Wà, Aug.

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Lára “Ọmọ Ẹ̀yìn Tí Jésù Nífẹ̀ẹ́,” Jan.

  • Kí Ló Ń Fi Hàn Pé Ẹnì Kan Ti Ronú Pìwà Dà Tọkàntọkàn? Oct.

  • Kò Sí Ohun Tó Lè Mú Kí Olódodo Kọsẹ̀, May

  • Má Jẹ́ Kó Sú Ẹ Tó Bá Ṣòro Láti Wàásù Lágbègbè Yín, May

  • Má Ṣe Mú Kí “Àwọn Ẹni Kékeré Yìí” Kọsẹ̀ June

  • Máa Fi Hàn Pé O Mọyì Ìràpadà Nígbà Gbogbo, Apr.

  • Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Pé O Wà Nínú Ìdílé Jèhófà, Aug.

  • Mọyì Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Wà Nínú Ìjọ, Sept.

  • Mọyì Ipò Orí Tí Jèhófà Ṣètò Nínú Ìjọ, Feb.

  • Ǹjẹ́ O Mọyì Àwọn Àgbàlagbà Tó Wà Láàárín Wa, Sept.

  • Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn ti Àgùntàn Mìíràn Ń Yin Jèhófà àti Kristi, Jan.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àwọn Ọ̀rọ̀ Tí Jésù Sọ Kẹ́yìn, Apr.

  • Ohun Tí Ìwé Léfítíkù Kọ́ Wa Nípa Bó Ṣe Yẹ Ká Máa Ṣe Sáwọn Èèyàn, Dec.

  • O Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ìdẹkùn Èṣù! June

  • O Lè Jẹ́ Olóòótọ́ Tí Èèyàn Ẹ Kan Bá Fi Jèhófà Sílẹ̀, Sept.

  • “Orí Gbogbo Ọkùnrin Ni Kristi” Feb.

  • “Orí Obìnrin Ni Ọkùnrin”Feb.

  • O Ṣeyebíye Gan-an Lójú Jèhófà! Apr.

  • Ọlọ́run “Tí Àánú Rẹ̀ Pọ̀” Là Ń Sìn, Oct.

  • Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi, June

  • Ṣé Ìwọ Náà Lè Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn? July

  • Ṣé O Máa Ń Fara Dà Á Bíi Ti Jèhófà? July

  • Ṣé O Ní Ìgbàgbọ́ Tó Lágbára Tó? Nov.

  • Ṣé Wàá Dúró De Jèhófà? Aug.

  • Ṣé Wàá Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Nípa Jésù Mú Kó O Kọsẹ̀? May

  • “Tọ Ipasẹ̀ Rẹ̀ Pẹ́kípẹ́kí,” Apr.

BÍBÉLÌ

  • Báwo ni ọ̀rọ̀ tí wọ́n kọ sára òkúta kan láyé àtijọ́ ṣe fi hàn pé òótọ́ ni ọ̀rọ̀ inú Bíbélì? Jan.

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

  • Kí ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé: “Nípasẹ̀ òfin, mo ti di òkú sí òfin”? (Gál. 2:19), June

  • Kí ni òfin tó sọ pé ká má “dìde lòdì sí ẹ̀mí ẹnì kejì” wa túmọ̀ sí? (Léf. 19:16) Dec.

  • Kí nìdí tí Jésù fi sọ ohun tó wà nínú Sáàmù 22:1 ṣáájú ikú rẹ̀? Apr.

  • Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni máa ṣọ́ra tá a bá ń lo àwọn ètò ìṣiṣẹ́ tí wọ́n fi ń fọ̀rọ̀ ránṣẹ́? Mar.

  • Ṣé ó yẹ káwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa lo ìkànnì àwọn tó ń wá ọkọ tàbí ìyàwó láti wá ẹni tá a máa fẹ́? July

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

  • Jẹ́ Kí Àjọṣe Ìwọ àti Jèhófà Pa Dà Gún Régé, Oct.

  • Ṣé Alábàáṣiṣẹ́ Rere Ni Ẹ́? Dec.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

  • A Pinnu Pé A Ò Ní Kọ Iṣẹ́ Tí Jèhófà Bá Fún Wa (K. Logan), Jan.

  • Jèhófà ‘Mú Kí Àwọn Ọ̀nà Mi Tọ́’ (S. Hardy), Feb.

  • Mo Gbádùn Ayé Mi Gan-an Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà (J. Kikot), July

  • “Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Gan-an Lára Àwọn Míì!” (L. Breine), May

  • Mo Máa Ń Ro Ti Jèhófà Tí Mo Bá Ń Ṣèpinnu (D. Yazbek), June

  • Mò Ń Wá Bí Mo Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Tó Dáa (M. Witholt), Nov.

  • “Mo Ti Ń Gbádùn Iṣẹ́ Ìwàásù Báyìí!” (V. Vicini), Apr.

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

  • Arábìnrin Kan Rẹ́rìn-ín Músẹ́! Feb.

  • Kí ló ṣẹlẹ̀ sí ìlú Nínéfè lẹ́yìn ìgbà ayé Jónà? Nov.

  • Owó orí nígbà ayé Jésù, June

  • Wọ́n ń fi òrépèté ṣe ọkọ̀ ojú omi láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì, May

ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE

  • Ayé Tuntun Ti Dé Tán, No. 2

  • Kí Ló Lè Mú Kí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Dáa? No. 3

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbàdúrà? No. 1

JÍ!

  • Ewu Wo Ló Wà Nínú Ẹ̀rọ Ìgbàlódé? No. 2

  • Ẹ̀rí Wo Ló Fi Hàn Pé Ẹlẹ́dàá Wà? No. 3

  • Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dùn, No. 1