Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2022

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2022

Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ILÉ ÌṢỌ́ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • 1922​—Ní Ọgọ́rùn-Ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

  • ‘Aláyọ̀ Ni Àwọn Tó Jẹ́ Olóòótọ́ sí Jèhófà’, Oct.

  • Àwa Èèyàn Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Aug.

  • ‘Àwọn Tó Ń Wá Jèhófà Kò Ní Ṣaláìní Ohun Rere,’ Jan.

  • Bí Àsọtẹ́lẹ̀ Kan Tó Ti Pẹ́ Ṣe Kàn Ẹ́, July

  • Bí Ìfẹ́ Ṣe Lè Jẹ́ Ká Borí Ìbẹ̀rù, June

  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Jẹ́ Ká Fara Dà Á Ká sì Máa Láyọ̀, Nov.

  • Bí Ọkàn Ẹ Ṣe Lè Balẹ̀ Nígbà Rògbòdìyàn, Dec.

  • Bó O Ṣe Lè Ní Àfojúsùn Nínú Ìjọsìn Ọlọ́run Kí Ọwọ́ Ẹ sì Tẹ̀ Ẹ́, Apr.

  • Ẹ Máa “Gbé Ara Yín Ró,” Aug.

  • “Ẹ Máa Lo Àkókò Yín Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ,” Jan.

  • ‘Ẹ Máa Rìn Nínú Òtítọ́,’ Aug.

  • Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Máa Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù, Mar.

  • Ẹ̀yin Ìyá, Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Yùníìsì, Apr.

  • Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, May

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Tẹ̀ Síwájú Lẹ́yìn Tẹ́ Ẹ Ti Ṣèrìbọmi, Aug.

  • ‘Fetí Sí Ọ̀rọ̀ Ọlọgbọ́n’ Feb.

  • Fọkàn Tán Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Rẹ, Sept.

  • “Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà,” June

  • Ìdí Tá A Fi Ń Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi, Jan.

  • Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso! July

  • Ìjọsìn Tòótọ́ Máa Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Láyọ̀, Mar.

  • Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Táá Jẹ́ Káyé Wa Dùn, May

  • Jèhófà Fẹ́ Ká Wà Láàyè Títí Láé, Dec.

  • Jèhófà Fẹ́ Kó O Ní Ọgbọ́n Tòótọ́, Oct.

  • Jèhófà Máa Ń Bójú Tó Àwọn Èèyàn Rẹ̀, Aug.

  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ń Dárí Jini, June

  • Jèhófà Máa Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù, Nov.

  • Jẹ́ Kí Inú Ẹ Máa Dùn Bó O Ṣe Ń Ṣe Gbogbo Ohun Tó O Lè Ṣe fún Jèhófà, Apr.

  • Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Dá Ẹ Lójú, Oct.

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àbúrò Jésù, Jan.

  • Kí La Rí Kọ́ Nínú Bí Jésù Ṣe Sunkún?, Jan.

  • Kò Sẹ́ni Tó Lè Dárí Jini Bíi Ti Jèhófà, June

  • Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Mú Kó O Fi Jèhófà Sílẹ̀, Nov.

  • Máa Fi “Ìwà Tuntun” Wọ Ara Rẹ Láṣọ Lẹ́yìn Tó O Ti Ṣèrìbọmi, Mar.

  • Máa Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Bíi Ti Jésù, Feb.

  • Máa Ronú Bó Ṣe Tọ́ Tí Nǹkan Kan Bá Dán Ìgbàgbọ́ Ẹ Wò, Nov.

  • Máa Ṣohun Táá Jẹ́ Káwọn Èèyàn Fọkàn Tán Ẹ, Sept.

  • Máa Ti Jésù Alábòójútó Wa Lẹ́yìn, July

  • Mọyì Àǹfààní Tí Jèhófà Fún Ẹ Láti Máa Gbàdúrà, July

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwé Ìfihàn, May

  • Ohun Tí Ìwé Ìfihàn Sọ Nípa Ọjọ́ Iwájú, May

  • Ohun Tí Ìwé Ìfihàn Sọ Pé Ó Máa Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Ọ̀tá Ọlọ́run, May

  • O Lè “Bọ́ Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀,” Mar.

  • O Lè Ní Ayọ̀ Tòótọ́, Oct.

  • “O Máa Wà Pẹ̀lú Mi Ní Párádísè,” Dec.

  • Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Fara Dà Á Nígbà Ìṣòro, Dec.

  • Ṣé Bó O Ṣe Ń Gba Àwọn Èèyàn Nímọ̀ràn ‘Máa Ń Mú Ọkàn Wọn Yọ̀?’ Feb.

  • Ṣé O Gbà Pé Ohun Tó Tọ́ Ni Jèhófà Máa Ń Ṣe? Feb.

  • Ṣé Ò Ń Rí Ohun Tí Sekaráyà Rí? Mar.

  • Ṣé Orúkọ Ẹ Wà Nínú “Ìwé Ìyè”? Sept.

  • Ṣé Ọ̀rọ̀ Ẹnu Ẹ Máa Ń Tu Àwọn Èèyàn Lára? Apr.

  • ‘Wọ́n Ń Sọ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Di Olódodo’ Sept.

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

  • Àwọn wo ni Jèhófà máa jí dìde sí ayé, irú àjíǹde wo ni wọ́n sì máa ní? Sept.

  • Kí ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ẹni tí a bí ní kògbókògbó” lòun? (1Kọ 15:8), Sept.

  • Kí ni Jésù ń sọ nígbà tó ní: “Ẹ má rò pé mo wá láti mú àlàáfíà wá”? (Mát. 10:34, 35), July

  • Kí nìdí tí Dáfídì fi “ṣàánú Méfíbóṣétì” síbẹ̀ tí Dáfídì tún ní kí wọ́n pa Méfíbóṣétì? (2Sa 21:7-9), Mar.

  • Ṣé àsọdùn ni Dáfídì sọ nínú Sáàmù 61:8 nígbà tó sọ pé òun á máa yin orúkọ Ọlọ́run “títí láé”? (Sm 61:8), Dec.

  • Ṣé Bíbélì sọ pé kéèyàn máa búra? Apr.

  • Tí Kristẹni kan bá kọ ìyàwó ẹ̀ sílẹ̀ lọ́nà tí kò bá Ìwé Mímọ́ mu, tó sì fẹ́ ẹlòmíì, irú ojú wo ló yẹ kí ìjọ fi wo ìgbéyàwó tó kọ́kọ́ ṣe àti ìgbéyàwó tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe?, Apr.

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

  • Bó O Ṣe Lè Máa Fara Dà Á Tó O Bá Ní Ìdààmú Ọkàn, Apr.

  • Jẹ́ Kí “Òfin Inú Rere” Máa Darí Rẹ, June

  • Kí Nìdí Táwa Kristẹni Kì í Fi í Jagun Báwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Àtijọ́ Ṣe Jagun? Oct.

  • Ṣé O Ti Múra Tán Láti “Jogún Ayé”? Dec.

  • Wọ́n Fún Àwọn Ajá Mi Ní Bisikíìtì (ìwàásù níbi ìpàtẹ ìwé), Apr.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

  • “Iṣẹ́ Jèhófà Ni Mo Fẹ́ Fayé Mi Ṣe” (D. van Marl), Nov.

  • Mo Gbádùn Bí Mo Ṣe Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Jèhófà àti Bí Mo Ṣe Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn Nípa Ẹ̀ (L. Weaver, Jr.), Sept.

  • Mo Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Mi Sọ́nà (K. Eaton), July

  • Mo Rí Ohun Tó Dáa Ju Iṣẹ́ Dókítà Lọ (R. Ruhlmann), Feb.

ǸJẸ́ O MỌ̀?

  • Kí nìdí táwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́ fi máa ń san owó orí ìyàwó? Feb.

  • Kí nìdí tí Jèhófà fi gbà káwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa fi ẹyẹ oriri àti ẹyẹlé rúbọ? Feb.

  • Nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, báwo ni wọ́n ṣe ń ka oṣù àti ọdún? June

  • Ṣé àwọn ará Róòmù máa ń gbà kí wọ́n sin òkú ẹni tí wọ́n pa sórí òpó igi, irú bí wọ́n ṣe pa Jésù? June

  • Ṣé ẹni tó ń jẹ́ Módékáì wà lóòótọ́? Nov.

ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE

  • Bá A Ṣe Lè Borí Ìkórìíra, No. 1

JÍ!

  • Ayé Dojú Rú​—Kí Lọ̀nà Àbáyọ?, No. 1