ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ December 2023

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 5–March 3, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 50

Ìgbàgbọ́ àti Iṣẹ́ Máa Sọ Ẹ́ Di Olódodo

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 5-11, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 51

Ìrètí Tó O Ní Ò Ní Já Ẹ Kulẹ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 12-18, 2024.

Ṣé Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ọtí Lo Fi Ń Wò Ó?

Àwọn kan máa ń mutí, àwọn kan sì ti pinnu pé àwọn ò ní mu ún. Kí ni ò ní jẹ́ kí Kristẹni kan kó síṣòro tí àwọn tó ń mutí jù máa ń kó sí?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 52

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́bìnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 19-25, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 53

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 26–March 3, 2024.

Ǹjẹ́ O Rántí?

Nígbà tó o ka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lọ́dún yìí, ṣó o gbádùn ẹ̀? Wò ó bóyá wàá lè dáhùn àwọn ìbéèrè yìí.

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2023

Atọ́ka gbogbo àkòrí tó jáde nínú Ilé Ìṣọ́ àti Jí! ọdún 2023.

Ìrírí

Báwo ni arábìnrin kan ṣe fàánú hàn sáwọn èèyàn, tó sì lo àǹfààní yẹn láti wàásù fún wọn?