Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2023

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2023

Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ILÉ ÌṢỌ́ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • Máa Fàánú Hàn sí Gbogbo Èèyàn, Dec.

  • 1923—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.

  • Ọwọ́ Hulda Tẹ Ohun Tó Ń Wá, Nov.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

  • “Arákùnrin Rẹ Máa Dìde”! Apr.

  • Àwọn Nǹkan Tó O Máa Ṣe Kó O Lè Ṣèrìbọmi, Mar.

  • Bá A Ṣe Lè Mú Kí Ìfẹ́ Tá A Ní Sáwọn Ará Túbọ̀ Lágbára, Nov.

  • Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wa Túbọ̀ Lágbára Pé Ayé Tuntun Máa Dé? Apr.

  • Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Dáhùn Àdúrà Wa?, May

  • Bíi Ti Pétérù, Má Jẹ́ Kó Sú Ẹ, Sept.

  • Bó O Ṣe Lè Mọyì Ìwàláàyè Tí Ọlọ́run Fún Ẹ, Feb.

  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Àdúrà Ẹ Sunwọ̀n Sí I, May

  • Bó O Ṣe Lè Túbọ̀ Jàǹfààní Tó O Bá Ń Ka Bíbélì, Feb.

  • “Èyí Ni Gbogbo Èèyàn Máa Fi Mọ̀ Pé Ọmọ Ẹ̀yìn Mi Ni Yín,” Mar.

  • “Ẹ Dúró Gbọn-in, Ẹ Má Yẹsẹ̀,” July

  • Ẹ Máa Gba Ara Yín Níyànjú Nípàdé Ìjọ, Apr.

  • Ẹ Máa Múra Sílẹ̀ De Ọjọ́ Jèhófà, June

  • Ẹ Máa Ní Sùúrù, Aug.

  • “Ẹ Máa Ronú Bó Ṣe Tọ́, Ẹ Wà Lójúfò!” Feb.

  • “Ẹ Para Dà Nípa Yíyí Èrò Inú Yín Pa Dà,” Jan.

  • Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Gídíónì, June

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Báwo Lẹ Ṣe Fẹ́ Káyé Yín Rí? Sept.

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́bìnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín, Dec.

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín, Dec.

  • Ẹ̀yin Tọkọtaya, Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Yín Dà Bí “Ọwọ́ Iná Jáà”, May

  • Gbé Ẹrù Tó Yẹ Kó O Gbé, Kó O sì Ju Èyí Tí Ò Yẹ Nù, Aug.

  • Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Bíi Ti Sámúsìn, Sept.

  • “Ìfẹ́ Tí Kristi Ní Sọ Ọ́ Di Dandan fún Wa,” Jan.

  • Ìgbàgbọ́ àti Iṣẹ́ Máa Sọ Ẹ́ Di Olódodo, Dec.

  • Ìrètí Tó O Ní Ò Ní Já Ẹ Kulẹ̀, Dec.

  • Jèhófà Fi Dá Wa Lójú Pé Òun Máa Sọ Ayé Di Párádísè, Nov.

  • Jèhófà Máa Jẹ́ Kó O Ṣàṣeyọrí, Jan.

  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Wa Tá A Bá Ṣe Ìrántí Ikú Kristi, Jan.

  • Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Ìṣòro Tó Dé Bá Ẹ, Apr.

  • ‘Jèhófà Máa Sọ Ẹ́ Di Alágbára’ Oct.

  • Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nígbà Ìṣòro, Nov.

  • Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Òtítọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, Jan.

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Dáníẹ́lì, Aug.

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Lẹ́tà Méjì Tí Pétérù Kọ, Sept.

  • Kí La Rí Kọ́ Nínú Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Tí Jésù Ṣe? Apr.

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Bẹ̀rù Jèhófà? June

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ṣèrìbọmi? Mar.

  • Máa Fi Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Dá Kọ́ Ọmọ Rẹ, Mar.

  • Máa Fòye Báni Lò Bíi Ti Jèhófà, July

  • Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Jinlẹ̀, Oct.

  • Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Jọ́sìn Jèhófà Nínú Tẹ́ńpìlì Tẹ̀mí, Oct.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì, Aug.

  • Ohun Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Sọ Nípa Ẹni Tó Ni Bíbélì, Feb.

  • “Ọ̀nà Ìjẹ́mímọ́” May

  • Ọwọ́ Ẹ Tẹ Àwọn Àfojúsùn Ẹ, May

  • Ṣé Jèhófà Máa Dáhùn Àdúrà Mi? Nov.

  • Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ De Ìpọ́njú Ńlá? July

  • Ṣé O “Ṣe Tán Láti Ṣègbọràn”? Oct.

  • Tó O Bá Ní Ìwà Tútù, Wàá Di Alágbára, Sept.

  • Túbọ̀ Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Jèhófà Lára Àwọn Nǹkan Tó Dá, Mar.

  • Túbọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Àtàwọn Ará, July

  • Wàá Jàǹfààní Tó O Bá Ń Bẹ̀rù Ọlọ́run, June

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

  • Báwo ni àpilẹ̀kọ náà “Kí Orúkọ Rẹ Di Mímọ́” nínú Ilé Ìṣọ́ June 2020 ṣe ṣàlàyé ohun tá a gbà gbọ́ nípa orúkọ Jèhófà àti bó ṣe jẹ́ Ọba Aláṣẹ Ayé Àtọ̀run? Aug.

  • Kí nìdí tí Jósẹ́fù àti Màríà ò fi kúrò ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù? June

  • Kí nìdí tí ọkùnrin tí Bíbélì pè ní “Èèyàn mi” fi sọ pé òun máa “run” ogún òun tí òun bá fẹ́ Rúùtù? (Rúùtù 4:1, 6), Mar.

  • Ṣé mánà àti àparò nìkan làwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ nígbà tí wọ́n wà ní aginjù? Oct.

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

  • Ṣé Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ọtí Lo Fi Ń Wò Ó?, Dec.

  • Tí Ọkọ Tàbí Aya Kan Bá Ń Wo Àwòrán Ìṣekúṣe, Aug.

  • Wọ́n Fìfẹ́ Hàn sí Wọn Gan-an, Feb.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

  • Jèhófà Dáàbò Bò Mí Torí Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé E (I. Itajobi), Nov.

  • Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà, Ó sì Ṣe Ohun Tó Yà Mí Lẹ́nu (R. Kesk), June

  • Mo Ti Rí i Pé Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Tó Nígbàgbọ́ (R. Landis), Feb.

  • Tá A Bá Ń Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́, A Máa Jàǹfààní Ẹ̀ Títí Láé (R. Reid), July

ǸJẸ́ O MỌ̀?

  • Báwo ni àwọn bíríkì tí wọ́n rí ní Bábílónì àtijọ́ tó ti di àwókù àti bí wọ́n ṣe ṣe bíríkì náà ṣe jẹ́rìí sí i pé àkọsílẹ̀ Bíbélì jóòótọ́? July

OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́

  • Àwọn Àpilẹ̀kọ Míì Nínú Ilé Ìṣọ́ (JW Library®), June

  • Àwọn Nǹkan Tá A Lè Fi Kọ́ Àwọn Ọmọdé (jw.org), Sept.

  • Àwọn Ohun Tá A Lè Fi Ṣèwádìí Lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ™ ti Watchtower, May

  • Bá A Ṣe Lè Lo Abala “Ohun Tuntun” Lọ́nà Tó Dáa (JW Library® àti jw.org), Mar.

  • Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Àwọn Òye Tuntun Tá A Ní (Watch Tower Publications Index tàbí Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà), Oct.

  • Bó O Ṣe Lè Wá Àwọn Àpilẹ̀kọ Tó Máa Ń Wà Níbẹ̀rẹ̀ Jw.Org (jw.org), Feb.

  • Ìtàn ìgbésí ayé àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa, Jan.

  • Máa jàǹfààní látinú àwọn ẹsẹ Bíbélì tá a ṣàlàyé nínú Ìwé Ìwádìí, Apr.

  • Mọ Àwọn Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe, July

  • Mọ “Àwọn Orin Ẹ̀mí” Sórí (jw.org), Nov.

  • Wá Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Nípa Jèhófà (Watch Tower Publications Index tàbí Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà), Aug.

ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE

  • Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìlera Ọpọlọ, No. 1

JÍ!

  • Àwọn Èèyàn Ti Ba Ayé Yìí Jẹ́ Gan-an! Ṣé Ọ̀nà Àbáyọ Wà, No. 1