ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ December 2024
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 3–March 2, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 48
Ohun Tá A Kọ́ Nígbà Tí Jésù Pèsè Búrẹ́dì Lọ́nà Ìyanu
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 3-9, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 49
Kí Ló Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 10-16, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 50
Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Túbọ̀ Lágbára
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 17-23, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 51
Jèhófà Mọ Ohun Tó Ń Pa Ẹ́ Lẹ́kún
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 24–March 2, 2025.
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Gbogbo Ìgbà Ni Mò Ń Kẹ́kọ̀ọ́
Arákùnrin Joel Adams sọ ohun tó ràn án lọ́wọ́ láti fara dà á, tó sì jẹ́ kó máa láyọ̀ bó ṣe ń ṣiṣẹ́ ìsìn Jèhófà fún ohun tó ju ọgọ́rin (80) ọdún lọ.
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Àwọn wo ni “àwọn áńgẹ́lì àyànfẹ́” tí 1 Tímótì 5:21 sọ̀rọ̀ nípa wọn?
Ǹjẹ́ O Rántí?
Nígbà tó o ka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lọ́dún yìí, ṣó o gbádùn ẹ̀? Wò ó bóyá wàá lè rántí ohun tó o kà.
Àwọn Olóòótọ́ Ìránṣẹ́ Jèhófà Máa Ń San Ẹ̀jẹ́ Wọn
Ẹ̀kọ́ wo la lè kọ́ lára Jẹ́fútà àti ọmọbìnrin ẹ̀?