ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ February 2025

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 14–May 4, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 6

A Mọyì Ẹ̀ Gan-an Pé Jèhófà Ń Dárí Jì Wá

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 14-20, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 7

Àǹfààní Tá À Ń Rí Tí Jèhófà Bá Dárí Jì Wá

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 21-27, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 8

Bá A Ṣe Lè Máa Dárí Ji Ara Wa Bí Jèhófà Ṣe Ń Dárí Jì Wá

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 28–May 4, 2025.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

“Mo Dá Wà, àmọ́ Jèhófà Wà Pẹ̀lú Mi”

Wo ìdí tí Angelito Balboa fi gbà pé Jèhófà wà pẹ̀lú òun ní gbogbo ìgbà, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó láwọn ìṣòro tó le.

Má Fìwà Jọ Àwọn Tó Mọ Tara Wọn Nìkan

Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń rò pé àwọn sàn ju àwọn mí ì lọ, wọ́n máa ń fẹ́ kí wọ́n fún wọn nípò pàtàkì láwùjọ, wọ́n sì máa ń rò pé ohun kan tọ́ sí àwọn. Wo àwọn ìlànà Bíbélì tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ò ní jẹ́ kó o nírú èrò yẹn.

Bá A Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Tòótọ́

Bíbélì sọ pé ọ̀rẹ́ tòótọ́ wúlò gan-an nígbà ìṣòro.

Ìbéèrè Ṣókí Tó Lè Mú Káwọn Èèyàn Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Bíi ti Mary, ìwọ náà lè bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó o bá ń béèrè ìbéèrè ṣókí.

Máa Fìgboyà Ṣe Ohun Tó Tọ́

Báwo lo ṣe lè ní ìgboyà bíi Jeremáyà àti Ebedi-mélékì?