ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ January 2024
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 4–April 7, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1
Tó O Bá Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Wàá Borí Ìbẹ̀rù
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 4-10, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2
Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ De Ọjọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ́dún?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 11-17, 2024.
Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Obìnrin Lo Fi Ń Wò Wọ́n?
Láìka ibi tí arákùnrin kan dàgbà sí, ó lè fi ojú tí Jèhófà fi ń wo àwọn obìnrin wò wọ́n, kó sì máa bọ̀wọ̀ fún wọn.
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Irú ohun ìrìnnà wo ni ìjòyè Etiópíà wà nínú ẹ̀ nígbà tí Fílípì lọ bá a?
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3
Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nígbà Ìṣòro
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 25-31, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4
Jèhófà Ní Ìfẹ́ Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ Sí Ẹ
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 1-7, 2024.