ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ January 2025

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 3–​April 6, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1

Ẹ Máa Yin Jèhófà Lógo

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 3-9, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2

Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Máa Bọlá fún Ìyàwó Yín

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 10-16, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3

Máa Ṣe Ìpinnu Táá Múnú Jèhófà Dùn

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 17-23, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4

Kí La Kọ́ Nínú Ìràpadà Tí Jésù Ṣe?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 24-30, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 5

Bá A Ṣe Ń Jàǹfààní Ìfẹ́ Tí Jèhófà Fi Hàn sí Wa

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní March 31–​April 6, 2025.

Àwòrán Ń Jẹ́ Ká Rántí Ohun Tá A Kọ́

Tó o bá ń yàwòrán ohun tó ò ń kọ́ sórí ìwé, wàá túbọ̀ máa rántí ẹ̀.