ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ July 2018
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 3 sí 30, 2018 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
WỌ́N YỌ̀ǸDA ARA WỌN TINÚTINÚ
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Myanmar
Kí ló mú kí ọ̀pọ̀ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi ìlú wọn sílẹ̀ kí wọ́n lè ṣe nínú iṣẹ́ ìkórè tó ń lọ ní Myanmar?
Ojúure Ta Lò Ń Wá?
Kí la rí kọ́ látinú bí Jèhófà ṣe fojúure hàn sáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́?
Ṣé Jèhófà Lo Tẹjú Mọ́?
A lè kọ́ ẹ̀kọ́ pàtàkì nínú àṣìṣe tí Mósè ṣe.
“Ta Ni Ó Wà ní Ìhà Ọ̀dọ̀ Jèhófà?”
Ìtàn Kéènì, Sólómọ́nì, Mósè àti Áárónì jẹ́ ká rí i pé ìwà ọgbọ́n ló jẹ́ láti wà ní ìhà ọ̀dọ̀ Jèhófà.
A Jẹ́ ti Jèhófà
Ọ̀nà wo la lè gbà dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún àǹfààní tó fún wa láti jẹ́ èèyàn rẹ̀?
Máa Fàánú Hàn sí “Gbogbo Onírúurú Ènìyàn”
O lè fara wé Jèhófà tó o bá ń fàánú hàn sáwọn tó níṣòro, tó o sì ń ṣe gbogbo ohun tó o lè ṣe láti ràn wọ́n lọ́wọ́.
Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Gbádùn Mọ́ Ẹ Kó sì Ṣe Ẹ́ Láǹfààní
Wàá rí àwọn ìṣúra tẹ̀mí.
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Ṣé a lè sọ pé àwọn méjì tí kì í ṣe tọkọtaya ti dẹ́ṣẹ̀ tó burú jáì tí wọ́n bá jọ sún inú ilé kan náà mọ́jú lábẹ́ ipò tí ń kọni lóminú?