ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ July 2023
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 11–October 8, 2023 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 29
Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ De Ìpọ́njú Ńlá?
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní September 11-17, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 30
Túbọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Àtàwọn Ará
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní September 18-24, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 31
“Ẹ Dúró Gbọn-in, Ẹ Má Yẹsẹ̀”
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní September 25–October 1, 2023.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 32
Máa Fòye Báni Lò Bíi Ti Jèhófà
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní October 2-8, 2023.
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Tá A Bá Ń Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́, A Máa Jàǹfààní Ẹ̀ Títí Láé
Ìtàn Ìgbésí Ayé: Arákùnrin Russell Reid