ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ June 2021 Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 2-29, 2021 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí. Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi Fọkàn Balẹ̀, Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ O Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ìdẹkùn Èṣù! Má Ṣe Mú Kí “Àwọn Ẹni Kékeré Yìí” Kọsẹ̀ Ǹjẹ́ O Mọ̀? ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ Mo Máa Ń Ro Ti Jèhófà Tí Mo Bá Ń Ṣèpinnu Ìtàn ìgbésí ayé: Dyah Yazbek Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé