ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ November 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní January 6–​February 2, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 44

Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 6-12, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 45

Kí La Kọ́ Nínú Ohun Táwọn Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Kí Wọ́n Tó Kú?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 13-19, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 46

Ẹ̀yin Arákùnrin, Ṣé Ẹ̀ Ń Ṣiṣẹ́ Kára Kẹ́ Ẹ Lè Di Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 20-26, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 47

Ẹ̀yin Arákùnrin, Ṣé Ẹ̀ Ń Ṣiṣẹ́ Kára Kẹ́ Ẹ Lè Di Alàgbà?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 27–​February 2, 2025.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Fún Wa Lókun Lákòókò Ogun àti Lákòókò Àlàáfíà

Paul àti Anne Crudass sọ bí Jèhófà ṣe fún wọn lókun lákòókò ogun àti nígbà ìṣòro.

Ohun Tó O Lè Ṣe Kó O Lè Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Déédéé

Àwọn àbá mẹ́rin tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ táá jẹ́ kó o máa kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì déédéé, kó o sì máa gbádùn ẹ̀.

Wá Ibi Tó Dáa Tó O Ti Lè Kẹ́kọ̀ọ́

Wo nǹkan mẹ́ta tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ táá jẹ́ kó o túbọ̀ fọkàn sí àwọn nǹkan tó ò ń kọ́.