ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ October 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti December 9, 2024–​January 5, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

1924—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn

Lọ́dún 1924, àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ṣe irinṣẹ́ tí wọ́n á fi máa wàásù ìhìn rere Ìjọba náà.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 40

Jèhófà “Ń Mú Àwọn Tó Ní Ọgbẹ́ Ọkàn Lára Dá”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 9-15, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 41

Àwọn Nǹkan Tá A Kọ́ Lára Jésù ní Ogójì Ọjọ́ Tó Lò Kẹ́yìn Láyé

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 16-22, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 42

Máa Fi Hàn Pé O Mọyì “Àwọn Ẹ̀bùn Tí Ó Jẹ́ Èèyàn”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 23-29, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 43

Bó O Ṣe Lè Borí Èrò Tí Ò Tọ́

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 30, 2024–​January 5, 2025.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Báwo ni orin ti ṣe pàtàkì tó nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Báwo ni ibi àbáwọlé tó wà níwájú tẹ́ńpìlì tí Sólómọ́nì kọ́ ṣe ga tó?

Máa Ṣàtúnyẹ̀wò Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Tó O Kọ́

Ṣé ó ti ṣe ẹ́ rí pé o ò rántí ohun tó o ṣẹ̀ṣẹ̀ kọ́? Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́?