ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti October 24 sí November 27, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

‘Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Rọ Jọwọrọ’

Báwo ni Jèhófà ṣe ń fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lókun tó sì ń fún wọn níṣìírí? Báwo ni ìwọ náà ṣe lè ṣe bẹ́ẹ̀?

Máa Jà Fitafita Kó O Lè Rí Ìbùkún Jèhófà

Ọ̀pọ̀ nǹkan làwọn èèyàn Ọlọ́run ń kojú bí wọ́n ṣe ń tiraka láti rí ojúure Ọlọ́run. Síbẹ̀ wọ́n á mókè!

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Kí ni “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” tí Hébérù 4:​12 sọ pé ó “yè, ó sì ń sa agbára”?

À Ń Gbèjà Ìhìn Rere Níwájú Àwọn Aláṣẹ

A lè kẹ́kọ̀ọ́ látinú bí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ṣe gbèjà ara rẹ̀ nígbà ayé rẹ̀.

Ǹjẹ́ Ìmúra Rẹ Ń Fògo fún Ọlọ́run?

Àwọn ìlànà Bíbélì máa tọ́ wa sọ́nà.

Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Tọ́ Ẹ Sọ́nà

Àwọn Ẹlẹ́rìí tó wà ní Poland àti Fíjì ṣèpinnu tó bọ́gbọ́n mu.

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Mú Kí Ìgbàgbọ́ Yín Túbọ̀ Lágbára

Ṣé àwọn mí ì máa ń fẹ́ kó o tẹ̀ síbi táyé tẹ̀ sí, kó o gbà pé ẹfolúṣọ̀n ló mú káwọn nǹkan wà dípò Ẹlẹ́dàá? Tó bá rí bẹ́ẹ̀, àpilẹ̀kọ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Káwọn Ọmọ Yín Nígbàgbọ́

Ṣé ó máa ń ṣe ẹ́ bíi pé o ò ní lè tọ́ àwọn ọmọ rẹ yanjú? Àwọn kókó mẹ́rin yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ gan-⁠an.