ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2018

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti October 29 sí December 2, 2018 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí

“Bí Ẹ Bá Mọ Nǹkan Wọ̀nyí, Aláyọ̀ Ni Yín Bí Ẹ Bá Ń Ṣe Wọ́n”

Àwọn ọ̀nà wo la lè gbà fi hàn pé a lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀, kí sì nìdí tíyẹn fi ṣe pàtàkì?

Ẹ̀yin Àgbàlagbà​—Jèhófà Mọyì Iṣẹ́ Yín

Báwo làwọn alàgbà tó jẹ́ àgbàlagbà ṣe fi hàn pé àwọn lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀?

Ẹ Máa Fìfẹ́ Gbé Àwọn Míì Ró

Kọ́ bó o ṣe lè gbé àwọn míì ró láwọn àsìkò tí nǹkan le yìí.

Aláyọ̀ Ni Àwọn Tó Ń Sin “Ọlọ́run Aláyọ̀”

Kí ló máa jẹ́ ká láyọ̀ láìka gbogbo ìṣòro tó wà nínú ayé Sátánì yìí sí?

Ǹjẹ́ O Mọ Ohun Tí Aago Sọ?

Báwo làwọn èèyàn ṣe ń mọ àkókò láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì?

Alágbára Ńlá Ni Jèhófà, Síbẹ̀ Ó Ń Gba Tẹni Rò

Báwo ni Jèhófà ṣe fi àpẹẹrẹ tó dáa lélẹ̀ tó bá di pé ká gba tàwọn míì rò?

Máa Gba Tàwọn Míì Rò Bíi Ti Jèhófà

Wàá rí àwọn ọ̀nà tó o lè gbà fi ìgbatẹnirò hàn nínú ìdílé, nínú ìjọ àti lóde ẹ̀rí.