ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2022
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti November 7–December 4, 2022 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 37
Fọkàn Tán Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Rẹ
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 38
Máa Ṣohun Táá Jẹ́ Káwọn Èèyàn Fọkàn Tán Ẹ
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 39
Ṣé Orúkọ Ẹ Wà Nínú “Ìwé Ìyè”?
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 40
‘Wọ́n Ń Sọ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Di Olódodo’
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Àwọn wo ló máa jí dìde sí ayé, irú àjíǹde wo sì ni wọ́n máa ní?
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Kí ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ẹni tí a bí ní kògbókògbó” lòun? (1 Kọ́ríńtì 15:8)
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Mo Gbádùn Bí Mo Ṣe Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Jèhófà àti Bí Mo Ṣe Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn Nípa Ẹ̀
Ìtàn Ìgbésí Ayé: Leon Weaver, Jr.