ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti November 11–​December 8, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 36

“Ẹ Máa Ṣe Ohun Tí Ọ̀rọ̀ Náà Sọ”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 11-17, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 37

Lẹ́tà Tó Máa Mú Ká Jẹ́ Olóòótọ́, Ká sì Fara Dà Á Dópin

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 18-24, 2024.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Bù Kún Mi Gan-an Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Ẹ̀

Arákùnrin André Ramseyer ti lo àádọ́rin (70) ọdún lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún, wọ́n sì ti gbádùn ọ̀pọ̀ àǹfààní lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn náà. Àwọn ìṣòro wo ni wọ́n ní, báwo ni wọ́n sì ṣe fi Jèhófà sípò àkọ́kọ́ láyé wọn?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ní alẹ́ ọjọ́ tí Jésù dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀, ibo làwọn àádọ́rin (70) ọmọlẹ́yìn tó rán jáde lọ wàásù wà? Ṣé wọ́n ti sá fi Jésù sílẹ̀ ni?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 38

Ṣé O Ò Gbàgbé Ìkìlọ̀ Jésù?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní November 25–December 1, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 39

Wàá Túbọ̀ Láyọ̀ Tó O Bá Ń Fún Àwọn Èèyàn Ní Nǹkan

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 2-8, 2024.

Máa Kọ́ Ohun Tuntun Tó O Bá Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Báwo ni ohun tí Jèhófà ń kọ́ wa se lè túbọ̀ yé wa tá a bá ń dá kẹ́kọ̀ọ́?