Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2019

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2019

Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • 1919​—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.

  • Ẹnì Kan Ṣẹ̀ṣẹ̀ Di Ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí (K. Cook, Jr.), Jan.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

  • “A Kò Juwọ́ Sílẹ̀”! Aug.

  • Àwọn Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwé Léfítíkù, Nov.

  • “Àwọn Tó Ń Fetí Sí Ọ” Máa Rí Ìgbàlà, Aug.

  • Bá A Ṣe Lè Pèsè Ìtùnú fún Àwọn Tí Wọ́n Bá Lò Pọ̀ Nígbà Tí Wọ́n Wà Lọ́mọdé, May

  • Bá A Ṣe Lè Wàásù fún Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan, July

  • Báwo Lo Ṣe Lè Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ? Jan.

  • Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́, Nov.

  • Bó O Ṣe Lè Láyọ̀ Tí Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ Bá Yí Pa Dà, Aug.

  • Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Yín Máa Pọ̀ Sí I, Aug.

  • ‘Ẹ Lọ, Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn,’ July

  • “Ẹ Parí Ohun Tí Ẹ Ti Bẹ̀rẹ̀,” Nov.

  • ‘Ẹ Ṣọ́ra Kí Ẹnikẹ́ni Má Bàa Mú Yín Lẹ́rú!’ June

  • “Ẹ Wá Sọ́dọ̀ Mi, . . . Màá sì Tù Yín Lára,” Sept.

  • Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, Dec.

  • Fara Wé Jésù Kó O Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn, Apr.

  • Fetí sí Ohùn Jèhófà, Mar.

  • Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ìdààmú Ọkàn, June

  • Ìfẹ́ àti Ìdájọ́ Òdodo Nílẹ̀ Ísírẹ́lì Àtijọ́, Feb.

  • Ìfẹ́ àti Ìdájọ́ Òdodo Nínú Ìjọ Kristẹni, May

  • Ìròyìn Ayọ̀ Ni Amágẹ́dọ́nì! Sept.

  • Ìsinsìnyí Gan-An Ni Kó O Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Múra Sílẹ̀ fún Inúnibíni, July

  • Jèhófà Ló Ń Fúnni Ní Òmìnira, Dec.

  • Jèhófà Mọyì Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Tó Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀, Sept.

  • Jèhófà Nìkan Ṣoṣo Ni Kó O Máa Jọ́sìn, Oct.

  • Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Borí Àwọn Ẹ̀mí Èṣù, Apr.

  • Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Dí Ní “Apá Ìgbẹ̀yìn Àwọn Ọjọ́” Yìí Oct.

  • Jẹ́ Olóòótọ́ Lákòókò “Ìpọ́njú Ńlá,” Oct.

  • Jẹ́ Ọlọ́kàn Tútù Kó O Lè Múnú Jèhófà Dùn, Feb.

  • Kí Ló Ń Dá Mi Dúró Láti Ṣèrìbọmi? Mar.

  • Kí Ni Jèhófà Máa Mú Kó O Dì? Oct.

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fi Ìmoore Hàn? Feb.

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó Máa Yá Wa Lára Láti Fi Ara Wa Sábẹ́ Jèhófà? Sept.

  • Má Ṣe Jẹ́ Kí “Ọgbọ́n Ayé Yìí” Nípa Lórí Rẹ, May

  • “Má Wò Yí Ká, Nítorí Èmi Ni Ọlọ́run Rẹ,” Jan.

  • Máa Fi Ìfẹ́ Hàn sí Àwọn Tí Wọ́n Hùwà Ìkà Sí, Kó O sì Máa Ṣèdájọ́ Òdodo, May

  • Máa Gba Tàwọn Èèyàn Rò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù, Mar.

  • Máa Gba Tàwọn Míì Rò, Mar.

  • Máa Hùwà Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo! Feb.

  • Máa Sin Jèhófà Nìṣó Tí Wọ́n Bá Tiẹ̀ Fòfin De Iṣẹ́ Wa, July

  • Máa Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tó Ní Ìdààmú Ọkàn, June

  • Máa Yin Jèhófà Nínú Ìjọ, Jan.

  • Mú Kí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I! May

  • Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Ará Kí Òpin Tó Dé, Nov.

  • Ǹjẹ́ Ò Ń Ṣe Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Láṣeyanjú? Apr.

  • Ó Yẹ Ká Ní Àkókò fún Iṣẹ́ àti Ìsinmi, Dec.

  • Ohun Tí Ètò Ráńpẹ́ Kan Kọ́ Wa Nípa Jésù Ọba Wa, Jan.

  • Ohun Tí Lílọ sí Ìpàdé Ń Sọ Nípa Wa, Jan.

  • Rọ̀ Mọ́ Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ipò Táwọn Òkú Wà, Apr.

  • Ṣé Ó Dá Ẹ Lójú Pé O Mọ Jèhófà? Dec.

  • Ṣé Ò Ń Bójú Tó “Apata Ńlá Ti Ìgbàgbọ́” Rẹ? Nov.

  • Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kó O Borí Gbogbo Ìrònú Tí Kò Bá Ìmọ̀ Ọlọ́run Mu! June

  • ‘Wò Ó! Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn,’ Sept.

BÍBÉLÌ

  • Àkájọ Ìwé Àtijọ́ Kan, June

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

  • Ṣé ọgbà Édẹ́nì ni ẹ̀kọ́ àìleèkú ọkàn ti bẹ̀rẹ̀? (Jẹ 3:4), Dec.

  • Tí ọkùnrin kan bá fipá bá ọ̀dọ́bìnrin kan lòpọ̀ ní “inú oko,” kí nìdí tó fi jẹ́ pé ọkùnrin yẹn nìkan ló jẹ̀bi, nígbà tí ẹlẹ́rìí ò pé méjì? (Di 22:​25-27), Dec.

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

  • Àpẹẹrẹ Ẹnì Kan Tó Láyọ̀ Láìka Ìyípadà Tó Dé Bá A (Jòhánù Arinibọmi), Aug.

  • “Ẹ Máa Dúpẹ́ Ohun Gbogbo,” Dec.

  • Ìgbàgbọ́​—Ànímọ́ Tó Ń Sọni Di Alágbára, Aug.

  • Ìwà Rere​—Bá A Ṣe Lè Ní In, Mar.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

  • A Rí “Péálì Kan Tó Níye Lórí Gan-An” (W. àti P. Payne), Apr.

  • Àpẹẹrẹ Àwọn Ẹni Tẹ̀mí Mú Kí N Fayé Mi Sin Jèhófà (W. Mills), Feb.

  • Jèhófà Bù Kún Mi Kọjá Ohun Tí Mo Lérò (M. Tonak), July

JÈHÓFÀ

  • “Àmín” Wa Ṣe Pàtàkì sí Jèhófà, Mar.

  • Ṣé Jèhófà Máa Ń Kìlọ̀ Fáwọn Èèyàn? Oct.

JÉSÙ KRISTI

  • Ṣé Èmi Ni Jésù Kú fún Lóòótọ́? July

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

  • Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Ṣètò Láti Bá Ọkọ̀ Ojú Omi Rìn Láyé Àtijọ́, Apr.

  • Dáàbò Bo Ara Rẹ Lọ́wọ́ Pańpẹ́ Sátánì (àwòrán oníhòòhò), June

  • Ìgbà Táwọn Júù Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Lo Sínágọ́gù, Feb.

  • Iṣẹ́ Táwọn Ìríjú Máa Ń Ṣe Láyé Àtijọ́, Nov.

ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE

  • Ayé Rẹ Ṣì Máa Dùn! No. 2

  • Ṣé Ìgbésí Ayé Ẹ̀dá Kò Jù Báyìí Náà Lọ? No. 3

  • Ta Ni Ọlọ́run? No. 1

JÍ!

  • Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí I? No. 3

  • Ohun Mẹ́fà Tó Yẹ Ká Kọ́ Àwọn Ọmọ, No. 2

  • Ǹjẹ́ Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ọkàn Wa Máa Balẹ̀? No. 1