ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ February 2016
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 4 sí May 1, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
Jèhófà Pè É Ní “Ọ̀rẹ́ Mi”
Ṣé ó wù ẹ́ kó o dọ̀rẹ́ Jèhófà? Àpẹẹrẹ Ábúráhámù máa jẹ́ kó o mọ bó o ṣe lè dọ̀rẹ́ Jèhófà.
Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà
Báwo ni Rúùtù, Hesekáyà àti Màríà ṣe ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú Ọlọ́run?
Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà
Ọ̀nà mẹ́rin kan wà tí àpẹẹrẹ Jónátánì lè gbà ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà tá a bá níṣòro tó le koko.
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin
Báwo ni Dáfídì, Jónátánì, Nátánì àti Húṣáì ṣe fi hàn pé ohun tó ṣe pàtàkì jù ni pé káwọn jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Jèhófà Ti Jẹ́ Kí N Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ̀
Ọdún 73 ni Corwin Robison fi sin Ọlọ́run tọkàntọkàn, ó sì lé ní 60 ọdún tó lò ní Bẹ́tẹ́lì tó wà lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Máa Fayọ̀ Sin Jèhófà
Àwọn ìlànà mẹ́ta wo ló yẹ kó o máa ronú lé lórí kó o lè máa fayọ̀ sin Jèhófà?