ILÉ ÌṢỌ́ No. 1 2016 | Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Olóòótọ́?
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló jẹ́ pé tí wọ́n bá sọ̀rọ̀ fún ìṣẹ́jú mẹ́wàá, ó kéré tán irọ́ kan á wà níbẹ̀. Ṣé dandan ni ká dá yàtọ̀?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Àǹfààní Tó Wà Nínú Jíjẹ́ Olóòótọ́
Ohun tó ṣẹlẹ̀ sáwọn kan jẹ́ ká rí àǹfààní tó wà nínú jíjẹ́ olóòótọ́.
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Fún Mi Ní Ayọ̀ àti Ìbàlẹ̀ Ọkàn fún Ọdún Kan Péré
Ohun tó wà nínú 1 Jòhánù 1:9 wọ Alain Broggio lọ́kàn gan-an.
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Láyé àtijọ́, báwo ni wọ́n ṣe ń ṣe àkájọ ìwé, báwo sì ni wọ́n ṣe ń lò ó? Àwọn wo ló ṣeé ṣe kó wà lára “àwọn olórí àlùfáà” tá a mẹ́nu kàn nínú Bíbélì?
Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan
Ohun mẹ́ta tó o lè ṣe láti níyì lójú ara wa.
Ọ̀RỌ̀ ỌGBỌ́N TÓ WÚLÒ LÓDE ÒNÍ
Má Ṣe Máa Ṣàníyàn
Yàtọ̀ sí pé Jésù ní ká dẹ́kun ṣíṣàníyàn, ó tún ṣàlàyé bá a ṣe lè ṣe é.
Ohun Tí Bíbélì Sọ
Ǹjẹ́ àwọn òkú lè jíǹde?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ní Ìrẹ̀wẹ̀sì Ọkàn?
Àwọn ohun mẹ́ta kan wà tí Ọlọ́run máa ń fún wa ká lè fara da ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.