Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ILÉ ÌṢỌ́ No. 2 2017 | Ṣé Wàá Gba Ẹ̀bùn Ọlọ́run Tó Dára Jù?

Kí Lèrò Rẹ?

Kí ni ẹ̀bùn tó dára jù tí Ọlọ́run fún wa?

Bíbélì sọ pé: “Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ayé tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ó fi fi Ọmọ bíbí rẹ̀ kan ṣoṣo fúnni.”​Jòhánù 3:16.

Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí jíròrò ìdí tí Ọlọ́run fi rán Jésù wá sáyé láti wá kú fún wa àti bá a ṣe lè fi ẹ̀mí ìmoore hàn fún ẹ̀bùn náà.

 

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ẹ̀bùn Tó Ju Gbogbo Ẹ̀bùn Lọ

Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀bùn kan tí iye rẹ̀ kò ṣeé ṣírò, tó sì lè fún àwọn tó bá gbà á ní ìyè àìnípẹ̀kun. Ṣé ẹ̀bùn mí ì wà tó ju èyí lọ?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tí Ẹ̀bùn Yìí Fi Ṣe Iyebíye Gan-an?

Àwọn nǹkan wo ló lè mú kí ẹ̀bùn kan ṣeyebíye ju ẹ̀bùn mí ì lọ? Tá a bá ronú lórí kókó yìí, ó máa jẹ́ ká túbọ̀ lè mọ rírì ìràpadà náà.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Lo Máa Ṣe sí Ẹ̀bùn Ọlọ́run Tó Dára Jù Lọ?

Kí ni ìfẹ́ tí Kristi fi hàn sí wa ti sún wa ṣe?

Ṣé Ó Pọn Dandan Kí Kristẹni Òjíṣẹ́ Wà Láìgbéyàwó?

Àwọn ẹ̀sìn kan gbà pé ó pọn dandan kí àwọn olórí wọn tàbí òjíṣẹ́ wọn wà láìgbéyàwó. Àmọ́ kí ni Ìwé Mímọ́ sọ nípa rẹ̀?

Òwò Ẹrú​—Láyé Àtijọ́ àti Lóde Òní

Nígbà àtijọ́, àwọn èèyàn Ọlọ́run bọ́ lóko ẹrú. Ó bani nínú jẹ́ pé àìmọye èèyàn ló ṣì wà lóko ẹrú.

Èrè Tó Wà Nínú Fífúnni Ní Nǹkan

Fífúnni ní nǹkan máa mú èrè wá fún ẹ àtàwọn mí ì. Ó máa ń jẹ́ kí àjọṣe tó dáa wà láàárín àwọn èèyàn. Báwo lo ṣe lè ní ẹ̀mí fífúnni?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Bíbélì sọ pé “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn” máa jẹ́ “àwọn àkókò lílekoko tí ó nira láti bá lò.” Ǹjẹ́ ohun tí Bíbélì sọ yẹn bá ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní àkókò tí a wà yìí mu?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì