Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

OHUN TÓ Ń FÚNNI LÁYỌ̀

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I

ṢÓ O MÁA Ń RONÚ LÓRÍ ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ?

  • Báwo ni ìdílé mi ṣe lè láyọ̀?

  • Báwo ni mo ṣe lè ní àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́ kí èmi náà sì jẹ́ ọ̀rẹ́ gidi?

  • Ṣé àwọn èèyàn mi tó ti kú ṣì lè jíǹde?

  • Ṣé ìyà lè dópin?

  • Ṣé àwọn èèyàn ló máa pa ayé yìí run?

  • Ṣé gbogbo ẹ̀sìn ni inú Ọlọ́run dùn sí?

O LÈ RÍ ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ ÀTÀWỌN ÌBÉÈRÈ MÍÌ

Lọ sí ìkànnì jw.org. Ó wà ní èdè tó ju 900 lọ. Wàá rí àwọn ìṣọfúnni tó máa wúlò fún ẹ nípa àwọn kókó ọ̀rọ̀ tó yàtọ̀ síra.

Wàá tún rí fídíò àwọn èèyàn káàkiri ayé tí wọ́n ti rí ọ̀nà ayọ̀, tí wọn ò sì bojú wẹ̀yìn mọ́! Oògùn olóró tiẹ̀ ti di bárakú fún àwọn kan lára wọn nígbà kan, bẹ́ẹ̀ làwọn míì sì jẹ́ àkòtagìrì ẹlẹ́wọ̀n tẹ́lẹ̀. Àwọn tó kàwé gan-an àtàwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tún wà lára wọn, títí kan àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì.

Tó o bá lọ sórí ìkànnì jw.org/yo, o lè ka Bíbélì àtàwọn ìwé míì tó ń ṣàlàyé Bíbélì tàbí kó o wà wọ́n jáde lọ́fẹ̀ẹ́. Díẹ̀ lára àwọn ìwé náà ni: