Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Kí Lèrò Rẹ?

Kí Lèrò Rẹ?
  •   Tí Ọlọ́run bá nífẹ̀ẹ́ wa lóòótọ́, kí nìdí tó fi jẹ́ kí ìwà ibi àti ìyà máa bá a lọ?

  •   Kí nìdí tó fi dá wa lójú pé àwọn ọjọ́ ìkẹyìn ayé là ń gbé yìí?

  •   Báwo la ṣe mọ̀ pé àwọn nǹkan tí Bíbélì sọ nípa Ìjọba Ọlọ́run máa ṣẹ?

  •   Ṣé Bíbélì lè ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe àwọn ìpinnu tó bọ́gbọ́n mu lóde òní?

Torí pé Ẹlẹ́dàá wa nífẹ̀ẹ́ wa, ó pèsè ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí àtàwọn míì. Lọ sí ìkànnì wa, www.pr418.com/yo, tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o ba lè rí àwọn ìdáhùn náà.

Tó o bá lọ sórí ìkànnì wa, wàá rí eré ìkẹ́kọ̀ọ́, àwọn àpilẹ̀kọ, ohùn tá a gbà sílẹ̀ àti fídíò, àwọn ìfòrọ̀wánilẹ́nuwò, àti ọ̀pọ̀ àwọn ìwé lóríṣiríṣi, títí kan Bíbélì. Ọ̀fẹ́ sì ni gbogbo wọn.