Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ayé yìí ti dojú rú. Bó pẹ́ bó yá, àjálù àtàwọn ìṣòro míì táwọn èèyàn fọwọ́ ara wọn fà lè mú kí nǹkan nira fún wa lẹ́nì kọ̀ọ̀kan. Kí ló lè ran ìwọ àti ìdílé ẹ lọ́wọ́ kí ọkàn yín lè balẹ̀ bẹ́ ẹ tiẹ̀ ń kojú àwọn ìṣòro tó wà láyé yìí?