Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀

Ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀

Ohun Mẹ́fà Tó Yẹ Ká Kọ́ Àwọn Ọmọ

Irú èèyàn wo lo fẹ́ káwọn ọmọ rẹ jẹ́ tí wọ́n bá dàgbà?

  • Ẹni Tó Máa Ń Kó Ara Rẹ̀ Níjàánu

  • Onírẹ̀lẹ̀

  • Ẹni Tó Ní Ìforítì

  • Ẹni Tó Ṣeé Gbára Lé

  • Ọlọ́gbọ́n

  • Olóòótọ́

Àwọn ọmọ ò lè ṣàdédé ní àwọn ìwà ọmọlúwàbí yìí. Àfi kó o kọ́ wọn.

Ìwé yìí sọ̀rọ̀ nípa ohun pàtàkì mẹ́fà tó yẹ kó o kọ́ àwọn ọmọ rẹ. Àwọn nǹkan náà sì máa ràn wọ́n lọ́wọ́ gan-an nígbà tí wọ́n bá dàgbà.