Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I Lórí Ìkànnì JW.ORG

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I Lórí Ìkànnì JW.ORG

Èwo nínú àwọn ìbéèrè yìí lo fẹ́ mọ ìdáhùn ẹ̀?

Báwo ni mo ṣe lè mú kí ìdílé mi túbọ̀ láyọ̀?

Wo àpilẹ̀kọ náà, “Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Ẹ̀rọ Ìgbàlódé Gbà Ẹ́ Lọ́kàn.”

Báwo ni mo ṣe lè kọ́ àwọn ọmọ mi kí wọ́n lè níwà tó dáa?

Wo àpilẹ̀kọ náà, “Kọ́ Àwọn Ọmọdé Bí Wọ́n Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Lo Fóònù.”

Kí ni mo lè ṣe kí n má bàa máa bẹ̀rù ọjọ́ ọ̀la?

Wo ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ náà, “Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú?

Bíbélì lè ran ìwọ àti ìdílé ẹ lọ́wọ́ kẹ́ ẹ lè gbádùn ayé yín ní báyìí, kí ọkàn yín sì balẹ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa.

NǸKAN MÍÌ TÓ WÀ LÓRÍ JW.ORG: Ohun Tá A Fi Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Ọ̀fẹ́ ni. O ò sì ní forúkọ sílẹ̀.