JÍ! No. 3 2016 | Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Èdè
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe iṣẹ́ bàǹtà banta láti túmọ̀ èdè.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Àtayébáyé
Kí nìdí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi ń túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde wọn sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Èdè —Iṣẹ́ Táwọn Atúmọ̀ Èdè Wa Ń Ṣe
Atúmọ̀ èdè kan ṣàlàyé bó ṣe ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀.
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Yanjú Ọ̀rọ̀
Ọ̀nà tí ọkùnrin àti obìnrin ń gbà sọ̀rọ̀ yàtọ̀ síra. Tá a bá lóye àwọn ìyàtọ̀ yìí, aáwọ̀ ò ní máa ṣẹlẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà.
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ìgbàgbọ́
Bíbélì sọ pé ‘láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti wù Ọlọ́run dáadáa.’ Kí ni ìgbàgbọ́? Báwo lo ṣe lè ní ìgbàgbọ́?
Oúnjẹ Tó Gbòdì Lára Àtèyí Tí Kò Báni Lára Mu —Ṣó Yàtọ̀ Síra??
Ewu wo ló wà nínú kéèyàn fúnra rẹ̀ pinnu èyí tó ń ṣe òun?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
‘Ìhìn Rere fún Gbogbo Èèyàn ní Èdè Wọn’
Ká tó lè wàásù òtítọ́ tó wà nínú Bíbélì fún ọ̀pọ̀ èèyàn, iṣẹ́ ìtúmọ̀ èdè gbọ́dọ̀ péye. Báwo la ṣe ń ṣe iṣẹ́ yìí. Àwọn ìṣòro wo ni àwọn atúmọ̀ èdè máa ń dojú kọ?