Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀

Ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀

Ọ̀pọ̀ lára wa ló máa ń sọ pé àwọn kan máa ń ṣe ẹ̀tanú tàbí pé wọ́n lẹ́mìí ìkórìíra. Ṣùgbọ́n, a lè má mọ̀ pé àwa náà máa ń ṣe ẹ̀tanú sáwọn kan.

Jẹ́ ká wo àwọn ìmọ̀ràn tó wúlò táá jẹ́ ká túbọ̀ máa fìfẹ́ hàn sí gbogbo èèyàn.