Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?

Àní nínú ayé onídààmú yìí, o lè jèrè ìmọ̀ pípéye Bíbélì nípa Ọlọ́run, Ìjọba rẹ̀ àti ète àgbàyanu rẹ̀ fún aráyé. Bí o bá fẹ́ gba ìsọfúnni síwájú sí i tàbí kí ẹnì kan kàn sí ọ nílé láti darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú rẹ lọ́fẹ̀ẹ́, jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Watch Tower, P.M.B 1090, Benin City, Edo State, Nigeria, tàbí sí àdírẹ́sì tí ó ṣe wẹ́kú nínú èyí tí a tò sí ojú ìwé kejì.