Atọ́ka Kókó Àpilẹ̀kọ Fún Ilé Ìṣọ́ 2000
Atọ́ka Kókó Àpilẹ̀kọ Fún Ilé Ìṣọ́ 2000
Ó ń tọ́ka sí ìtẹ̀jáde tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
A Forí Lé Àwọn Erékùṣù Pàsífíìkì—Láti Lọ Ṣiṣẹ́! 8/15
A San Èrè fún Ìwákiri Ọlọ́jọ́ Pípẹ́ (Denmark), 9/1
A Tú Ìwé Dáníẹ́lì Palẹ̀! (ìwé Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì), 1/15
Altiplano ní Peru, 11/15
“Àpẹẹrẹ Ìṣọ̀kan,” 10/15
Àwọn Ìlú Olókè ní Chiapas (Mẹ́síkò), 12/15
Àwọn Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Di Mẹ́ńbà Ẹgbẹ́ Olùṣàkóso, 1/1
Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Gilead, 6/15, 12/15
Bí Wọn Ò Tiẹ̀ Ga, Wọ́n Lọ́kàn Tó Dára, 2/15
Erékùṣù Robinson Crusoe, 6/15
Fífi Ìwà Ọ̀làwọ́ Hàn Lọ́pọ̀ Yanturu Ń Máyọ̀ Wá (ọrẹ), 11/1
Ìjọba Násì Ń Pọ́n Wọn Lójú (Netherlands), 4/1
Íńdíà, 5/15
Ìpàdé Àgbègbè “Àwọn Olùṣe Ohun Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Wí,” 5/1
Ìpàdé Àgbègbè “Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run,” 1/15
Ítálì, 1/15
Kíkéde Ìjọba ní Fíjì, 9/15
Pípẹja Ènìyàn Níbi Òkun Aegean, 4/15
Senegal, 3/15
Taiwan, 7/15
Tuvalu, 12/15
ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 8/1, 9/1, 12/1
BÍBÉLÌ
Àwọn Ìwé Ìhìn Rere—Ṣé Ìtàn Gidi Ni Tàbí Àròsọ? 5/15
Ǹjẹ́ Àwọn Ọ̀rọ̀ Wà Tó Jẹ́ Ẹnà? 4/1
Ọdún Tí Èyí Táa Pín Kiri Pọ̀ Jù Lọ, 1/15
Ṣé Ìwé Tó Kàn Dára Ni? 12/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Àwọn oògùn tí a mú jáde láti inú ẹ̀jẹ̀, 6/15
Ẹ̀jẹ̀ ara ẹni, 10/15
Ìrunú ta ni? (Ro 12:19), 3/15
Jèhófà ní inú dídùn sí títẹ Kristi rẹ́ kẹ̀? (Isa 53:10), 8/15
Kíkọ̀ láti tẹ́wọ́ gba ìgbésẹ̀ ìkọ̀sílẹ̀, 12/15
Ta ló ṣàròyé nípa òróró tẹ́nì kan dà sí Jésù lórí? 4/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Àwọn Àpẹẹrẹ Rere—Jàǹfààní Lára Wọn, 7/1
Àwọn Ìgbéyàwó Aláyọ̀ Tí Ń Bọlá fún Jèhófà, 5/1
Báwo Lo Ṣe Ń Yanjú Aáwọ̀? 8/15
Dídámọ̀ràn Ara Rẹ Fáwọn Ẹlòmíràn, 4/15
Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Ká Ní Ẹ̀mí Ìfara-Ẹni-Rúbọ? 9/15
Ẹ̀yin Kristẹni Olùṣọ́ Àgùntàn, ‘Ẹ Jẹ́ Kí Ọkàn-Àyà Yín Gbòòrò’! 7/1
Fi Ẹ̀mí Ìmúratán Sin Ọlọ́run, 11/15
“Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọkàn-Àyà Rẹ” (Òwe 4), 5/15
Fífi Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Olùrànlọ́wọ́ Ara Ẹni, 10/15
Fífi Ọkàn-Àyà Táa Ti Múra Sílẹ̀ Wá Jèhófà, 3/1
Ìfojúsọ́nà Tó Mọ Níwọ̀n, 8/1
Ìmẹ̀tọ́mọ̀wà Ń Gbé Àlàáfíà Lárugẹ, 3/15
Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Látọ̀dọ̀ Ìyá Kan (Òwe 31), 2/1
Ìtùnú Nínú Okun Jèhófà, 4/15
Jẹ́ Oníwà Mímọ́ Nínú Ayé Oníṣekúṣe (Òwe 5), 7/15
Kí Ló Dé Tí Wọn Kò Bímọ? 8/1
Kí Lo Fi Ń Díwọ̀n Àṣeyọrí? 11/1
Kí Ló Ń Mú Ọ Sin Ọlọ́run? 12/15
Kí Ni Jíjẹ́ Kristẹni Túmọ̀ Sí? 6/1
Kòṣeémánìí Lètò Àjọ Jèhófà, 1/1
Má Ba Ara Rẹ Lórúkọ Jẹ́ (Òwe 6), 9/15
Ní Ìbárẹ́ Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà (Òwe 3), 1/15
O Ha Jẹ́ Olóye Bí? 10/1
Ojú Wo Lo Fi Ń Wo Ara Rẹ? 1/15
Orin Tí Ń Múnú Ọlọ́run Dùn, 6/1
Ọ̀wọ̀ Fáwọn Aláṣẹ, 8/1
‘Pa Àwọn Àṣẹ Mọ́ Kí O sì Máa Bá A Lọ Ní Wíwà Láàyè’ (Òwe 7), 11/15
Sísún Mọ́ Ọlọ́run, 10/15
Ṣé O Ti Di “Géńdé” Kristẹni? 8/15
Ṣé Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Àwọn Oníwà Ipá Lo Fi Ń Wò Wọ́n? 4/15
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Àìwalé-Ayé-Máyà Ló Jẹ́ Kí N Lè Sin Jèhófà (C. Moyer), 3/1
Atànmọ́lẹ̀ fún Ọ̀pọ̀ Orílẹ̀-Èdè (G. Young), 7/1
Dídúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà—Nípa Ṣíṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún! (S. Reynolds), 5/1
“Ẹ Kan Sáárá sí Ìgbàgbọ́ Kan Tí Kì Í Yẹ̀”! (H. Müller), 11/1
“Ẹ Kò Mọ Ohun Tí Ìwàláàyè Yín Yóò Jẹ́ Lọ́la” (H. Jennings), 12/1
Jèhófà Máa Ń San Èrè fún Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Adúróṣinṣin (V. Duncombe), 9/1
Jèhófà Ni Ààbò àti Okun Mi (M. Filteau), 2/1
Mo Rí Ogún Àkànṣe Gbà (C. Allen), 10/1
Olùṣe Ohun Ìjà Tẹ́lẹ̀ Wá Di Olùgba Ẹ̀mí Là (I. Ismailidis), 8/1
Ó Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Borí Ìtìjú (R. Ulrich), 6/1
Rírántí Ẹlẹ́dàá Láti Ìgbà Èwe (D. Hibshman), 1/1
JÈHÓFÀ
Báwo Lo Ṣe Fẹ́ Kí Ó Rántí Rẹ? 2/1
Máa Ń Gbọ́ Àdúrà, 3/1
Tóbi Ju Ọkàn-Àyà Wa Lọ, 5/1
JÉSÙ KRISTI
Bí Jésù Kristi Ṣe Lè Ràn Wá Lọ́wọ́, 3/15
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
“Arákùnrin Ni Gbogbo Yín,” 6/15
Àwọn Ẹbọ Ìyìn Tí Inú Jèhófà Dùn Sí, 8/15
Àwọn Ẹbọ Tí Inú Ọlọ́run Dùn Sí, 8/15
“Àwọn Ohun Fífani-Lọ́kàn-Mọ́ra” Ń Kún Ilé Jèhófà, 1/15
Àwọn Tí Ń Bá Ọlọ́run Jà Kò Ní Borí, 4/1
Àwọn Wo Ni Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Lóde Òní? 11/15
Ayé Tuntun Náà—Ṣé Wàá Wà Níbẹ̀? 4/15
Báwo Ni Àkókò Tó Ṣẹ́ Kù fún Àwọn Olubi Ti Pọ̀ Tó? 2/1
Bíbá Olùṣọ́ Náà Ṣiṣẹ́ Pọ̀, 1/1
Bíbélì Kíkà—Ó Lérè, Ó sì Gbádùn Mọ́ni, 10/1
Bí Jèhófà Ṣe Ń Ṣamọ̀nà Wa, 3/15
Di Ẹ̀kọ́ Ọlọ́run Mú Gírígírí, 5/1
Ẹ Dúró Lọ́nà Pípé Pẹ̀lú Ìgbàgbọ́ Tó Fìdí Múlẹ̀, 12/15
Ẹ Fi Ẹ̀mí Ìdúródeni Hàn! 9/1
“Ẹ Máa Bá A Nìṣó Ní Ṣíṣọ́nà,” 1/15
Ẹ Máa Bọlá fún Àwọn Tó Ní Ọlá Àṣẹ Lórí Yín, 6/15
“Ẹ Máa Wá Jèhófà àti Okun Rẹ̀,” 3/1
Ẹ Ní Ẹ̀mí Ìrònú Kristi, 9/1
Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run! 5/15
“Ẹni Tí Ó Kéré” Ti Di “Ẹgbẹ̀rún,” 1/1
Fífúnrúgbìn Òtítọ́ Ìjọba Náà, 7/1
‘Gba Ara Rẹ Àtàwọn Tí Ń Fetí sí Ọ Là,’ 6/1
Gbọ́ Ohun Tí Ẹ̀mí Ní Í Sọ, 5/1
Ìjọba Ọlọ́run—Ìṣàkóso Tuntun fún Ilẹ̀ Ayé, 10/15
Ìkùgbù Máa Ń Fa Àbùkù, 8/1
Ìrètí Àjíǹde Dájú! 7/15
Ìrètí Àjíǹde Lágbára, 7/15
Iṣẹ́ Ìsìn Ń Fún Àwọn Kristẹni Láyọ̀, 11/15
Jèhófà—Alágbára Ńlá, 3/1
Jèhófà Kò Ní Fi Nǹkan Falẹ̀, 2/1
Jèhófà Ń Fi Agbára fún Ẹni Tó Ti Rẹ̀, 12/1
Jẹ́ Kí “Ìrètí Ìgbàlà” Wà Lọ́kàn Rẹ Digbí! 6/1
Kíkẹ́kọ̀ọ́—Ó Ṣàǹfààní, Ó sì Gbádùn Mọ́ni, 10/1
Kíkún fún Ìdùnnú Nínú Ọlọ́run Ìgbàlà Wa, 2/1
Máa Fi Ìháragàgà Polongo Ìhìn Rere Náà, 7/1
Máa Fiyè sí Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run, 4/1
Máa Fiyè sí Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run fún Ọjọ́ Wa, 5/15
Mímọ “Èrò Inú Kristi,” 2/15
Ǹjẹ́ A Sún Ọ Láti Ṣe Bíi Ti Jésù? 2/15
Ǹjẹ́ O Ní “Èrò Inú Kristi”? 2/15
Ǹjẹ́ O Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ìránnilétí Jèhófà Lọ́nà Tó Kọyọyọ? 12/1
Ogún Wa Ṣíṣeyebíye—Kí Ló Túmọ̀ sí fún Ọ? 9/1
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Yóò Ṣe, 10/15
Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ìwà Mímọ́, 11/1
O Lè Máa Bá Híhùwà Mímọ́ Nìṣó, 11/1
“Ọgbọ́n Wà Pẹ̀lú Àwọn Amẹ̀tọ́mọ̀wà,” 8/1
‘Ọlọ́run, Rán Ìmọ́lẹ̀ Rẹ Jáde,’ 3/15
Ran Àwọn Ẹlòmíràn Lọ́wọ́ Láti Rìn Lọ́nà Tó Yẹ Jèhófà, 12/15
Ríra Àkókò Padà Láti Kàwé àti Láti Kẹ́kọ̀ọ́, 10/1
Sísọ Ohun Gbogbo Di Tuntun—Bí A Ti Sọ Ọ́ Tẹ́lẹ̀, 4/15
“Wákàtí Náà Ti Dé!” 9/15
“Wákàtí Rẹ̀ Kò Tíì Dé,” 9/15
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Àjẹ́ Ṣíṣe, 4/1
Àlàáfíà Ayé—Lọ́nà Wo? 11/1
Áńtíókù (Síríà), 7/15
Àṣírí Àṣeyọrí, 2/1
“Àwọn Àkókò Ìmúpadàbọ̀sípò” Ti Kù sí Dẹ̀dẹ̀! 9/1
Àwọn Alárìíwísí, 7/15
“Àwọn Ará ní Poland,” 1/1
Àwọn Ohun Tí Wọ́n Rí ní Jésíréélì, 3/1
Ayé Téèyàn Ò Ti Ní Bọ́hùn Mọ́, 9/15
Bí Ẹ̀mí Ṣe Ń Ṣiṣẹ́ Lónìí, 4/1
Bí O Ṣe Lè Ní Ọ̀rẹ́, 12/1
Cyril Lucaris—Ọkùnrin Tó Mọyì Bíbélì, 2/15
Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Ká Borí Ẹ̀mí Ìṣefínnífínní Dóríi Bíńtín? 6/15
“Ewúrẹ́ Olóòfà Ẹwà Ti Orí Òkè Ńlá,” 10/1
Ẹwà Inú Lọ́hùn-ún, 11/15
Gbígbógun Ti Ìwà Ìbàjẹ́, 5/1
Ibi Tóo Ti Lè Rí Ìmọ̀ràn Rere Gbà, 6/1
Igi Ólífì, 5/15
Ìgbàgbọ́ Lè Yí Ìgbésí Ayé Rẹ Padà, 1/1
Ìgbésí Ayé Lè Túbọ̀ Nítumọ̀, 7/15
Ìkórìíra, Dópin Kẹ̀? 8/15
Ìṣọ̀kan Ìsìn Ha Sún Mọ́lé Bí? 12/1
Ìwàláàyè Lẹ́yìn Ikú, 10/1
Ìwàláàyè Pípé—Kì Í Màá Ṣe Àlá Lásán! 6/15
Jòsáyà, 9/15
Kíkẹ́kọ̀ọ́ Lára Tọkọtaya Ẹ̀dá Ènìyàn Àkọ́kọ́, 11/15
Máa Kọbi Ara sí Ìkìlọ̀! 2/15
Ǹjẹ́ Àṣà Kérésìmesì Bá Ìsìn Kristẹni Mu? 12/15
Ǹjẹ́ Ìwà Rere Tí Bíbélì Fi Kọ́ni Ṣeé Fi Sílò? 11/1
Ǹjẹ́ O Máa Ń Gba Ohun Tí O Kò Lè Rí Gbọ́? 6/15
Ǹjẹ́ O Mọ Bí A Ṣe Ń Dúró De Nǹkan? 9/1
Ǹjẹ́ Ó Tiẹ̀ Láǹfààní Tádùúrà Gbígbà Ń Ṣe? 11/15
Onínúnibíni Rí Ìmọ́lẹ̀ Ńlá (Pọ́ọ̀lù), 1/15
Ọkùnrin Àwòfiṣàpẹẹrẹ Kan Tó Tẹ́wọ́ Gba Ìbáwí (Jóòbù), 3/15
Ọlọ́run Máa Ń Gbọ́ Àdúrà, 3/1
“Rìn Yí Ká Pẹpẹ Rẹ,” 5/1
Rírí Ìbàlẹ̀ Ọkàn, 7/1
Ṣàyẹ̀wò Àwọn Ẹ̀sìn Mìíràn Kẹ̀? 10/15
Ṣé Dandan Ni Kí O Gbà Á Gbọ́? 12/1
Ṣíṣiṣẹ́ Nínú “Pápá”—Ṣáájú Ìkórè, 10/15