Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2001

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2001

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2001

Ó ń tọ́ka sí ìtẹ̀jáde tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

A Kò Nìkan Wà Nígbà Táa Dán Ìgbàgbọ́ Wa Wò (ẹ̀jẹ̀), 4/15

A Ń Sa Gbogbo Ipá Wa! (àwọn míṣọ́nnárì) 10/15

Àpéjọpọ̀ “Àwọn Olùkọ́ni Ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,” 5/1

Àpéjọpọ̀ “Àwọn Olùṣe Ohun Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Wí,” 1/15

Àwọn Àpéjọpọ̀—Àkókò Aláyọ̀ fún Ẹgbẹ́ Àwọn Ará, 9/15

Bíborí Inúnibíni Ìjọba Násì, 3/15

Ẹgbẹ́ Olùṣàkóso àti Àjọ Táa Fòfin Gbé Kalẹ̀, 1/15

Ìgbà Kan Wà Táa Jẹ́ Ìkookò—A Ti Di Àgùntàn Báyìí! 9/1

Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Gílíádì, 6/15, 12/15

Ilẹ̀ Faransé, 8/15, 9/1

“Ìpàdé Di Inú Ìjọba Ọlọ́run” (F. Drozg), 11/15

Ìpàdé Ọdọọdún ti Ọdún 2000, 1/15

“Iṣẹ́ Àgbàyanu Kan” (Photo-Drama [Àwòkẹ́kọ̀ọ́ Onífọ́tò]), 1/15

Ìwé Ẹ̀rí Ìgbóríyìnfúnni (Kóńgò [Kinshasa]), 8/15

Jíjàre ní Kóòtù Tí Ń Rí Sọ́ràn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn (Jámánì), 8/15

‘Ká Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Nítorí Òmìnira Ìsìn,’ 5/15

Kẹ́ńyà, 2/15

Ó Ha Lè Jẹ́ Iṣẹ́ Tó Dára Jù Lọ fún Ọ? (Iṣẹ́ Ìsìn Bẹ́tẹ́lì), 3/15

Omi Tí Ń Fúnni Ní Ìyè Ń Ṣàn Láwọn Òkè Andes, 10/15

Oníṣègùn Ojú Gbin Irúgbìn (Ukraine, Israel), 2/1

“Ọjọ́ Ìfàyègba Ẹ̀sìn Mìíràn” (iléèwé Poland), 11/1

Ríran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́, 7/15

Wọ́n Bìkítà fún Ara Wọn (àwọn tí ogun sọ di olùwá-ibi-ìsádi), 4/15

ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN

2/1, 4/1, 5/1, 6/1, 8/1, 10/1, 12/1

BÍBÉLÌ

Àwọn Àkájọ Ìwé Òkun Òkú, 2/15

Àwọn Èèyàn Mọyì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, 11/15

Bíbélì Wà Ní Ìdìpọ̀ Kan Ṣoṣo, 5/1

Cyril àti Methodius—Àwọn Olùtumọ̀, 3/1

Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Ká Kẹ́kọ̀ọ́ Rẹ̀? 7/1

Lílóye Bíbélì, 7/1

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

Àwọn ọ̀pá tá a fi ń gbé àpótí májẹ̀mú (1Ọb 8:8), 10/15

Báwo la ṣe dá ohun gbogbo “fún” Jésù? (Kól 1:16), 9/1

Báwo ni àkókò tí Jóòbù fi jìyà ṣe gùn tó? 8/15

Báwo ni ejò ṣe bá Éfà sọ̀rọ̀? 11/15

Èé ṣe tó fi yẹ ká jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ fáwọn alàgbà? 6/1

Fífúnni ní àkójọ ìlànà tí kọ̀ǹpútà fi ń ṣiṣẹ́, 2/15

Ibo ni Dáníẹ́lì wà nígbà àdánwò ère oníwúrà? (Dá 3), 8/1

“Ìbọ̀rìṣà tí ó lòdì sí òfin” (1Pé 4:3), 7/15

Ìgbà wo la fòróró yan “Ibi Mímọ́ nínú Àwọn Ibi Mímọ́”? (Dá 9:24), 5/15

Ìtumọ̀ sísìn “ní ẹ̀mí” (Jò 4:24), 9/15

Kristẹni aya àti àwọn ọdún, 12/15

Ṣé ó yẹ ká gbàdúrà nípa ẹni tá a yọ lẹ́gbẹ́? (Jer 7:16), 12/1

Ṣé Úrì ni Jèhófà ti bá Ábúráhámù dá májẹ̀mú tàbí Háránì? 11/1

Wíwọnú ìsinmi Jèhófà (Héb 4:9-11), 10/1

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

“Aláyọ̀ Ni Ènìyàn Tí Ó Ti Wá Ọgbọ́n Rí” (Òwe 8), 3/15

Àwọn Àṣà, 8/1

Bíborí Èrò Òdì, 4/15

Borí Àwọn Ohun Tó Lè Dènà Ìtẹ̀síwájú, 8/1

Dáàbò Bo Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ, 11/1

Ẹ fún Àwọn Ọmọ Yín Lóhun Tí Wọ́n Nílò! 12/15

Ẹ Máa Bójú Tó Àwọn Ọmọ Òrukàn Àtàwọn Opó, 6/15

“Ẹ Sáré Ní Irúfẹ́ Ọ̀nà Bẹ́ẹ̀,” 1/1

Fífún Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Jèhófà Lókun, 6/1

‘Ìbùkún Jèhófà Ní Í Sọni Di Ọlọ́rọ̀,’ 11/1

‘Ìbùkún Wà fún Olódodo’ (Òwe 10), 7/15

Ìdúróṣinṣin, 10/1

Ìgbọràn—Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Téèyàn Ń Kọ́ Lọ́mọdé, 4/1

Ìjẹ́wọ́, 6/1

Iyèméjì, 7/1

Kíkẹ́sẹ Járí Láìka Bí Wọ́n Ṣe Tọ́ni Dàgbà Sí, 4/15

Máa Rìn Ní ‘Ipa Ọ̀nà Ìdúróṣánṣán’ (Òwe 10), 9/15

Ní Ìwà Funfun, 1/15

‘Nípasẹ̀ Ọgbọ́n Ni Ọjọ́ Wa Yóò Fi Di Púpọ̀’ (Òwe 9), 5/15

Ǹjẹ́ Ó Máa Ń Dà Bíi Pé Wọ́n Ṣì Ọ́ Lóye? 4/1

Ojú Tá A Fi Ń Wo Ìwà Àgàbàgebè, 11/15

O Mà Lè Borí Ìrẹ̀wẹ̀sì! 2/1

Ríran Àwọn Opó Lọ́wọ́, 5/1

Ṣé Lóòótọ́ Ni Ò Ń Rára Gba Nǹkan? 7/15

Ṣíṣe Àwọn Ìpinnu Tó Mọ́gbọ́n Dání, 9/1

Yẹra fún Àrùn Ọkàn Nípa Tẹ̀mí, 12/1

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

A Dán Jèhófà Wò (P. Scribner), 7/1

Ayọ̀ Mi Kún, Ẹnu Mi Ò Sì Gbọpẹ́, Láìka Àdánù Ńláǹlà Sí (N. Porter), 6/1

Dídúpẹ́ fún Àwọn Ìrírí Mánigbàgbé! (D. Caine), 8/1

Ìgbésí Ayé Alárinrin Nínú Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà (R. Kurzen), 11/1

Ìmọ́lẹ̀ Ti Tàn ní Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn (N. Salem), 9/1

Jèhófà Mẹ́sẹ̀ Mi Dúró (F. Lee), 3/1

Ó “Fara Dà Á Dé Òpin” (L. Swingle), 7/1

Ohun Ìyanu Lọ́tùn-ún Lósì (E. & H. Beveridge), 10/1

“Oore Tí Jèhófà Ṣe fún Mi Mà Pọ̀ O!” (K. Klein), 5/1

Òṣùṣù Ọwọ̀ Ni Wá (M. Barry), 4/1

Sísìn Níbikíbi Tí A Bá Ti Nílò Mi (J. Berry), 2/1

Sísìn Tọkàntọkàn Lójú Onírúurú Àdánwò (R. Lozano), 1/1

Títẹ̀síwájú Lọ́nà Jèhófà (L. Valentino), 5/1

Títẹ́wọ́gba Ìkésíni Látọ̀dọ̀ Jèhófà (M. Zanardi), 12/1

JÈHÓFÀ

Fífún Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Rẹ̀ Lókun, 6/1

‘Ìbùkún Rẹ̀ Ń Sọni Di Ọlọ́rọ̀,’ 11/1

JÉSÙ KRISTI

Àjíǹde, 3/15

Ẹni Náà Gan-an Tí A Ń Pè Ní Jésù, 12/15

Jésù Ń Gbani Là—Lọ́nà Wo? 11/15

LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Ábúráhámù—Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́, 8/15

Àwọn Alábòójútó àti Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Táa Yàn Sípò Lọ́nà Ìṣàkóso Ọlọ́run, 1/15

Àwọn Ènìyàn Jèhófà Tí A Mú Bọ̀ Sípò Ń Yìn Ín Jákèjádò Ayé, 2/15

Ayọ̀ Yíyọ̀ Fáwọn Tí Ń Rìn Nínú Ìmọ́lẹ̀, 3/1

Báwo Lo Ṣe Lè Ran Ọmọ “Onínàákúnàá” Lọ́wọ́? 10/1

Báwo Ni Àlàáfíà Kristi Ṣe Lè Máa Ṣàkóso Nínú Ọkàn-Àyà Wa? 9/1

Báwo Ní Ìfẹ́ Rẹ Ṣe Gbòòrò Tó? 1/1

Bẹ̀rù Jèhófà, Kí O sì Pa Àwọn Àṣẹ Rẹ̀ Mọ́, 12/1

Bíborí Àìpé Ẹ̀dá, 3/15

“Bí Ọlọ́run Bá Wà fún Wa, Ta Ni Yóò Wà Lòdì sí Wa?” 6/1

‘Ẹ Fi Ìpamọ́ra Wọ Ara Yín Láṣọ,’ 11/1

Ẹ Jẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Ń Fi Tayọ̀tayọ̀ Kórè! 7/15

‘Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Mi,’ 12/15

Ẹ Máa Bá A Lọ Ní Fífẹsẹ̀múlẹ̀ Ṣinṣin Bí Ẹni Tí Ń Rí Ẹni Tí A Kò Lè Rí! 6/15

Ẹ Máa Bá Iṣẹ́ Ìkórè Náà Lọ Ní Rabidun! 7/15

Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Ìmọ̀ Jèhófà, 7/1

Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà, 5/1

Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ọlọ́run Aláyọ̀, 5/1

Ẹ Má Ṣe Di Olùgbọ́ Tí Ń Gbàgbé, 6/15

Ẹ Má Ṣe Juwọ́ Sílẹ̀ Ní Ṣíṣe Ohun Tó Dára, 8/15

Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé, 2/15

Ẹ Wá Wo Olùṣe Àwọn Ohun Àgbàyanu! 4/15

Ẹ Yin Jèhófà Nítorí Àwọn Iṣẹ́ Àrà Rẹ̀! 5/15

Fara Wé Jèhófà Nígbà Tóo Bá Ń Tọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ, 10/1

Fiyè sí Àwọn Iṣẹ́ Àgbàyanu Ọlọ́run, 4/15

Gbé Èrò Inú Rẹ Ka Ẹ̀mí, Kí O sì Yè! 3/15

Gbígbé Ìdílé Tó Dúró Sán-ún Nípa Tẹ̀mí Ró, 5/15

Ìbùkún Jèhófà Ní Í Sọ Wá Dọlọ́rọ̀, 9/15

Ìbùkún Jèhófà Yóò Ha Dé Bá Ọ Bí? 9/15

Ìgbàlà Fáwọn Tó Yan Ìmọ́lẹ̀, 3/1

Ìsìn Kristẹni Tòótọ́ Ti Borí! 4/1

Ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run Lórí Ọ̀ràn Yíyan Ẹni Tí A Óò Fẹ́, 5/15

Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Onípamọ́ra, 11/1

Jèhófà Ń Fi Bí A Ó Ṣe Máa Ka Àwọn Ọjọ́ Wa Hàn Wá, 11/15

Jèhófà Ni Ibi Ìsádi Wa, 11/15

Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Jèhófà Wà ní Ọkàn Rẹ, 12/1

Jẹ́ Kí Ìlọsíwájú Rẹ Fara Hàn Kedere, 8/1

Kí Ìfẹ́ Máa Gbé Yín Ró, 1/1

Máa Bá Ètò Àjọ Jèhófà Rìn, 1/15

“Máa Wá Àlàáfíà, Kí O sì Máa Lépa Rẹ̀,” 9/1

Ní Irú Ìgbàgbọ́ Tí Ábúráhámù Ní! 8/15

Ní Ọkàn-Àyà Tó Tẹ́ Jèhófà Lọ́rùn, 10/15

Nípìn-ín Nínú Ayọ̀ Tó Wà Nínú Fífúnni! 7/1

Ǹjẹ́ O Lè “Fi Ìyàtọ̀ Sáàárín Ohun Tí Ó Tọ́ àti Ohun Tí Kò Tọ́”? 8/1

Ǹjẹ́ Ò Ń Gbé Níbàámu Pẹ̀lú Ìyàsímímọ́ Rẹ? 2/1

Ǹjẹ́ O Ti Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ? 2/1

Oògùn Ajẹ́bíidán fún Másùnmáwo, 12/15

Ọjọ́ Ìdájọ́ Jèhófà Ti Sún Mọ́lé! 2/15

“Ọ̀rọ̀ Jèhófà Ń Bá A Lọ Ní Gbígbilẹ̀,” 4/1

Pa Ọkàn-Àyà Rẹ Mọ́! 10/15

Ta Ni Yóò Yà Wá Kúrò Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run? 10/15

Títẹ̀síwájú sí Ìṣẹ́gun Ìkẹyìn! 6/1

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

Ààbò Nínú Ayé Eléwu, 2/1

“Amúniláradá fún Ìdodo Rẹ,” 2/1

Àwọn Bàbá Ìjọ—Ṣé Alágbàwí Òtítọ́ Ni Wọ́n? 4/15

Àwọn Hasmonaean, 6/15

Àwọn Igi Tó Rọ́kú, 7/1

Àwọn Ohun Tó Ń Pagi Run, 11/1

Àwọn Ọgbẹ́ Ogun, 1/1

Ayọ̀, 3/1

Bí Ìgbà Èwe Ṣe Lè Dùn Bí Oyin, 8/15

Énọ́kù Bá Ọlọ́run Rìn, 9/15

Èrò Tó Wà Níwọ̀ntúnwọ̀nsì Nípa Owó, 6/15

Èṣù, 9/1

“Ewu Tó Dojú Kọ Ìlera Gbogbo Ènìyàn,” (Ohun arùfẹ́-ìṣekúṣe-sókè lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì), 4/15

Ẹ̀kọ́ Táa Lè Rí Kọ́ Lára Igi Ọ̀pẹ, 10/1

‘Ẹ Wò Ó! Ogunlọ́gọ̀ Ńlá Náà!’ 5/15

Ìbẹ́mìílò, 5/1

Ìdí fún Ohun Tóo Gbà Gbọ́, 8/1

Ìgbàgbọ́ Nóà Dá Ayé Lẹ́bi, 11/15

Ìhìn Rere Ìjọba Náà, 4/1

Ìlànà Ta Ni O Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé? 6/1

Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀, 3/1

Ìyà, 5/15

Kí Ló Níye Lórí Jù Lọ? 9/15

Máa Dúpẹ́, Kóo sì Máa Yọ̀, 9/1

“Mo Ké Gbàjarè sí Késárì!” 12/15

“Nípasẹ̀ Ìmọ́lẹ̀ Láti Ọ̀dọ̀ Rẹ Ni Àwa Fi Lè Rí Ìmọ́lẹ̀,”12/1

Ǹjẹ́ Ẹ̀mí Èèyàn Máa Ń Kú? 7/15

Ǹjẹ́ Nǹkan Kan Tiẹ̀ Wà Tó Lè So Aráyé Pọ̀ Ṣọ̀kan? 9/15

Ǹjẹ́ O Lè Tún Ayé Ṣe? 10/15

Òfin Pàtàkì Náà Ṣì Bóde Mu, 12/1

Ó Lálòpẹ́ Ju Ògidì Wúrà Lọ, 8/1

O Lè Ní Ìgbàgbọ́ Tòótọ́, 10/1

“Oògùn Ojú Láti Fi Pa Ojú Rẹ,” 12/15

Origen—Bí Ẹ̀kọ́ Rẹ̀ Ṣe Nípa Lórí Ṣọ́ọ̀ṣì, 7/15

Párádísè Tẹ̀mí, 3/1

Pọ́ọ̀lù Ṣètò Ọrẹ Àfiṣèrànwọ́ Fáwọn Ẹni Mímọ́, 3/15

Síkítíánì, 11/15

Ṣé Èèyàn Máa Ń Wà Láàyè Lẹ́yìn Ikú? 7/15