Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2003

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2003

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2003

Ó ń tọ́ka sí ìtẹ̀jáde tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Àpéjọ Àgbègbè “Àwọn Olùfi Ìtara Pòkìkí Ìjọba Ọlọ́run,” 1/15

Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Fi Ògo fún Ọlọ́run,” 5/1

Àwọn Òṣìṣẹ́ Káyé (Mẹ́síkò), 5/1

Àwùjọ Kan Tí Èdè Wọn Yàtọ̀ (Korea), 6/15

“Ayé Dùn O!” 1/1

Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 6/15, 12/15

Brasil (ìwàásù fáwọn adití), 2/1

Fídíò Tá A Ṣe Láti Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́, 7/1

“Gbára Dì fún Iṣẹ́ Rere Gbogbo,” 12/1

Ìgbésí Ayé Nínú Àgọ́ Àwọn Olùwá-ibi-ìsádi (Tanzania), 2/15

Ìjọsìn Tòótọ́ So Ìdílé Kan Pọ̀, 8/15

Ilé Ẹjọ́ Gíga Ti Ìsìn Tòótọ́ Lẹ́yìn (Armenia), 4/1

Ilẹ̀ Faransé, 12/1

Inúnibíni, 3/1

Ìrànlọ́wọ́ Láti Múni Dúró Ṣinṣin Lórí Ọ̀ràn Ìjẹ́mímọ́ Ẹ̀jẹ̀ (Philippines), 5/1

Iṣẹ́ Ìwàásù Tí A Kò Lè Gbàgbé (Mẹ́síkò), 4/15

Kàlẹ́ńdà, 11/15

Nígbà Kan Rí àti Nísinsìnyí, 1/15, 3/15, 5/15, 7/15, 9/15, 11/15

‘Ó Dí Àlàfo Kan’ (ìwé Sún Mọ́ Jèhófà), 7/1

Ó Jèrè Ìfaradà Tó Ní, 1/1

Orílẹ̀-èdè Czech, 8/1

Poland, 10/1

São Tomé àti Príncipe, 10/15

Ukraine, 10/1

Wọ́n Pa Wọ́n, A Rántí Wọn (Hungary), 1/15

BÍBÉLÌ

Àwọn Ẹni Rírẹlẹ̀ Láwùjọ Túmọ̀ (Èdè Tahiti), 7/1

Fi Ọwọ́ Títọ̀nà Mú Òtítọ́?, 1/1

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

Bí ẹni àmì òróró tó jẹ́ aláìlera ò bá lè wá síbi Ìṣe Ìrántí, 3/15

Ẹ̀bùn nígbà ayẹyẹ ìgbéyàwó, 9/1

Ìbatisí nítorí òkú (1Kọ 15:29, Bibeli Mimọ), 10/1

Ìdí tí nọ́ńbà ẹsẹ ìwé Sáàmù fi yàtọ̀ nínú onírúurú ìtumọ̀ Bíbélì, 4/1

Ìkóbìnrinjọ, ṣé ìlànà nípa rẹ̀ máa ń yí padà ni?, 8/1

“Ipa méjì” nínú ẹ̀mí Èlíjà (2Ọb 2:9), 11/1

Ìsíkíẹ́lì yadi? (Isk 24:27; 33:22), 12/1

Kí nìdí téèyàn fi gbọ́dọ̀ lọgun tí wọ́n bá fẹ́ fipá bá a lò pọ̀? 2/1

“Nígbàkúùgbà tí ẹ bá ń jẹ,” (1Kọ 11:25, 26), 1/1

‘Ní ìyè nínú ara ẹni,’ (Joh 5:26; 6:53) 9/15

Ǹjẹ́ gbígbọ́ ohùn túmọ̀ sí pé ẹ̀mí èṣù ń gbógun tini?, 5/1

Ǹjẹ́ ó tọ́ láti búra ní kóòtù pé wàá sòótọ́? 1/15

Ǹjẹ́ ó lòdì láti gbẹ̀mí ẹran ọ̀sìn? 6/1

Ǹjẹ́ Sátánì lágbára láti mọ èrò inú èèyàn? 6/15

Ǹjẹ́ Sátánì “ní ọ̀nà àtimú ikú wá”? (Heb 2:14), 7/1

Òkúta ọ̀ṣọ́ tó ní í ṣe pẹ̀lú ọjọ́ ìbí, 11/15

“Ọ̀kan lára wa” (Jẹ 3:22), 10/15

‘Rí Olùkọ́ni,’ ‘gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́yìn’ (Aís 30:20, 21), 2/15

Ṣé àmì ìyàsímímọ́ ni ìrìbọmi ní Pẹ́ńtíkọ́sì 33 Sànmánì Tiwa jẹ́?, 5/15

Ṣé ìfẹ́ Ọlọ́run ti di ṣíṣe ní ọ̀run? (Mt 6:10), 12/15

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Bá A Ṣe Lè Fọgbọ́n Bá Àwọn Èèyàn Lò, 8/1

Ẹ Dúró Ṣinṣin, 5/15

“Ẹ Má Ṣe Fi Àìdọ́gba So Pọ̀,” 10/15

“Ẹ Mọ́kànle! Mo Ti Ṣẹ́gun Ayé,” 3/15

Ẹ̀mí Ohun-Moní-Tómi, 6/1

‘Ẹni Rere Ń Rí Ojú Rere Ọlọ́run’ (Owe 12), 1/15

‘Ètè Òtítọ́’ (Owe 12), 3/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Rìn ní Ọ̀nà Tó Wu Jèhófà, 10/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ǹjẹ́ Ẹ̀ Ń Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí? 4/1

Gbin Ohun Tó Dáa Sọ́kàn Ọmọ Rẹ Láti Kékeré! 2/15

Ìfẹ́, 7/1

Lo Ipò Nǹkan Tó Ń Yí Padà Lọ́nà Tó Dáa, 3/1

Máa Yin Jèhófà “ní Àárín Ìjọ,” 9/1

Mímọrírì Ìdí Tá A Fi Ń Báni Wí, 10/1

Mọyì Àwọn Àgbàlagbà, 9/1

Ní Ẹ̀mí Fífúnni Ní Nǹkan, 11/1

Ǹjẹ́ Jèhófà Ń Kíyè sí Ohun Tí Ò Ń Ṣe? 5/1

Ǹjẹ́ Ò Ń Wá Jèhófà Tọkàntọkàn, 8/15

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí Ọmọ Mi Lọ Sílé Ẹ̀kọ́? 3/15

‘Òfin Ọlọ́gbọ́n’ (Owe 13), 9/15

“Ọ̀fẹ́ Ni Ẹ̀yin Gbà, Ọ̀fẹ́ Ni Kí Ẹ Fúnni,” 8/1

Ọrẹ Tí Inú Ọlọ́run Ń Dùn Sí, 6/1

Ronú Lọ́nà Tó Ṣe Tààrà Kó O sì Fi Ọgbọ́n Hùwà, 7/15

Ṣé Ìgbà Tó O Bá Rí Òfin Bíbélì Ni? 12/1

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

A Dán Mi Wò Lọ́nà Tó Múná, (P. Yannouris), 2/1

Aláyọ̀ Ni Ẹni Tí Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Rẹ̀ (T. Didur), 8/1

Ayọ̀ Tí Ò Lẹ́gbẹ́! (R. Wallwork), 6/1

Ìsapá Mi Nínú Ìtẹ̀síwájú Ìmọ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì Kárí Ayé (R. Nisbet), 4/1

Ìwé Pélébé Tó Yí Ìgbésí Ayé Mi Padà (I. Hochstenbach), 1/1

Jèhófà Kọ́ Mi Láti Ìgbà Èwe Mi (R. Abrahamson), 11/1

Jèhófà Máa Ń Bójú Tó Wa (E. Mzanga), 9/1

Jèhófà Máa Ń Fa Àwọn Onírẹ̀lẹ̀ Wá Sínú Òtítọ́ (A. Koshino), 10/1

“Kí Ni Èmi Yóò San Padà fún Jèhófà?” (M. Kerasinis), 12/1

Lílo Ara Ẹni Fáwọn Ẹlòmíràn Ń Dín Ìṣòro Kù (J. Arias), 7/1

Onínúure Ni (M. Henschel), 8/15

Wíwá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́—Ìgbésí Ayé Ìfọ̀kànbalẹ̀ àti Ayọ̀ (J. Sunal), 3/1

JÈHÓFÀ

Kí Nìdí Tó O Fi Gba Ọlọ́run Gbọ́? 12/1

Ǹjẹ́ Ó Ń Kíyè sí Ohun Tí Ò Ń Ṣe? 5/1

Ó Ń Bójú Tó Àwọn Mẹ̀kúnnù, 4/15

Ǹjẹ́ Ó Tiẹ̀ Bìkítà? 10/1

Ohun Tí Wàá Béèrè Lọ́wọ́ Ọlọ́run, 5/1

Ọlọ́run Tó Yẹ Ká Mọ̀ Dáadáa, 2/15

JÉSÙ KRISTI

Ìdílé, 12/15

Ṣé Ó Wá Sáyé Rí? 6/15

LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àkókò Yìí Gan-an Ló Yẹ Ká Ṣọ́nà Ju Ti Tẹ́lẹ̀ Lọ, 12/15

A Óò Máa Rìn Ní Orúkọ Jèhófà Títí Láé! (Míkà), 8/15

A Ṣe Inúnibíni sí Wọn Nítorí Wọ́n Jẹ́ Olódodo, 10/1

Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Ní Ìrètí Tòótọ́ (Míkà), 8/15

Àwọn Kristẹni Ìjímìjí àti Òfin Mósè, 3/15

Àwọn Obìnrin Kristẹni Olóòótọ́ Jẹ́ Ẹni Ọ̀wọ́n Tó Ń Sin Ọlọ́run, 11/1

Àwọn Obìnrin Tó Mú Inú Jèhófà Dùn, 11/1

Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀, 4/15

Báwo Ni Ìgbàgbọ́ Rẹ Ṣe Lágbára Tó? 1/15

Ẹ Dúró Jẹ́ẹ́ Kí Ẹ sì Rí Ìgbàlà Jèhófà! 6/1

‘Ẹ Dúró Nínú Ọ̀rọ̀ Mi,’ 2/1

Ẹ Fetí sí Ohun Tí Ẹ̀mí Ń Sọ! 5/15

Ẹ Fi Ìkóra-Ẹni-Níjàánu Kún Ìmọ̀ Yín, 10/15

‘Ẹ Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára!’ 3/1

“Ẹ Máa Bá A Nìṣó Ní Ṣíṣọ́nà”! 1/1

Ẹ “Máa Fi Gbogbo Ìwà Tútù Hàn sí Ènìyàn Gbogbo,” 4/1

‘Ẹ Máa Kún fún Ọpẹ́,’ 12/1

‘Ẹ Máa So Èso Púpọ̀,’ 2/1

Ẹ Máa Wá Ànímọ́ Rere Lára Gbogbo Ènìyàn, 6/15

“Ẹ Má Fòyà Tàbí Kí Ẹ Jáyà,” 6/1

‘Ẹ Ní Ìfẹ́ Láàárín Ara Yín,’ 2/1

Ẹ Wà Lójúfò Nísinsìnyí Ju Ti Ìgbàkígbà Rí Lọ! 1/1

Ẹ Wà Ní Ìmúratán De Ọjọ́ Jèhófà, 12/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́Jèhófà Ò Mà Ní Gbàgbé Iṣẹ́ Yín! 4/15

Fara Wé Jèhófà, Ọlọ́run Wa Tí Kì Í Ṣojúsàájú, 6/15

Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, 3/1

‘Fi Ọwọ́ Títọ̀nà Mú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,’ 11/15

Fífara Da Àdánwò Máa Ń Fi Ìyìn fún Jèhófà, 10/1

Fífarawé Ọlọ́run Òtítọ́, 8/1

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, 9/1

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Pátápátá Lákòókò Ìpọ́njú, 9/1

Ibo La Ti Lè Rí Ojúlówó Ìtùnú? 5/1

Ìwà Tútù—Ànímọ́ Kristẹni Tó Ṣe Pàtàkì, 4/1

Jèhófà, Ọlọ́run Òtítọ́, 8/1

Jíjíròrò Ohun Tẹ̀mí Ń Gbéni Ró, 9/15

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbàdúrà Láìdabọ̀? 9/15

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Ṣayẹyẹ Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa? 2/15

Kí Ni Jèhófà Ń Retí Pé Ká Máa Ṣe? (Míkà), 8/15

Kí Ni Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Túmọ̀ Sí fún Ọ? 2/15

Kó Ara Rẹ Níjàánu Kí O Lè Gba Èrè Náà! 10/15

Kristi Bá Àwọn Ìjọ Sọ̀rọ̀, 5/15

“Máa Ní Inú Dídùn Kíkọyọyọ Nínú Jèhófà,” 12/1

Ǹjẹ́ O Máa Ń Béèrè Pé “Jèhófà Dà?” 5/1

Ǹjẹ́ O Ní “Ẹ̀mí Ìdúródeni”? 7/15

Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Ẹlòmíràn Ni Kó O Máa Fi Wò Wọ́n, 3/15

Ojú Wo Ló Yẹ Ká Máa Fi Wo Àwọn Èèyàn bí Ọjọ́ Jèhófà Ṣe Ń Sún Mọ́lé? 7/15

“Ọlọ́run Jẹ́ Ìfẹ́,” 7/1

Ran Àwọn Ẹlòmíràn Lọ́wọ́ Láti Tẹ́wọ́ Gba Ìhìn Ìjọba, 11/15

Ṣé Lóòótọ́ Lo Nígbàgbọ́ Nínú Ìhìn Rere? 1/15

Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú, 5/1

Wàásù Láti Sọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn, 11/15

“Wò Ó! Ọlọ́run Wa Nìyí,” 7/1

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

Alexander Kẹfà (póòpù), 6/15

Àkọsílẹ̀ Nípa Ọjọ́ Nóà, 5/15

‘A Kò Ṣe Sólómọ́nì Lọ́ṣọ̀ọ́ Bí Ọ̀kan Lára Ìwọ̀nyí,’ 6/1

Ayọ̀ àti Ìfọ̀kànbalẹ̀ Níbi Iṣẹ́, 2/1

Bá A Ṣe Lè Ní Èrò Tó Yẹ Nípa Iṣẹ́, 2/1

Bárákì, 11/15

Bíbélì Lè Ràn Ṣèrànwọ́ Nínú Ìgbéyàwó, 9/15

“Ẹ Di Ẹ̀rí-Ọkàn Rere Mú,” 5/1

Ẹ̀kọ́ Táwọn Ẹyẹ Lè Kọ́ Wa, 6/15

Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Ń Jẹ́ Ká Jìyà, 1/1

Igi Ọ̀pọ̀tọ́, 5/15

Ìgbéyàwó Bóásì àti Rúùtù, 4/15

Ìkùdu, 12/1

Ìlànà Ẹ̀sìn Tòótọ́, 4/15

Ilẹ̀ Ayé Di Párádísè, 11/15

Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́, 4/15

Ipò Òṣì, 3/15, 8/1

Ìrànwọ́ fún Àwọn Òtòṣì, 9/1

Ìṣe Ìrántí (Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa), 4/1

Jékọ́bù, 10/15

Kí Lo Fẹ́ Ká Máa Fi Rántí Rẹ? 8/15

Kí Ló Ṣẹlẹ̀ Sí Wọn? (Nófì àti Nóò), 7/1

Martin Luther, 9/15

Ǹjẹ́ A Lè Dá Wà Láìfi Tàwọn Ẹlòmíràn Ṣe? 7/15

‘Ò Ń Tàpá sí Kẹ́sẹ́’ (Iṣe 26:14), 10/1

Òótọ́ Inú Dára, àmọ́ Ṣé Ó Tó?, 2/1

Owó Táwọn Èèyàn Fi Ń Ṣètọrẹ Àánú, 6/1

Pẹpẹ—Ìlò Rẹ̀ Nínú Ìjọsìn, 2/15

Ṣé Èṣù Ti Borí Ni? 1/15

Ṣé ‘Ìsìn Tòótọ́’ Kan Ṣoṣo Ló Wà? 9/1

Ṣíṣe Ìpinnu, 10/15

Ta Ló Tiẹ̀ Ṣeé Fọkàn Tán? 11/1

Tatian—Ṣé Agbèjà Ìgbàgbọ́ Ni àbí Aládàámọ̀? 5/15

Tùràrí Sísun, 6/1

Ugarit—Ìlú Ìgbàanì, 7/15

Wọ́n Wá Ojú Ọ̀nà Híhá (Àwọn Ará Tó Wà Níṣọ̀kan), 12/15

Yùsíbíọ̀sì—“Ṣé Ògbóǹkangí Òpìtàn Àwọn Ṣọ́ọ̀ṣì Ni?” 7/15