Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2005
Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2005
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní, 2/15
Àpéjọ Àyíká ní Àgọ́ Àwọn Tí Ogun Lé Kúrò Nílé (Kẹ́ńyà), 4/15
Àrọko Ọsirélíà, 4/1
Àwọn Èwe Ń Yin Jèhófà ní Iléèwé, 6/15
Àwọn Ẹlẹ́rìí Mẹ́síkò Ń Ran Àwọn Ará Ṣáínà Lọ́wọ́, 12/15
Àwọn Ẹlẹ́sìn Menno Fẹ́ Mọ Ohun Tí Bíbélì Kọ́ni (Bolivia), 9/1
Àwọn Olóòótọ́ Èèyàn, 6/1
Ẹ̀rí Tó Fi Ìfẹ́, Ìgbàgbọ́ àti Ìgbọràn Hàn (Ibi Ìtẹ̀wé ní Oko Watchtower), 12/1
Ibi Tí Ẹ̀sìn Kristẹni Ti Gbilẹ̀ Nígbà Ìjímìjí (Ítálì), 6/15
‘Ìfẹ́ Yín Lápapọ̀ Ń Pọ̀ Sí I’ (Japan), 11/15
“Ìgbàgbọ́ Wọn Ò Yẹ̀ Lábẹ́ Àdánwò” (fídíò), 3/1
“Ìhìn Rere Fáwọn Èèyàn Gbogbo Orílẹ̀-Èdè” (ìwé kékeré, Gẹ̀ẹ́sì), 12/1
Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 7/1
“Ilẹ̀ Ẹyẹ Idì” (Alibéníà), 10/15
Ìròyìn Iṣẹ́ Ìwàásù Wa ní Áfíríkà, 3/1
Ìwà Rere Méso Jáde (Japan), 11/1
Makedóníà, 4/15
“Ọ̀kan Lára Ọjọ́ Tínú Mi Dùn Jù Lọ Láyé Mi” (Ọsirélíà), 11/1
Ọrẹ, 11/1
Saba, 2/15
‘Wàásù Ìtúsílẹ̀ fún Àwọn Òǹdè’ (iṣẹ́ ìwàásù lọ́gbà ẹ̀wọ̀n), 12/15
‘Wọn Ì Bá Ti Dá Wọn Sílẹ̀,’ 8/15
“Wọn Kò Ṣe Ohun Tó Lòdì sí Ìgbàgbọ́ Wọn,” 7/15
Wọ́n Ń Sọ Ìhìn Rere Fáwọn Adití (Sípéènì), 11/1
‘Wọ́n Ṣe Inúnibíni sí Riet Nítorí Ìgbàgbọ́ Rẹ̀’ (N. Riet), 6/15
BÍBÉLÌ
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Àwọn Onídàájọ́, 1/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Rúùtù, 3/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní, 3/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Sámúẹ́lì Kejì, 5/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Àwọn Ọba Kìíní, 7/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Àwọn Ọba Kejì, 8/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Kíróníkà Kìíní, 10/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Kíróníkà Kejì, 12/1
Bíbélì Berleburg, 2/15
Bíbélì Èdè Ítálì—Ohun Tí Ojú Àwọn Olùtumọ̀ Rí, 12/15
Bíbélì Èdè Jámánì Ìjímìjí Lo Orúkọ Ọlọ́run, 9/1
Bíbélì Lè Ràn Ọ́ Lọ́wọ́ Láti Rí Ayọ̀, 8/1
Bíbélì Ọba, 8/15
Ẹ̀kọ́ Òtítọ́, 7/15
Ibi Ìkówèésí Àkọ́kọ́ Nílẹ̀ Rọ́ṣíà, 7/15
Ìtàn Inú Bíbélì—Ṣé Òótọ́ Ni àbí Àròsọ? 4/15
Ohun Tó Lè Mú Ìtumọ̀ Èdè Rọrùn, 4/15
Òkun Gálílì (ọkọ̀ ojú omi ayé àtijọ́), 8/15
Òkúta “Píìmù” Fi Hàn Pé Òótọ́ Ni Ìtàn inú Bíbélì, 3/15
“Ó Parí O” (Ìwé Mímọ́ Kristian Lédè Griki ní Ìtumọ̀ Ayé Titun lédè Lingala), 7/1
Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Bíbélì Ta Ko Ara Wọn? 4/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
“Áńgẹ́lì” Pétérù (Iṣe 12:15), 6/1
“A ó pa [àwọn obìnrin] mọ́ láìséwu nípasẹ̀ ọmọ bíbí” (1Ti 2:15), 5/1
Báwo ni Sámúsìnì ṣe lè fọwọ́ kan òkú kó ṣì tún jẹ́ Násírì? 1/15
“Bóyá” (Sef 2:3), 8/1
Dáfídì àtàwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ jẹ búrẹ́dì àfihàn, 3/15
Eré kọ̀ǹpútà oníwà ipá, 9/15
Iṣẹ́ tó gba pé kó máa gbé ìbọn, 11/1
Kí nìdí tí Ọlọ́run ò fi pa Dáfídì àti Bátí-ṣébà? 5/15
Ǹjẹ́ ìtakora wà lórí ọ̀rọ̀ jíjẹ òkú ẹran? (Le 11:40; Diu 14:21), 7/1
Ǹjẹ́ Kristẹni lè fún òṣìṣẹ́ ìjọba lówó kó lè ṣe iṣẹ́ tó yẹ kó ṣe? 4/1
Ǹjẹ́ Sámúsìnì ya kìnnìún sí méjì bíi pé ọmọ ẹran ni? 1/15
Ǹjẹ́ Sólómọ́nì yóò jíǹde? 7/15
Ohun tí ìmọ́lẹ̀ Ṣèkínà dúró fún, 8/15
Pọ́ọ̀lù sọ pé: “Farisí ni mí” (Iṣe 23:6), 4/15
Ṣé Jésù ni “ẹnì kan ṣoṣo tí ó ní àìkú” àti “ẹni tí kò sí ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn tí ó ti rí i” ń tọ́ka sí? (1Ti 6:15, 16), 9/1
Ṣé Jésù ni Sítéfánù gbàdúrà sí? 1/1
Ṣé òótọ́ ni Dáfídì dá àwọn òǹdè lóró? 2/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
‘Afọgbọ́nhùwà Ń Ronú Nípa Ìṣísẹ̀ Ara Rẹ̀’ (Owe 14), 7/15
Àkókò Oúnjẹ, 1/1
A Lè Borí Àdánwò Èyíkéyìí! 6/15
Àwọn Àṣà Ìbílẹ̀ Tí Inú Ọlọ́run Kò Dùn Sí, 1/1
Bí A Ṣe Lè Fi Jèhófà Ṣe Ọlọ́run Wa, 4/1
Èdèkòyédè Láàárín Tọkọtaya, 6/1
Èrò Táwọn Èèyàn Ní Nípa Wa, 9/15
“Ẹ Ní Ẹ̀mí Aájò Àlejò,” 1/15
Fífarabalẹ̀ Tẹ́tí Síni, 11/15
Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Yọ Àwọn Ọmọ Nínú Ewu, 1/1
‘Ìbẹ̀rù Jèhófà Ni Ọgbọ́n’ (Owe 14), 9/15
Ìgbà Wo Ló Yẹ Kéèyàn Bínú? 8/1
Ìgboyà Nígbà Àtakò, 5/1
Ìṣòtítọ́, 9/1
Làákàyè, 5/15
Máa Lo Ọjọ́ Kọ̀ọ̀kan Lọ́nà Rere, 5/1
Má Ṣe Fàyè Gba Èrò Òdì! 9/15
Má Ṣe Juwọ́ Sílẹ̀ Nínú Ṣíṣe Ohun Tó Dára, 6/1
Ǹjẹ́ Ìwọ àti Ìdílé Rẹ Máa Ń Jùmọ̀ Sọ̀rọ̀?, 6/1
Ǹjẹ́ O Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Dáadáa? 10/1
Ǹjẹ́ Ò Ń Fi Iṣẹ́ Ti Ìgbàgbọ́ Rẹ Lẹ́yìn? 4/15
Ǹjẹ́ O ‘Ní Ọrọ̀ Sọ́dọ̀ Ọlọ́run’? 10/1
Ǹjẹ́ Òtítọ́ Ń So Èso Nínú Àwọn Tó Ò Ń Kọ́? 2/1
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Máa Fi Ara Ẹ Wé Àwọn Ẹlòmíì? 2/15
Orí Ìpìlẹ̀ Wo Lò Ń Kọ́ Ìgbésí Ayé Rẹ Lé? 5/15
Yíyanjú Aáwọ̀, 3/1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
A Fi Gbogbo Ọkàn Wa Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà (N. Holtorf), 1/1
Àpẹẹrẹ Àwọn Òbí Mi fún Mi Lókun (J. Rekelj), 10/1
Bí Mo Tilẹ̀ Jẹ́ Aláìlera, Mo Di Alágbára (L. Engleitner), 5/1
Inú Mi Dùn Pé Mo Kópa Nínú Iṣẹ́ Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì (A. Matheakis), 7/1
Ipò Wa Tó Ń Yí Padà Jẹ́ Ká Lè Wàásù Láwọn Ibi Jíjìnnà Réré (R. Malicsi), 3/1
Jèhófà Máa Ń San Èrè Rẹpẹtẹ (R. Stawski), 8/1
Mo Gbádùn ‘Ìgbésí Ayé Ìsinsìnyí’ Dé Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́! (T. Buckingham), 6/1
Mo Ní Ìfaradà Bí Ọmọ Ogun Kristi (Y. Kaptola), 9/1
Mo Pinnu Láti Máa Sin Ẹlẹ́dàá Nìṣó (C. Benanti), 12/1
Obìnrin Tó Ṣẹ́gun Lọ́nà Àrà Ọ̀tọ̀ (E. Ludolph), 5/1
Ọlọ́run Fún Mi Ní ‘Ohun Tí Ọkàn Mi Ń Fẹ́’ (D. Morgou), 11/1
Ọmọ Òrukàn Rí Baba Onífẹ̀ẹ́ (D. Sidiropoulos), 4/1
JÈHÓFÀ
Jèhófà Kì Yóò Fi Ọ́ Sílẹ̀ Lọ́nàkọnà, 10/15
Jèhófà Máa Ń Ṣe Ohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo, 2/1
Jẹ́ Kí “Àsọjáde” Jèhófà Máa Ṣọ́ Ọ, 9/1
JÉSÙ KRISTI
Ipa Wo Ni Jésù Kristi Ń Ní Lórí Rẹ? 3/15
Ta Ni Jésù Kristi? 9/15
KÀLẸ́ŃDÀ
Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Fìyìn fún Jèhófà, 3/15
Ẹ̀mí Ìfara-Ẹni-Rúbọ, 11/15
Ìdílé Wà Níṣọ̀kan, 5/15
Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Ń Di Olùjọsìn Jèhófà, 9/15
Ọjọ́ Ogbó Jẹ́ “Adé Ẹwà,” 1/15
Wọn Ò Lọ́kọ Wọn Ò Láya àmọ́ Ọkàn Wọn Balẹ̀, 7/15
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àkókò Yìí Gan-An Ló Yẹ Kó O Gbé Ìgbésẹ̀ Kánkán, 12/15
A Ó Máa Rìn Ní Orúkọ Jèhófà Ọlọ́run Wa, 9/1
Àsọtẹ́lẹ̀ Hóséà Ń Fún Wa Níṣìírí Láti Bá Ọlọ́run Rìn, 11/15
“A Ti Rà Yín ní Iye Kan,” 3/15
Àwa Kristẹni Ń Gbé Ògo Jèhófà Yọ, 8/15
Àwọn Èèyàn “Láti Inú Gbogbo Èdè” Ń Gbọ́ Ìhìn Rere, 12/1
Àwọn Èèyàn Ń Wá ‘Péálì Olówó Iyebíye’ Lónìí, 2/1
Àwọn Ọ̀nà Jèhófà Dúró Ṣánṣán, 11/15
‘Àwọn Tí Ń Mú Ìhìn Rere Ohun Tí Ó Dára Jù Wá,’ 7/1
Àwọn Wo Ni Yóò Jíǹde? 5/1
Bá A Ṣe Lè Di Òjíṣẹ́ Tó Mọṣẹ́ Rẹ̀ Níṣẹ́ Tó Tún Mọwọ́ Yí Padà, 12/1
Bá Ọlọ́run Rìn Kó O Lè Kórè Ohun Tó Dára, 11/15
Báwo Ni Ìgbàgbọ́ Nínú Àjíǹde Ṣe Jinlẹ̀ Tó Lọ́kàn Rẹ? 5/1
Bí A Ò Ṣe Ní Wà Láàyè fún Ara Wa Mọ́, 3/15
Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Láyọ̀ Lóde Òní, 3/1
Ẹ Bá Ọlọ́run Rìn Lákòókò Hílàhílo Yìí, 9/1
Ẹ Jẹ́ Kí Inú Yín Máa Dùn Pé Kristẹni Ni Yín! 2/15
Ẹ̀kọ́ Àjíǹde Kàn Ọ́, 5/1
‘Ẹ Máa Ṣọ́nà’—Wákàtí Ìdájọ́ Ti Dé! 10/1
Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Tí Jésù Fi Lélẹ̀, 1/1
“Ẹ Máa Wádìí Ohun Tí Ẹ̀yin Fúnra Yín Jẹ́,” 7/15
Ẹ̀yin Èwe, Ẹ Yin Jèhófà! 6/15
Ẹ̀yin Òbí—Báwo Lẹ Ṣe Fẹ́ Kí Ọjọ́ Ọ̀la Àwọn Ọmọ Yín Rí? 10/1
Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Dáàbò Bo Ogún Iyebíye Tẹ́ Ẹ Ní, 4/1
Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Pèsè Ohun Tí Ìdílé Yín Nílò, 6/15
Gbẹ́kẹ̀ Lé Ọ̀rọ̀ Jèhófà, 4/15
Ìhìn Rere fún Àwọn Èèyàn Gbogbo Orílẹ̀-Èdè, 7/1
Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n fún Àwọn Tọkọtaya, 3/1
Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí La Fi Gbà Wọ́n Là, Kì Í Ṣe Iṣẹ́ Nìkan, 6/1
Ìran Tó Jẹ́ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìjọba Ọlọ́run Nímùúṣẹ, 1/15
Ìtọ́ni Jésù Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Láti Jẹ́rìí Kúnnákúnná, 1/1
Jèhófà Mọ Iye ‘Irun Orí Rẹ,’ 8/1
Jèhófà Ń Dáàbò Bo Àwọn Tó Ní Ìrètí Nínú Rẹ̀, 6/1
Jèhófà Ni “Olùsẹ̀san fún Àwọn Tí Ń Fi Taratara Wá A,” 8/1
Jèhófà Ni Olùṣọ́ Àgùntàn Wa, 11/1
Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Tànmọ́lẹ̀ sí Òpópónà Rẹ, 4/15
Kristi Làwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Tọ́ka Sí, 1/15
Máa Bá A Lọ Ní Títẹ̀lé Ìṣísẹ̀ Jésù Kristi, 9/15
‘Máa Kó Ara Rẹ Níjàánu Lábẹ́ Ibi,’ 5/15
Máa Rìn Nípa Ìgbàgbọ́, Má Ṣe Rìn Nípa Ohun Tó O Lè Fojú Rí! 9/15
Má Ṣe Ní Ẹ̀mí Ìgbéraga, 10/15
Má Ṣe Sọ Ìwà Kristẹni Nù, 2/15
Mọ Àwọn Ọ̀nà Jèhófà, 5/15
Ní Ojúlówó Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, 10/15
Ǹjẹ́ O Máa Ń Ṣòótọ́ Nínú Gbogbo Nǹkan? 7/15
Ǹjẹ́ Wàá Gbé Ògo Ọlọ́run Yọ? 8/15
Òfin Ìfẹ́ Tá A Kọ Sínú Ọkàn, 8/15
Ogun Iyebíye Làwọn Ọmọ Wa, 4/1
Ṣé Wàá Bá Ọlọ́run Rìn? 11/1
Ta Ni Ìwọ Ń Ṣègbọràn Sí—Ọlọ́run Ni Tàbí Ènìyàn? 12/15
‘Wọ́n Rí Péálì Olówó Iyebíye,’ 2/1
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Àjíǹde, 5/1
Amágẹ́dọ́nì, 12/1
Àmì Tó Fi Hàn Pé Jésù Ti Wà Níhìn-ín, 10/1
Àsìkò Ọdún, 12/15
Àwọn Èèyàn Ń Wá Ìbàlẹ̀ Ọkàn, 7/1
“Awọn Ti Nsọkalẹ Lọ si Okun Ninu Ọkọ̀,” 10/15
‘Bí Ẹnì Kan Bá Fipá Gbéṣẹ́ fún Ọ’ (Mt 5:41), 2/15
Ẹ̀kọ́ Kíkọ́—Nísinsìnyí àti Títí Láé, 4/15
Ẹ̀kọ́ Òtítọ́, 7/15
Ẹ̀kọ́ Tó Dára Jù Lọ, 10/15
Ẹ̀mí Rẹ Ṣe Pàtàkì, 2/1
Ẹ̀sìn Kristẹni Láàárín Àwọn Júù Ọ̀rúndún Kìíní, 10/15
“Idà Jèhófà àti Ti Gídíónì!” 7/15
Ìgbà Ọdún Kérésì, 12/15
Ikú, 8/15
Ipò Òṣì, 5/15
Ìràpadà Túbọ̀ Fi Òdodo Ọlọ́run Hàn, 11/1
Iṣẹ́ Àrà inú Ìṣẹ̀dá Ń Gbé Jèhófà Ga, 11/15
Iṣẹ́ Ìwàásù Mú Kí Wọ́n Ṣe Inúnibíni sí Sọ́ọ̀lù, 1/15
Iṣẹ́ Ìyanu, 2/15
Iṣẹ́ Ṣíṣe—Ìbùkún Ni Tàbí Ègún? 6/15
Ìṣọ̀kan Ayé, 6/1
Mari—Ìlú Pàtàkì Kan Tó Wà Nínú Aṣálẹ̀, 5/15
Ǹjẹ́ Èṣù Wà Lóòótọ́? 11/15
Ǹjẹ́ Ẹnì Kan Lè Yí Ayé Padà? 11/1
Ǹjẹ́ Ìsìn Lè Mú Kí Aráyé Wà Níṣọ̀kan? 1/1
Ǹjẹ́ O Lè Pinnu Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ? 1/15
‘Òkúta Aláwọ̀ Pupa Tí Ó Ṣeyebíye’ (Iṣi 4:3), 3/15
Philo Ará Alẹkisáńdíríà, 6/15
Pọ́ńtíù Pílátù, 9/15
Sámúsìnì Borí, 3/15