Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

January 15, 2008

Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

February 11-17, 2008

“Máa Ṣọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí O Tẹ́wọ́ Gbà Nínú Olúwa”

OJÚ ÌWÉ 4

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 193, 151

February 18-24, 2008

Fiyè sí “Ọnà Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́” Rẹ

OJÚ ÌWÉ 8

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 6, 123

February 25, 2008–March 2, 2008

Àwọn Tó “Ní Ìtẹ̀sí-Ọkàn Títọ́” Ń Kọbi Ara sí Ìwàásù Wa

OJÚ ÌWÉ 13

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 156, 133

March 3-9, 2008

Ọlọ́run Kà Wá Yẹ Láti Gba Ìjọba Kan

OJÚ ÌWÉ 20

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 195, 60

March 10-16, 2008

Ọlọ́run Kà Wọ́n Sẹ́ni Tó Yẹ Láti Ṣamọ̀nà Lọ Sáwọn Ìsun Omi Ìyè

OJÚ ÌWÉ 24

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 99, 187

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 4 sí 17

Àwọn àpilẹ̀kọ mẹ́ta yìí á sọ ìpinnu rẹ dọ̀tun kó o lè máa bá iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ nìṣó. Wọ́n á rán ẹ létí ìdí tó fi yẹ kó o jẹ́ onítara, wọ́n á jẹ́ kó o rí bó o ṣe lè mú kí ọ̀nà tó o gbà ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ sunwọ̀n sí i, wọ́n á sì tún fún ẹ níṣìírí kó o lè rí i pé ọ̀pọ̀ èèyàn ló ṣì ń tẹ́tí sí ìwàásù wa.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 àti 5 OJÚ ÌWÉ 20 sí 28

Àwọn àpilẹ̀kọ méjì yìí ṣe ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé lórí ohun táwọn Kristẹni tòótọ́ ń fojú sọ́nà fún. Yálà o wà lára àwọn tó máa wà pẹ̀lú Kristi lókè ọ̀run ni o tàbí ò ń fojú sọ́nà láti máa gbé títí láé lórí ilẹ̀ ayé, lábẹ́ ìṣàkóso Ìjọba Ọlọ́run, àwọn àpilẹ̀kọ náà á mú kó o túbọ̀ mọrírì rẹ̀ pé Jèhófà ní inú rere onífẹ̀ẹ́, ọgbọ́n rẹ̀ sì jẹ́ àwámáàrídìí.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Ilé Ìṣọ́ Tuntun Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

OJÚ ÌWÉ 3

Wọ́n Yan Ohun Tó Sàn Jù, Ṣé Wàá Fara Wé Wọn?

OJÚ ÌWÉ 17

Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè​—⁠Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Mátíù

OJÚ ÌWÉ 29

Nígbà Tí Èṣù Bá Ku Àwọn Kristẹni bí Àlìkámà

OJÚ ÌWÉ 32