Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 15, 2008
Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
March 17-23, 2008
Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 37, 26
March 24-30, 2008
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 138, 57
March 31, 2008–April 6, 2008
Jésù Kristi—Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 172, 72
April 7-13, 2008
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ
OJÚ ÌWÉ 16
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 211, 209
April 14-20, 2008
Wíwàníhìn-ín Kristi—Báwo Ló Ṣe Yé Ọ Sí?
OJÚ ÌWÉ 21
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 168, 21
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11
Ṣíṣàṣàrò lórí àwọn ìtàn inú Bíbélì máa ń fún ìgbàgbọ́ wa lókun. Tá a bá ń wo Jèhófà níwájú wa nígbà gbogbo, ó máa dáhùn àwọn àdúrà wa. Àmọ́, a ní láti máa ṣègbọràn sí Ọlọ́run ká sì máa gbẹ́kẹ̀ lé e. Rírìn ní ọ̀nà rẹ̀ máa mú ká jẹ́ ẹni tó ṣeé fọkàn tán, onírẹ̀lẹ̀, onígboyà àtẹni tó ń fi ọ̀ràn àwọn ẹlòmíì sọ́kàn.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 12 sí 20
Jésù Kristi ni Míṣọ́nnárì tó ju gbogbo míṣọ́nnárì lọ. Kọ́ nípa bó ṣe gba ìdálẹ́kọ̀ọ́, bó ṣe kọ́ àwọn míì lẹ́kọ̀ọ́ àtohun tó mú káwọn èèyàn fẹ́ràn rẹ̀. Kọ́ nípa bá a ṣe lè fara wé Jésù àti bá a ṣe lè máa kọ́ àwọn èèyàn lọ́nà tí ìhìn rere náà á fi wọ̀ wọ́n lọ́kàn.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 5 OJÚ ÌWÉ 21 sí 25
Wàá rí ìdí tá a fi lè sọ pé àkókò gígùn ni ìgbà wíwàníhìn Kristi. Ṣàgbéyẹ̀wò àwọn ẹ̀rí tá a rí látinú Ìwé Mímọ́ tó jẹ́ ká mọ àwọn tí Jésù pè ní “ìran yìí.” (Mát. 24:34) Wàá sì rí ìdí tí kò fi ṣeé ṣe láti ṣírò bí “ìran yìí” ṣe máa gùn tó.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Fi Àṣìṣe Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́gbọ́n
OJÚ ÌWÉ 26
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Máàkù
OJÚ ÌWÉ 28
Wọ́n Rọ Àwọn Tó Kẹ́kọ̀ọ́ Yege Nílé Ẹ̀kọ́ Gílíádì Pé Kí Wọ́n “Máa Walẹ̀ Jìn”
OJÚ ÌWÉ 31