Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

March 15, 2008

Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

April 21-27, 2008

Má Ṣe Máa Rin Kinkin

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 8, 177

April 28, 2008–May 4, 2008

Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ilé Rẹ

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 117, 89

May 5-11, 2008

Jèhófà Ń Gbọ́ Igbe Wa fún Ìrànlọ́wọ́

OJÚ ÌWÉ 12

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 58, 135

May 12-18, 2008

“Ta Ni Nínú Yín Tí Ó Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n àti Olóye?”

OJÚ ÌWÉ 21

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 106, 51

May 19-25, 2008

Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Lo Fi Ń Wò Wọ́n?

OJÚ ÌWÉ 25

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 127, 213

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11

Yàtọ̀ sí ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń rò, àwa Kristẹni ní láti jẹ́ ẹni tí kì í rin kinkin. Kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa rin kinkin? Kí lo lè ṣe tó ò fi ní jẹ́ ẹni tó ń rin kinkin jù nínú ìdílé?

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 12 sí 16

Kí nìdí tó fi lè dá wa lójú pé Jèhófà ń gbọ́ igbe wa fún ìrànlọ́wọ́ àti pé ó máa ń wá nǹkan ṣe sí ìṣòro wa? Àpilẹ̀kọ yìí yóò dáhùn ìbéèrè yẹn, yóò sì tún jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè fara da ìpọ́njú.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 àti 5 OJÚ ÌWÉ 21 sí 29

Àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí yóò ràn wá lọ́wọ́ láti máa fojú tó tọ́ wo àwọn èèyàn, yóò sì tún jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè yẹra fún dídá àwọn ẹlòmíì lẹ́jọ́ bí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe máa ń ṣe. A óò tún rí ìyàtọ̀ láàárín ẹni tó gbọ́n àti ẹni tí kò gbọ́n.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Bá A Ṣe Mú Ìhìn Rere Dé Orí Àwọn Òkè Ńlá Nílẹ̀ Bòlífíà

OJÚ ÌWÉ 16

Àdéhùn Pàtàkì Kan

OJÚ ÌWÉ 19

Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè​—⁠Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Lúùkù

OJÚ ÌWÉ 30