Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 15, 2008
Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
May 26, 2008–June 1, 2008
Kọ “Àwọn Ohun Tí Kò Ní Láárí” Sílẹ̀
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 48, 20
June 2-8, 2008
Jẹ́ Kí Ọlọ́run Máa Ṣamọ̀nà Rẹ Nínú Ohun Gbogbo
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 131, 225
June 9-15, 2008
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Rántí Ẹlẹ́dàá Yín Atóbilọ́lá Nísinsìnyí
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 157, 183
June 16-22, 2008
Ìgbéyàwó àti Ọmọ Bíbí Lákòókò Òpin Yìí
OJÚ ÌWÉ 16
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 24, 164
June 23-29, 2008
Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Rere?
OJÚ ÌWÉ 21
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 214, 67
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11
Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí á jẹ́ ká mọ “àwọn ohun tí kò ní láárí,” ìyẹn àwọn ohun tí kò ní jẹ́ ká lè fi gbogbo ọkàn wa sin Jèhófà. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí jẹ́ ká rí àwọn ohun tó lè dẹkùn mú wa láìfura, ó sì jẹ́ ká rí ọ̀pọ̀ ìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí Jèhófà máa ṣamọ̀nà wa nínú ohun gbogbo.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 12 sí 20
Àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí jẹ́ káwọn ọ̀dọ́ mọ bí Bíbélì ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́ tí wọ́n bá fẹ́ ṣe àwọn ìpinnu tó ṣe pàtàkì láyé wọn. Àpilẹ̀kọ kejì fún àwọn ọ̀dọ́ ní ìtọ́sọ́nà tó bọ́gbọ́n mu látinú Ìwé Mímọ́ lórí ohun tí wọ́n gbọ́dọ̀ fi sọ́kàn tí wọ́n bá ń ronú àtiṣègbéyàwó tàbí tí wọ́n bá n ronú ọmọ bíbí.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 5 OJÚ ÌWÉ 21 sí 5
Àpilẹ̀kọ tó kẹ́yìn ṣe àlàyé tó ń múni ronú jinlẹ̀ lórí ìwé Oníwàásù. Ó sọ àwọn nǹkan táwọn èèyàn kà sí pàtàkì láyé tá a wà yìí, ó tún wá sọ àwọn nǹkan tó ṣe pàtàkì jù lọ nígbèésí ayé àwa èèyàn.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Wọn Ò Sí Láàárín Wa àmọ́ A Kò Gbàgbé Wọn
OJÚ ÌWÉ 25
OJÚ ÌWÉ 29
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù
OJÚ ÌWÉ 30