Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

May 15, 2008

Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

June 30, 2008–July 6, 2008

Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Ṣe Sáwọn Èèyàn?

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 35, 62

July 7-13, 2008

Ẹ Máa Ṣe Rere

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 95, 145

July 14-20, 2008

Ìdáǹdè Nípasẹ̀ Ìjọba Ọlọ́run Kù sí Dẹ̀dẹ̀!

OJÚ ÌWÉ 12

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 181, 130

July 21-27, 2008

Pinnu Láti Sin Jèhófà Látìgbà Èwe Rẹ

OJÚ ÌWÉ 17

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 157, 221

July 28, 2008–August 3, 2008

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù Kó O Lè Tẹ̀ Síwájú Nínú Òtítọ́

OJÚ ÌWÉ 21

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 123, 129

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11

Nínú Ìwàásù Lórí Òkè tí Jésù ṣe, èyí táwọn èèyàn mọ̀ bí ẹní mowó, ó sọ bó ṣe ṣe pàtàkì tó pé ká jẹ́ onínú tútù, aláàánú, àti ẹlẹ́mìí àlàáfíà. Ó gba àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ níyànjú pé kí wọ́n jẹ́ ‘kí ìmọ́lẹ̀ wọn máa tàn,’ ó sì jẹ́ ká mọ bó ṣe yẹ ká máa ṣe sáwọn ọ̀tá wa àtàwọn ẹlòmíì.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 12 sí 16

Ṣàgbéyẹ̀wò bó o ṣe máa ṣàlàyé ìdí tí aráyé fi nílò ìdáǹdè lóde òní ju ti ìgbàkigbà rí lọ. Wo bó o ṣe lè mọ Jèhófà bí Olùdáǹdè tó ta yọ, kó o sì jẹ́ káwọn èèyàn mọ bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa dá aráyé nídè láìpẹ́.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 àti 5 OJÚ ÌWÉ 17 sí 25

Kí nìdí táwọn ọ̀dọ́ fi gbọ́dọ̀ sin Ọlọ́run? Ǹjẹ́ wọ́n lè máa gbé ìgbé ayé ẹni tó ya ara rẹ̀ sí mímọ́ fún Jèhófà láìka ojú táwọn èèyàn lè máa fi wò wọ́n sí? Àwọn àǹfààní iṣẹ́ ìsìn wo ni wọ́n lè ní? Báwo ni àpẹẹrẹ àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ṣe lè ran gbogbo àwọn ará ìjọ lọ́wọ́ láti túbọ̀ dẹni tó ń tọ Kristi lẹ́yìn pẹ́kípẹ́kí? Irú àwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì wọ̀nyí la fọ́ sí wẹ́wẹ́ nínú àwọn àpilẹ̀kọ méjì yìí.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Ẹ Máa Wà Ní Mímọ́ Nínú Ìbẹ̀rù Ọlọ́run

OJÚ ÌWÉ 26

Bí A Ṣe Ṣètò Ìgbìmọ̀ Olùdarí

OJÚ ÌWÉ 29

Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè​​—⁠Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìṣe

OJÚ ÌWÉ 30