Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2008

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2008

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2008

Tó ń tọ́ka sáwọn ìtẹ̀jáde Ilé Ìṣọ́ táwọn àpilẹ̀kọ kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àwọn Ànímọ́ Tá A Gbọ́dọ̀ Máa Lépa, 6/15

Àwọn Ohun Tá A Gbọ́dọ̀ Máa Sá Fún, 6/15

Àwọn Tó “Ní Ìtẹ̀sí-Ọkàn Títọ́” Ń Kọbi Ara sí Ìwàásù Wa, 1/15

Bá A Ṣe Lè Borí Ìṣòro Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù Ilé-dé-Ilé, 7/15

Bá A Ṣe Lè Mọyì Ipa Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Tí Jésù Kó Nínú Mímú Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Ní Lọ́kàn Ṣẹ, 12/15

Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Rere? 4/15

Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Ṣe Sáwọn Èèyàn? 5/15

“Ẹ Kọ Ojú Ìjà sí Èṣù” Bí Jésù Ti Ṣe, 11/15

Ẹ Máa Ṣe Rere, 5/15

Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Ìlànà Ìwé Mímọ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Ìtọ́jú Ara, 11/15

Ẹ Ràn Wọ́n Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Pa Dà Sínú Agbo, 11/15

Ẹ Ràn Wọ́n Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tètè Pa Dà! 11/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Rántí Ẹlẹ́dàá Yín Atóbilọ́lá Nísinsìnyí, 4/15

Fiyè sí “Ọnà Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́” Rẹ, 1/15

Ìdáǹdè Nípasẹ̀ Ìjọba Ọlọ́run Kù sí Dẹ̀dẹ̀! 5/15

Ìdí Tó Fi Yẹ Kó O Pa Ìwà Títọ́ Rẹ Mọ́, 12/15

Ìgbéyàwó àti Ọmọ Bíbí Lákòókò Òpin Yìí, 4/15

Ìwọ Kò Mọ Ibi Tí Yóò Ti Ṣàṣeyọrí! 7/15

Jèhófà Dáhùn Àdúrà Àtọkànwá Tí Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Kan Gbà, 10/15

Jèhófà Jẹ́ “Olùpèsè Àsálà” fún Wa, 9/15

Jèhófà Jẹ́ “Olùpèsè Àsálà” Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 9/15

Jèhófà Kì Yóò Fi Àwọn Ẹni Ìdúróṣinṣin Rẹ̀ Sílẹ̀, 8/15

Jèhófà Ń Gbọ́ Igbe Wa Fún Ìrànlọ́wọ́, 3/15

Jèhófà Ń Ṣìkẹ́ Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Tó Jẹ́ Àgbàlagbà, 8/15

Jèhófà Ń Ṣọ́ Wa Fún Ire Wa, 10/15

Jésù Kristi—Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ, 2/15

Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ilé Rẹ, 3/15

Jẹ́ Kí Jèhófà Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo, 2/15

Jẹ́ Kí Ọlọ́run Máa Ṣamọ̀nà Rẹ Nínú Ohun Gbogbo, 4/15

Kí Lo Máa Yááfì Kó O Lè Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun? 10/15

Kí Nìdí Tí Iṣẹ́ Ìwàásù Ilé-dé-Ilé Fi Ṣe Pàtàkì Nísinsìnyí? 7/15

Kọ “Àwọn Ohun Tí Kò Ní Láárí” Sílẹ̀, 4/15

Máa Jẹ́ Adúróṣinṣin Pẹ̀lú Ọkàn Tó Ṣọ̀kan, 8/15

Máa Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Rẹ Jẹ́ “Okùn Onífọ́nrán Mẹ́ta,” 9/15

Máa Rìn ní Ọ̀nà Jèhófà, 2/15

Máa Ṣe Ohun Tó Ń Gbé Iyì Jèhófà Yọ, 8/15

Máa Ṣọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí O Tẹ́wọ́ Gbà Nínú Olúwa,” 1/15

Máa Tẹ̀ Lé Àṣẹ Jèhófà, 6/15

Má Ṣe Fàyè Gba “Ẹ̀mí Ayé,” 9/15

Má Ṣe Jẹ́ Kí ‘Ìfẹ́ Tó O Ní Lákọ̀ọ́kọ́’ Jó Rẹ̀yìn, 6/15

Má Ṣe Máa Rin Kinkin, 3/15

Ǹjẹ́ Ò Ń Sọ “Èdè Mímọ́” Lọ́nà Tó Já Geere? 8/15

Ojú Jèhófà “Títàn Yanran” Ń Ṣàyẹ̀wò Gbogbo Èèyàn, 10/15

Ọlọ́run Kà Wá Yẹ Láti Gba Ìjọba Kan, 1/15

Ọlọ́run Kà Wọ́n Sẹ́ni Tó Yẹ Láti Ṣamọ̀nà Lọ Sáwọn Ìsun Omi Ìyè, 1/15

‘Ọlọ́run Ló Ń Mú Kí Ó Dàgbà’! 7/15

Pinnu Láti Sin Jèhófà Látìgbà Èwe Rẹ, 5/15

Ṣé O Ń Mú Ipò Iwájú Nínú Bíbu Ọlá Fáwọn Èèyàn? 10/15

Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Lo Fi Ń Wò Wọ́n? 3/15

Ṣé Wàá Pa Ìwà Títọ́ Rẹ Mọ́? 12/15

“Ta Ni Nínú Yín Tí Ó Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n àti Olóye?” 3/15

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ, 2/15

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù Kó O Lè Tẹ̀ Síwájú Nínú Òtítọ́, 5/15

Wọ́n Pinnu Láti Jẹ́rìí Kúnnákúnná sí Ìhìn Rere, 12/15

Wíwàníhìn-ín Kristi—Báwo Ló Ṣe Yé Ọ Sí? 2/15

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Àdéhùn Pàtàkì Kan, 3/15

Àjálù Ṣẹlẹ̀ Ní Erékùṣù Solomon Islands, 5/1

Àwọn Maya Rí Òmìnira Tòótọ́ Gbà, 12/1

Bá A Ṣe Mú Ìhìn Rere Dé ilẹ̀ Bòlífíà, 3/15

Bí A Ṣe Ṣètò Ìgbìmọ̀ Olùdarí, 5/15

Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere, 8/1

Gbogbo Wọn Ń Fi “Ọkàn Kan” Sin Ọlọ́run (àwọn ọrẹ), 11/15

Ìdí Tí Wọ́n Fi Pe Tonílé Tàlejò (Orílẹ̀-èdè South Africa), 11/1

Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Gílíádì, 2/15, 8/15

Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tuntun Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́, 1/15

Ilé Tó Ń Fìyìn Fún Jèhófà (Gbọ̀ngàn Ìjọba ní Mẹ́síkò, Belize), 2/1

Iṣẹ́ Ìwàásù àti Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Nílẹ̀ Áfíríkà, 3/1

Kí Nìdí Tí Wọn Kì Í Fi Í Lo Àgbélébùú? 3/1

Kí Nìdí Tí Wọn Ki Í Fi Í Lọ Sójú Ogun? 7/1

‘Màá Kà Á Létí Iná Àgọ́,’ 6/1

“Mi Ò Rí Irú Ìfẹ́ Báyìí Rí” (Ilẹ̀ Dominican Republic), 3/1

Mo Rí I Bí Ẹ̀mí Wa Ti Ṣeyebíye Tó, 9/1

Ó Múra Tán Láti Gbèjà Ìgbàgbọ́ (ọ̀dọ́mọbìnrin ọmọléèwé), 6/15

Ọgbọ́n Táwọn Kan Dá (láti lọ sí àpéjọ àgbègbè), 6/15

Ọjọ́ Tí Akọni Dèèyàn Jẹ́jẹ́, 12/1

Ọmọbìnrin Tó Ṣe Bí Ọmọdébìnrin Ilẹ̀ Ísírẹ́lì Àtijọ́, 6/1

Sí Ẹ̀yin Òǹkàwé Wa (àwọn nǹkan tuntun nínú Ilé Ìṣọ́), 1/1

Ṣáwọn Nìkan Ló Máa Nígbàlà? 11/1

Ṣé Wọ́n Gba Májẹ̀mú Láéláé Gbọ́? 12/1

Ṣé Wọn Máa Ń Tú Ìgbéyàwó Ká Ni? 11/1

“Tó O Bá Dé Etí Odò Coco, Yà Sápá Ọ̀tún,” 9/1

Wíwàásù ní Ọjà, 9/15

Wọ́n Gbèjà Àwọn Tí Wọ́n Hùwà Ìkà Sí (lórílẹ̀-èdè Georgia), 3/1

BÍBÉLÌ

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Gálátíà, Éfésù, Fílípì àti Kólósè, 8/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìṣe, 5/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jákọ́bù, Pétérù Kìíní àti Pétérù Kejì, 11/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù, 4/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù Kìíní, Jòhánù Kejì, Jòhánù Kẹta àti Ìwé Júúdà, 12/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Kọ́ríńtì Kìíní àti Ìkejì, 7/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Lúùkù, 3/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Máàkù, 2/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Mátíù, 1/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Róòmù, 6/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Tẹsalóníkà Kìíní àti Ìkejì, àti Ìwé Tímótì Kìíní àti Ìkejì, 9/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Títù, Fílémónì, àti Hébérù, 10/15

Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere, 8/1

“Ìwé Orin Òkun,” 11/15

Mọ Bíbélì Tí Wọ́n Túmọ̀ Lọ́nà Tó Dára, 5/1

Ohun Tí Jésù Sọ Ni Wọ́n Kọ Sínú Ìwé Mímọ́, 9/1

Ṣé Bíbélì Sọ Bọ́jọ́ Ọ̀la Ṣe Máa Rí? 10/1

Ṣóòótọ́ Làwọn Ọ̀rọ̀ Inú Àwọn Ìwé Ìhìn Rere? 10/1

Wàláà Ayé Àtijọ́ àti Bíbélì, 12/15

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTÀWỌN ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

A Lè Jẹ́ Alágbára Láìfi Àìlera Wa Pè, 6/15

Bá A Ṣe Lè Bá Àwọn Ọmọ Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀, 8/1

Bá A Ṣe Lè Yanjú Èdèkòyedè (nínú ìgbéyàwó), 2/1

Bá A Ṣe Lè Yanjú Ìṣòro, 5/1

Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere, 10/1

Bí A Ṣe Lè Tu Aláìsàn Tó Ń Retí Ikú Nínú, 5/1

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Máa Ṣera Wọn Lọ́kan, 11/1

Bó Ṣe Yẹ Ká Máa Hùwà Sáwọn Èèyàn, 8/1

“Ẹ Di Aláfarawé Ọlọ́run,” 10/1

Ẹ Máa Wà Ní Mímọ́ Nínú Ìbẹ̀rù Ọlọ́run, 5/15

Ẹ̀mí Ìtọpinpin, 6/1

Fi Àṣìṣe Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́gbọ́n, 2/15

Iṣẹ́ Tó Lè Fún Abiyamọ Nítẹ̀ẹ́lọ́rùn Jù Lọ, 2/1

Irú Èèyàn Wo Lo Fẹ́ Jẹ́? 11/15

Kí Nìdí Tí Ìmọ́tótó Fi Ṣe Pàtàkì? 12/1

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dúpẹ́ Oore? 8/1

Máa Fi ‘Ọ̀rọ̀ Tó Dára’ Gbé Ìdílé Rẹ Ró, 1/1

Máa Kún Fún Ìmọ̀ Pípéye, 9/15

“Máa Lépa Àwọn Ohun Tí Ń Yọrí sí Àlàáfíà,” 11/15

Máa Ro Ìgbẹ̀yìn Ọ̀rọ̀, 9/1

Nígbà Tí Èṣù Bá Ku Àwọn Kristẹni bí Àlìkámà, 1/15

O Ṣì Lè Láyọ̀ Bí O Tilẹ̀ Rí Ìjákulẹ̀, 3/1

Ohun Tọ́wọ́ Rẹ Lè Tẹ̀ Ni Kó O Fi Ṣe Àfojúsùn Rẹ, 7/15

Ọmọ Títọ́ Láyé Táwọn Èèyàn Ti Ń Ṣèyí Tó Wù Wọ́n, 4/1

Ọmọbìnrin Kan Ran Ọ̀gá Rẹ̀ Lọ́wọ́, 6/1

Ran Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kó Lè Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Tí Ikú Fà, 7/1

Sámúẹ́lì Tẹra Mọ́ Ṣíṣe Ohun Tí Ó Tọ́, 8/1

Ṣé Ohun Tó Ò Ń Gbèrò Kò Ta Ko Ìfẹ́ Ọlọ́run? 7/1

Ṣé Orí Àpáta Lò Ń Kọ́lé sí àbí Orí Iyanrìn? 11/1

Ṣó O Máa Ń Jowú? Òjòwú Làwọn Ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù, 10/1

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù—Sin Ọlọ́run bí Ọlọ́run Ṣe Fẹ́, 9/15

Wọn Ò Sí Láàárín Wa àmọ́ A Kò Gbàgbé Wọn (ilé ìtọ́jú arúgbó), 4/15

Wọ́n Yan Ohun Tó Sàn Jù, 1/15

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àṣìṣe Wọn Ni Mò Ń Wá Ni Mo Bá Rí Òtítọ́ (R. S. Marshall), 12/1

Àyà Ò Fò Wá Torí Jèhófà Wà Pẹ̀lú Wa (E. Petridou), 7/15

Ayọ̀ Mi Ò Lópin Bí Mo Ti Ń Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run (B. Yaremchuk), 6/1

Bí Ìgbàgbọ́ Mi Ṣe Ràn mí Lọ́wọ́ Láti Fara Da Ìṣòro (S. Castillo), 10/1

“Jèhófà Ni Okun Mi” (J. Coville), 10/15

“Má Ṣe Gbàgbé Iṣẹ́ Ìwáàsú Ilé-dé-Ilé” (J. Neufeld), 9/1

Mo Bọ́ Lọ́wọ́ Ìdààmú Ìgbà Ọ̀dọ́ (E. Morcillo), 1/1

Mo Ti Rí Báwọn Èèyàn Ọlọ́run Ṣe Pọ̀ Sí I Lórílẹ̀-Èdè Kòríà (M. Hamilton), 12/15

“Ó Ń Ṣamọ̀nà Mi Ní Àwọn Òpó Ọ̀nà Òdodo” (O. Campbell), 3/1

Ọlọ́run Fi Àánú Hàn sí Mi (B. Močnik), 7/1

JÈHÓFÀ

Àsọtẹ́lẹ̀ Jèhófà Máa Ń Ṣẹ, 1/1

Bó O Ṣe Lè Di Ọmọ Ọlọ́run, 3/1

“Ẹ Di Aláfarawé Ọlọ́run,” 10/1

Ẹlẹ́dàá Tó Yẹ Ká Fọpẹ́ Fún, 12/1

Ẹni Tó Máa Ń Dárí Jini, 6/1

Ẹni Tó Mọ Ìnira Wa, 5/1

Ẹni Tó Mọyì Wa, 4/1

Ẹni Tó Ń Sọ Òkú Di Alààyè, 3/1

Ìṣẹ̀dá Ń Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Hàn, 5/1

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba ìjìyà? 2/1

“Kò Jìnnà sí Ẹnì Kọ̀ọ̀kan Wa,” 7/1

Kò sí Bàbá Tó Dà Bíi Rẹ̀, 1/1

Lo Orúkọ Ọlọ́run Bá Ò Tiẹ̀ Mọ Bí Wọ́n Ṣe Ń Pè É, 9/1

Mọ Bàbá Rẹ Ọ̀run, 9/1

Ǹjẹ́ Ohunkóhun “Lè Yà Wá Kúrò Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run”? 8/1

Ó Fẹ́ràn Ìdájọ́ Òdodo, 11/1

Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù, 2/1

Olùṣọ́ Àgùntàn Tó Bìkítà, 2/1

“Orúkọ Ọlọ́run Tó Tóbi Tó Sì Jẹ́ Mímọ́,” 10/15

“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo,” 9/1

Ṣé Bó Ṣe Wù Wá La Ṣe Lè Sin Ọlọ́run? 6/1

Ṣé Ó Yẹ Kí Orúkọ Náà Jèhófà Wà Nínú Májẹ̀mú Tuntun? 8/1

Ṣé “Orúkọ Tá Ò Gbọ́dọ̀ Pè,” Ni? 6/1

Ṣé Ọlọ́run Ló Ǹ Fa Àwọn Ìjábá? 5/1

Ṣó Dáa Kéèyàn Máa Lo Orúkọ Ọlọ́run? 7/1

JÉSÙ KRISTI

Àrà Tí Jésù Ì Bá Fi Iṣẹ́ Káfíńtà Dá, 12/1Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà, 10/1

Àwọn “Oníṣẹ́ Báńkì,” 12/1

Àwọn Tó Ń Gbọ́rọ̀ Rẹ̀ Ṣe Kàyéfì, 9/1

Bí Jésù ṣe la ojú afọ́jú kan díẹ̀díẹ̀, 4/1

Bí Ikú Jésù Ṣe Lè Gbà Ọ́, 3/1

Bó Ṣe Yẹ Ká Máa Hùwà Sáwọn Èèyàn, 8/1

Èdè Tí Jésù Sọ, 8/1

Ìgbà Wo Làwọn Awòràwọ̀ Lọ Sọ́dọ̀ Jésù? 1/1

Ipa Wo Ló Kó Nígbèésí Ayé Ẹ? 12/1

Iṣẹ́ Ìyanu, 5/1

Ṣé Iná Ọ̀run Àpáàdì Ni? (Mk 9:48), 6/15

Ṣé “Ọlọ́run” ni àbí “ọlọ́run kan”? 11/1

Kí Nìdí Tá A Fi Ń Gbàdúrà Lórúkọ Jésù? 2/1

Kí Nìdí Tí Ẹ̀rù Fi Ba Pílátù Nígbà Tí Jésù “Fi Ara Rẹ̀ Ṣe Ọmọ Ọlọ́run”? 6/1

Kí Nìdí Tó Fi Gba Ọgbọ̀n Owó Fàdákà? 9/1

Kí Nìdí Tó Fi Gba Jésù Ní Ọjọ́ Mẹ́rin? 1/1

Pétérù Sẹ́ Jésù, 1/1

Ọ̀KÀN-Ò-JỌ̀KAN

Amágẹ́dọ́nì, 4/1

Àwọn Òkúta Tẹ́ńpìlì, 8/1

“Àwọn Ọkọ̀ Òkun Táṣíṣì,” 11/1

Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Gíríìkì Lára Àwọn Tó Bẹ̀rẹ̀ Ìsìn Kristẹni, 12/1

Ayé Ń Móoru, 9/1

Báwo Ló Ṣe Ṣeé Ṣe Fún Ádámù Láti Dẹ́ṣẹ̀? 10/1

Báwo Ni Okun Dídà Ṣe Tóbi Tó? 2/1

Báwo Ni Wúrà Sólómọ́nì Ṣe Pọ̀ Tó? 11/1

Bí Sódómù àti Gòmórà Ṣe Pa Run, 3/1

Ẹ̀gbọ́n Bínú sí Àbúrò (Kéènì), 7/1

Fi “Jẹ Àwọn Ohun Ọlọ́ràá,” (Ne 8:10) àti “Ẹ Kò Gbọ́dọ̀ Jẹ Ọ̀rá Èyíkéyìí” (Le 3:17) Wéra, 12/15

Gbígba Ara Olúwa, 4/1

“Gbígbé Ọwọ́ Léni” Lórí (Heb 6:2), 9/15

Ìbàlẹ̀ Ọkàn, 2/1

Ibo Ni Ogun Amágẹ́dọ́nì Ti Máa Jà? 4/1

Ìdí Tá A Fi Wà Láàyè, 2/1

Ìdí Táwọn Júù Fi Máa Ń Bẹ̀rẹ̀ Sábáàtì Nírọ̀lẹ́, 10/1

Ìdí Tí Dáfídì Ò Fi Bẹ̀rù, 12/1

Ìdí Tí Sekaráyà Fi Sàsọtẹ́lẹ̀ Ìparun Ìlú Tírè Lẹ́yìn Tí Wọ́n Pa Ìlú Náà Run, 6/1

Ìgbà Wo Ni Sọ́ọ̀lù Di Pọ́ọ̀lù? 3/1

Ìgbé Ayé Ìrọ̀rùn, 8/1

Ìjọba Ọlọ́run, 1/1, 5/1

Ìlú Jẹ́ríkò Mélòó Ló Wà? 5/1

Ìrètí Fáwọn Òkú, 11/1

“Ìrìn Ọjọ́ Sábáàtì,” 10/1

“Ìwé Ẹ̀rí Ìkọ̀sílẹ̀,” 9/1

Kíka Àkájọ Ìwé, 4/1

Kí Nìdí Táwọn Júù Ò Fi Sí Lójú Kan Nígbà Tí Jésù Wà Láyé? 11/1

Lìdíà Là Wá Lóye, 4/1

Máàkù Ò Rẹ̀wẹ̀sì, 2/1

Nígbà Tí Èèyàn Ẹni Bá Kú, 7/1

Ǹjẹ́ Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Bá Bíbélì Mu? 1/1

Nóà àti Ìkún-Omi, 6/1

Ó Dé ‘Ìparí Èrò Nínú Ọkàn Rẹ̀’ (Màríà), 10/1

‘Òfin Ti Di Akọ́nilẹ́kọ̀ọ́,’ 3/1

Ó Gbèjà Ìjọsìn Mímọ́ (Èlíjà), 1/1

Omi Tó Ń Tú Yàà Sókè Láti Fúnni Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun, 6/1

Omijé Nínú Ìgò Awọ, 10/1

Òróró Onílọ́fínńdà tí Màríà Lò, 5/1

Ó Ṣọ́nà Ó sì Ní Sùúrù (Èlíjà), 4/1

Owó Ẹyọ Méjì Tí Opó Fi Sínú Àpótí, 3/1

Owó Kan Ṣoṣo Ni Jésù àti Pétérù Fi San Owó Orí, 2/1

Ọ̀rọ̀ Bẹ́yìn Yọ! (Dáníẹ́lì), 11/1

Ṣé Ayé Yìí Máa Wà Títí Láé? 8/1

Ṣé Gbogbo Àwọn Júù Pátá Máa Di Kristẹni? (Ro 11:26), 6/15

Ṣé Ilẹ̀ Ayé Máa Pa Run? 4/1

Ṣé Méjìlá Làwọn Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Ni Àbí Mẹ́tàlá? 7/1

Ṣé Ògiri Tó Ṣeé Fojú Rí Ni? (Ef 2:11-15), 7/1

Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Làwọn ‘Iṣẹ́ Ìyanu’ Òde Òní ti Wá? 12/1

Ṣó Yẹ Kó O Máa Bẹ̀rù Ọ̀run Àpáàdì? 11/1

Teli Árádì, 7/1

Tímótì, 4/1

“Wò Ó! Ẹrúbìnrin Jèhófà!” (Màríà), 7/1