Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2009

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2009

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2009

Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àwọn Áńgẹ́lì Jẹ́ “Ẹ̀mí fún Iṣẹ́ Ìsìn Gbogbo Ènìyàn,” 5/15

Àwọn Ìṣẹ̀dá Jèhófà Ń Fi Ọgbọ́n Rẹ̀ Hàn, 4/15

Àwọn Olódodo Yóò Máa Yin Ọlọ́run Títí Láé, 3/15

Bá A Ṣe Lè Máa Hùwà Tó Bójú Mu Gẹ́gẹ́ Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run, 11/15

Bá A Ṣe Lè Máa Ṣe Ọ̀rẹ́ Nínú Ayé Aláìnífẹ̀ẹ́ Yìí, 10/15

Bá A Ṣe Lè Mọyì Jésù Tó Jẹ́ Dáfídì àti Sólómọ́nì Títóbi Jù, 4/15

Bá A Ṣe Lè Mọyì Jésù Tó Jẹ́ Mósè Títóbi Jù, 4/15

Bá A Ṣe Lè Rí Ìṣúra Tá A Rọra Fi Pa Mọ́ Sínú Kristi, 7/15

Bí Ọ̀rọ̀ Jésù Ṣe Lè Sọni Di Aláyọ̀, 2/15

‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ 8/15

“Ẹ Jẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà Pẹ̀lú Gbogbo Ènìyàn,” 10/15

Ẹ Jẹ́ Kí Gbogbo Wa Jọ Yin Jèhófà, 3/15

‘Ẹ Jẹ́ Kí Iná Ẹ̀mí Máa Jó Nínú Yín,’ 10/15

Ẹ Ní Ìfẹ́ Tí Kì Í Kùnà Láé, 12/15

‘Ẹ Wà Lójúfò,’ 3/15

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù! 7/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ìtẹ̀síwájú Yín Fara Hàn Kedere, 5/15

Ìfẹ́ Kristi Ń Mú Ká Ní Ìfẹ́, 9/15

Ìránṣẹ́ Jèhófà Tí Wọ́n ‘Gún Nítorí Ìrélànàkọjá Wa,’ 1/15

Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lorí Ilẹ̀ Ayé Pa Dà Wá Sojú Tayé, 8/15

Ìwà Títọ́ Rẹ Ń Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀, 4/15

Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Tó O Ní Fáwọn Ará Máa Pọ̀ Sí I, 11/15

Jẹ́ Kí Ìlọsíwájú Rẹ Máa Fara Hàn Kedere, 12/15

Jẹ́ Onígbọràn àti Onígboyà Bíi Kristi, 9/15

Jẹ́ Onítara fún Ilé Jèhófà! 6/15

Jẹ́ “Onítara fún Iṣẹ́ Àtàtà”! 6/15

Jóòbù Gbé Orúkọ Jèhófà Ga, 4/15

Kí Ni Àdúrà Rẹ Ń Sọ Nípa Rẹ? 11/15

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Má Tẹ̀ Lé “Kristi”? 5/15

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìṣòro Ba Ayọ̀ Rẹ Jẹ́, 12/15

Máa Bá Aládùúgbò Rẹ Sọ Òtítọ́, 6/15

Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Láti Mú Kí Àdúrà Rẹ Sunwọ̀n Sí I, 11/15

Máa Rí Ìdùnnú Nínú Iṣẹ́ Sísọni Dọmọ Ẹ̀yìn, 1/15

Máa Tẹ̀ Lé Ọ̀rọ̀ Jésù Nínú Ìwà Àti Ìṣe Rẹ, 2/15

Máa Tẹ̀ Síwájú sí Ìdàgbàdénú Torí pé “Ọjọ́ Ńlá Jèhófà Sún Mọ́lé,” 5/15

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” 1/15

Mèsáyà! Ọ̀nà Ìgbàlà Tí Ọlọ́run Pèsè, 12/15

Mọyì Ojúṣe Rẹ Nínú Ìjọ, 11/15

Ǹjẹ́ ‘Ìríjú Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run’ Ni Ọ́? 1/15

Ǹjẹ́ O Máa Ń Tẹ̀ Lé Ọ̀rọ̀ Jésù Tó O Bá Ń Gbàdúrà? 2/15

Ǹjẹ́ O Mọyì Ohun Tí Jèhófà Ṣe Láti Dá Ọ Nídè? 9/15

Ohun Tó Mú Kí Ẹ̀kọ́ Tí Ọlọ́run Ń Kọ́ Wa Ta Yọ, 9/15

Olùṣòtítọ́ Ìríjú Náà àti Ìgbìmọ̀ Olùdarí Rẹ̀, 6/15

Ọlọ́run Ló Fún Aráyé Ní Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lorí Ilẹ̀ Ayé, 8/15

“Ọ̀rẹ́ Mi Ni Yín,” 10/15

Ṣé Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lorí Ilẹ̀ Ayé Jẹ́ Ìrètí Tó Wà Fáwọn Kristẹni? 8/15

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù Máa Fìgboyà Wàásù, 7/15

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù Máa Kọ́ni Pẹ̀lú Ìfẹ́, 7/15

Tẹjú Mọ́ Èrè Náà, 3/15

Wò ó! Ìránṣẹ́ Tí Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà, 1/15

Wọ́n “Ń Tọ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Náà Lẹ́yìn Ṣáá,” 2/15

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

A Fi Tọ̀yàyàtọ̀yàyà Pè Ọ́ (àwọn ìpàdé), 2/1

Adágún Títóbi Jù Lọ ní Amẹ́ríkà Àárín, 9/1

Àkànṣe Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn, 4/1

Àwárí, (Ireland), 3/1

Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 2/15, 9/1

Bẹ́tẹ́lì Tó Wà Ní Brooklyn Pé Ọgọ́rùn-ún Ọdún, 5/1

Ìdí Tí Wọn Kì í Fí Í Lo Ère, 2/1

Ìhìn Rere ní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Èdè, 11/1

Ìjì Òjò Lórílẹ̀-Èdè Myanmar, 3/1

Ilé Ìtẹ̀wé Tó Pabanbarì (Oko Watchtower lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà), 7/1

Ìrìn Àjò Gbé Wọn Pa Dà sí Ìgbà Àtijọ́ (Amish Lórílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà), 12/1

Ìrìn-Àjò Lọ sí ‘Abúlé Kan Tó Jìnnà Réré’ (Àgbègbè Sakha), 6/1

Irúgbìn Òtítọ́ Dé Àwọn Ibi Jíjìnnà Réré (Àgbègbè Tuva Nílẹ̀ Rọ́ṣíà), 7/15

Iṣẹ́ Ìwàásù àti Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Nílẹ̀ Áfíríkà, 3/1

‘Jèhófà Ti Mú Kí Ojú Rẹ̀ Tàn sí Wọn Lára’ (àwọn adití), 8/15

Máa Ṣìkẹ́ Àwọn Ará Tó Jẹ́ Adití,11/15

Ǹjẹ́ O Lè Ré Kọjá Lọ sí Makedóníà? 12/15

Ó Láyọ̀ Ó sì Nírètí Bí Kò Tiẹ̀ Lówó Lọ́wọ́, 9/1

Ó Rí Àwọn Ìṣúra Tó Wà ní Ìpamọ́ (Estonia), 8/15

Ọmọdébìnrin Tó Jẹ́ Ọ̀làwọ́, 11/15

Ṣé Ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì Ni Wọ́n? 11/1

Ṣé O Lè Sìn Níbi Tí Wọn Ti Nílò Oníwàásù? 4/15, 12/15

BÍBÉLÌ

Àwọn Àfiwé Ọ̀rọ̀, 5/1

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìṣípayá—Apá Kìíní, 1/15

Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìṣípayá—Apá Kejì, 2/15

Bó O Ṣe Lè Lóye Rẹ̀, 7/1

Ìdí Tí Wọ́n Fi Kọ Apá Kan Lédè Gíríìkì, 4/1

Ìwé Àfọwọ́kọ Vatican, 10/1

Kò Pa Run, 11/1

Ó Dé Erékùṣù Madagásíkà, 12/15

Ó Ń Yí Ìgbésí Ayé Èèyàn Pa Dà, 2/1, 7/1, 8/1, 11/1

Ó Wúlò, 6/1

Ó Yè Lédè Tó Ń Kú Lọ, 4/1

Ṣó Pọn Dandan Kó O Kọ́ Hébérù àti Gíríìkì? 11/1

Wọ́n Fẹ́ràn Rẹ̀, 6/1

Wọ́n Ṣàwárí Bíbélì Tó Ṣeyebíye (Codex Ephraemi Syri rescriptus), 9/1

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Ààwẹ̀ Gbígbà, 4/1

Àwọn Àdúrà Tí Ọlọ́run Kì Í Dáhùn, 1/1

Àwọn Àdúrà Tí Ọlọ́run Ń Gbọ́, 2/1

Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná, 8/1

Bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Nílò Àbójútó Àrà Ọ̀tọ̀, 11/1

Èló Ló Yẹ Kí N Fi Ṣètọrẹ? 8/1

Èmi Ló Yẹ Kí Pinnu Ẹ̀sìn Mi Àbáwọn Òbí Mi? 9/15

Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìfẹ́ Kristi, 5/15

Fi Ìfaradà Ṣe Iṣẹ́ Ìwàásù, 3/15

Fífasẹ́lénilọ́wọ́, 6/15

Fífúnni Ní Nǹkan Látọkàn Wá, 11/15

Ibi Tó Yẹ Kó O Wà Nígbà Tí Òpin Bá Dé, 5/15

Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ń Mú Ìtẹ̀síwájú Wá, 7/15

“Ìgbà Dídákẹ́,” 5/15

Ìgbésí Ayé Ìdílé, 11/1

Ìsìnkú, 2/15

Ítítáì, 5/15

Jẹ́ Kí Ọlọ́run BÁ Ọ Sọ̀rọ̀ Lójoojúmọ́, 8/1

Láyọ̀ Láìlọ́kọ Tàbí Aya, 6/15

Má Gbàgbé Jèhófà, 3/15

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn Rẹ Pínyà, 8/15

Máa Fi Ìmoore Hàn, Máa Fúnni Tọkàntọkàn, 7/15

Máa Láyọ̀ Nínú Iṣẹ́ Ọlọ́run Bí Ọwọ́ Rẹ Tiẹ̀ Dí, 12/15

Màríà, 1/1

Ọmọ Títọ́, 2/1

‘Ọ̀nà Ìfẹ́ Títayọ Ré Kọjá,’ 7/15

Ríran Ọmọ Tó Ń Bàlágà Lọ́wọ́, 5/1

Ṣé O Ti Sìn Nígbà Kan Rí? 8/15

Ṣé Ó Yẹ Kó O Rin Kinkin Mọ́ Ohun Tó Wù Ọ́? 2/15

Ṣó Yẹ Kí Obìnrin Tó Ń Túmọ̀ Àsọyé sí Èdè Àwọn Adití Bo Orí? 11/15

Tí Wọ́n Bá Ṣohun Tó Dùn Ọ́, 9/1

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àádọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn Ni Mo Bẹ̀rẹ̀ (E. Ridgwell), 7/15

“Áńgẹ́lì Jèhófà Dó Yí Àwọn Tí Ó Bẹ̀rù Rẹ̀ Ká” (C. Connell), 3/15

Àpéjọ Mẹ́ta Yí Ìgbésí Ayé Mi Pa Dà (G. Warienchuck), 10/15

Èèyàn Ò Gbọ́dọ̀ Wà Láàyè Nípa Oúnjẹ Nìkan (J. Hisiger), 3/1

“Èyí Ni Ọ̀nà. Ẹ Máa Rìn Nínú Rẹ̀” (E. Pederson látọwọ́ R. Pappas), 1/15

Kí Ni Mo Lè San Pa Dà fún Jèhófà? (R. Danner), 6/15

Mo Rí Ohun Rere Gbé Ṣe Nígbèésí Ayé Mi (G. Martínez), 9/15

Ó Láyọ̀ Láìka Àìlera Sí (P. Gaspar), 5/1

Ọpẹ́ Rẹ̀ Pọ̀ Láìka Àjálù Sí (E. Acosta), 6/1

JÈHÓFÀ

Àwọn Aláṣẹ Kátólíìkì Fẹ́ Pa Orúkọ Ọlọ́run Rẹ́, 4/1

Baba Àwọn Ọmọ Aláìníbaba, 4/1

Bẹ̀rù Ọlọ́run Dípò Èèyàn, 3/1

Bí Òun àti Jésù Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan, 9/1

Ẹ̀rí Tó Ta Yọ Jù Lọ Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Wa, 2/1

Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? 10/1

Má Gbàgbé Jèhófà, 3/15

“Mo Mọ Ìrora Tí Wọ́n Ń Jẹ” (Ẹk 3:1-10), 3/1

Ó Bìkítà, 6/1

Ó Fẹ́ Ká Ṣàṣeyọrí, 12/1

Ó Fún Wa Lómìnira Láti Yàn, 11/1

Ó Jẹ́ Mímọ́, 7/1

Ó Mọbi Tágbára Wa Mọ, 6/1

Ó Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́kàn Tútù, 8/1

Ó Ṣàpèjúwe Irú Ẹni Tó Jẹ́, 5/1

Onídàájọ́ Tó Máa Ń Ṣohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo, 1/1, 9/1

Ọlọ́run Nìkan Ló Lè Tún Ayé Yìí Ṣe, 1/1

Ṣé Ààwẹ̀ Gbígbà Ló Máa Jẹ́ Kó O Sún Mọ́ Ọn? 4/1

Ṣé Jésù Ni? 2/1, 4/1

Ṣé Ó Fọwọ́ Sí Ìkóbìnrinjọ? 7/1

Ṣé Ó Ń Fi Ìṣòro Jẹ Wá Níyà? 6/1

Ṣé Ó Ń Pa Àwọn Ọmọdé Kó Lè Sọ Wọ́n Di Áńgẹ́lì? 3/1

Ṣé Ó Ń Yíhùn Pa Dà? 6/1

Ṣé Ó Ṣèlérí Ọrọ̀? 9/1

Ta Ni Ọlọ́run? 2/1

Yóò Fòpin Sí Ìjìyà! 12/1

JÉSÙ KRISTI

Àwọn Farisí Dà Bí “Àwọn Sàréè Tí A Kùn Lẹ́fun,” 11/1

Bí Òun àti Bàbá Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan, 9/1

Ìdí Tí Ẹ̀wù Àwọ̀tẹ́lẹ̀ Rẹ̀ Fi Wu Àwọn Ọmọ Ogun, 7/1

Ìdí Tó Fi Sọ Pé, “Ábà, Baba” sí Jèhófà, 4/1

Ìdí Tí Jósẹ́fù Fi Fẹ́ Láti Kọ Màríà Sílẹ̀, 12/1

Ìkànìyàn Tó Wáyé Lákòókò Tí Wọ́n Bí I ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, 12/1

Kí Nìdí Tó Fi Fọ Ẹsẹ̀ Àwọn Àpọ́sítélì? 1/1

Ó Borí Ìdẹwò, 5/1

Ohun Tó Kọ́ni Nípa “Àkókò Òpin,” 5/1

Ohun Tó Kọ́ni Nípa Àwọn Àdúrà Tí Ọlọ́run Ń Gbọ́, 2/1

Ohun Tọ́ Kọni Nípa Ìgbésí Ayé Ìdílé, 11/1

Ohun Tó Kọ́ni Nípa Ọjọ́ Ọ̀la Aráyé, 8/1

Ṣé Òótọ́ Ni Àwọn Amòye Mẹ́ta Lọ Wò Ó Nígbà Tó Wà Ní Ọmọ Ọwọ́? 12/1

Ṣé Òun Ni Ọlọ́run? 2/1, 4/1

Ọ̀KAN Ò JỌ̀KAN

Ààbò Lọ́wọ́ Àwọn Ẹ̀mí Búburú, 5/1

Àlàáfíà Nínú Ayé Oníwàhálà, 7/1

“Àmín,” 6/1

Àpótí Májẹ̀mú, 9/1

Àwọn Akọ̀wé Òfin Tó Ta Ko Jésù, 8/1

Àwọn Bàbá Ìjọ, 7/1

Àwọn Júù “gbé ìgbésẹ̀ ní àìmọ̀” (Iṣe 3:17), 6/15

Àwọn Ọkùnrin Tó Ń Jẹ́ Jákọ́bù, 9/1

Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Awòràwọ̀, 3/1

“Àwọn Ọmọ Súúsì” (Iṣe 28:11), 3/1

Àtúnbí, 4/1

Bí Wọ́n Ṣe Pàdánù Párádísè, 11/1

Ẹ̀kọ́ Èké Mẹ́fà Tí Wọ́n Mú Wọnú Ìsìn Kristẹni, 11/1

Ẹ̀kọ́ Tí Òwe 24:27 Kọ́ Wa, 10/15

Ẹ̀mí Mímọ́—Ìdí Térò Kò Fi Ṣọ̀kan, 10/1

Ẹni Tó Gba Ìlérí Ọlọ́run Gbọ́ (Ábúráhámù), 7/1

Ẹ̀tẹ̀ Nínú Bíbélì, 2/1

“Hẹ́rọ́dù Ọba,” 12/1

Ìdí Táwọn Alágbẹ̀dẹ Fàdákà Fi Gbaná Jẹ Nígbà Tí Pọ́ọ̀lù Wàásù Nílùú Éfésù, 2/1

Igi ‘Tí Ẹ̀ka Rẹ̀ Kì Í Rọ,’ 3/1

Ìgbà Wo Ni Wọ́n Lé Sátánì Kúrò Lọ́run? 5/15

Ìgbàgbọ́ Tó Túbọ̀ Lágbára, 5/1

Ìjọsìn Báálì àti Ọ̀rọ̀ Ìṣekúṣe, 11/1

Ìjọsìn Ìdílé, 10/15

Ilé Là Ń Wò Ká Tó Sọmọ Lórúkọ, 2/1

Ìpakúpa Lọ́gbà Iléèwé, 12/1

Iṣẹ́ Ẹja Pípa Lórí Òkun Gálílì, 10/1

Ìtumọ̀ Ìfòróróyanni, 8/1

Ìwé “Jáṣárì,” Ti “Àwọn Ogun Jèhófà,” 3/15

Ìwòsàn Lọ́nà Ìyanu, 5/1

Ìyanu Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Pẹ́ńtíkọ́sì, 9/1

Jèhóáṣì, 4/1

Jeremáyà, 12/1

Jòsáyà, 2/1

Kádàrá, 3/1

“Kí Ni A Ó Jẹ?” 8/1

Kọ́ríńtì, 3/1

Lásárù Jíǹde, 3/1

Mímọ Ìsìn Tòótọ́, 8/1

Ó Gbógun Ti Ìbẹ̀rù àti Iyèméjì (Pétérù), 10/1

Ó Hùwà Ọgbọ́n (Ábígẹ́lì), 7/1

Ó Kọ́ Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Aláàánú (Jónà), 4/1

Ó Kọ́gbọ́n Látinú Àṣìṣe Ara Rẹ̀ (Jónà), 1/1

Ohun Gbogbo Làkókò Wà Fún, 3/1

Òjò, 1/1

“Olórí Ẹ̀ṣọ́ Tẹ́ńpìlì,” 10/1

Ọ̀dọ́ Kan Tó Nígboyà (Dáfídì), 1/1

Ọdún Tuntun (Éṣíà), 12/1

Ọmọkùnrin Tó Gba Ẹ̀mí Pọ́ọ̀lù Là, 6/1

Ọ̀nà Abẹ́lẹ̀ Ti Hesekáyà, 5/1

Ọwọ́ Tí Dáfídì Ọba Fi Mú Orin Kíkọ, 12/1

Ráhábù, 8/1

Ṣáwọn Míṣọ́nnárì Dé Ìpẹ̀kun Ìlà Oòrùn Ayé? 1/1

Ṣé Àjíǹde Wà Fọ́mọ Tó Kú Sínú Ìyá Rẹ̀? 4/15

Ṣé Eéṣú Wà Lára Oúnjẹ Látijọ́? (Mt 3:4), 10/1

Ṣé Ẹni Gidi Ni Èṣù? 10/1

Ṣé Ọlọ́run Kan Ni Gbogbo Wa Ń Sìn? 6/1

Ṣé Ọlọ́run Ti Kádàrá Wa? 4/1

Ṣé Wọ́n Fi Òpó Igi Olórí Ṣóńṣó Yí Jerúsálẹ́mù Ká? 5/1

Ṣé Wọ́n Ń Sin Oyin Ní Ísírẹ́lì Àtijọ́? 7/1

Ṣé Wọ́n Rí Ọkọ Nóà? 7/1

Ṣémù, 10/1

Ṣẹ́ni Gidi Ni Ádámù àti Éfà? 9/1

Ṣó O Máa Ń Bẹ̀rù Òkú? 1/1

Ṣó Ṣeé Ṣe Láti Nígbàgbọ́ Nínú Ẹlẹ́dàá? 10/1

Ṣó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Jagun? 10/1

Ṣó Yẹ Kí Pílátù Bẹ̀rù Késárì? 1/1

‘Ta Gbòǹgbò sì Fìdí Múlẹ̀ Lórí Ìpìlẹ̀ Náà,’ 10/15

Úrímù àti Túmímù, 6/1

Ya Àkókò Sọ́tọ̀ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, 10/15